Top 10 similar words or synonyms for dinku

ọmọde    0.998136

pese    0.997327

oru    0.997282

gbooro    0.997044

kin    0.996552

oore    0.996142

laisi    0.996077

nwaye    0.995376

atun    0.995341

bakiteria    0.995234

Top 30 analogous words or synonyms for dinku

Article Example
Kúrùpù Awọn aami aisan kúrùpù ni ninu ikọ́"gbígbó", idiwọ ọnafun(mimi ti o ngbọn), ohun kíkẹ̀, ati mimi ti o nira eyiti o maa nnira ni òru. Ikọ́ "gbígbó" naa ni a maa nsaba ṣ’apejuwe wipe o jọ ìpèerinmi tabi kiniun okun. Si sọkun le mu ki mimi ti o ngbọn naa ki o buru si; mimi ti o ngbọn le tunmọ si wipe ọ̀nà-atẹgun ti dinku. Bi kúrùpù ba ṣe nburu sii, mimi ti o ngbọn le dinku gan-an.
Anafilasisi Lọwọlọwọ, anafilasisi nfa iye iku 500–1,000 l’ọdun (2.4 ninu miliọnu) ni orilẹ-ede Amẹrika, iye iku 20 l’ọdun ni orilẹ-ede Gẹẹsi (0.33 ninu miliọnu), ati iye iku 15 l’ọdun ni Ọsirelia (0.64 ninu miliọnu).Iye iku ti dinku laarin awọn ọdun 1970 ati 2000. Ni Ọsirelia, iku anafilasisi ti ounjẹ nfa maa nsaba waye laarin awọn obinrin nigbati iku ti o nwaye nitori kokoro ti o jẹ ni maa nsaba waye laarin awọn ọkunrin. Ogun lilo ni o wọpọ julọ ti o nfa anafilasisi.
Anafilasisi Ninu ẹniti anafilasisi pa, [[iwadi nipa iku]] le fi "ọkan ti o ṣofo" kan han eyiti o waye nipasẹ oro ti o dinku lati ọwọ [[fifẹ awọn ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara]] ati ti tun tan kaa kiri omi ti o wa ninu awọn iṣan si awọn apo to wa lerefe. Awọn aami miiran ni kikorajọpọ omi ninu awọn alafo ara, eosinofilia ninu ẹdọ-foo, ọkan ati awọn tisu, ati ẹri myokadial haipopafusion. Awọn iwadi imọ-ijinlẹ le ṣe awari ipele sẹrọmu ti o pọ si [[tryptase]], pipọsi ni akotan ati ipele sẹrọmu IgE ni pato.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Ti ti di 2011, ko si abęrę fun àrùn jẹdọjẹdọ C. Awon abęrę ṣi wa ni ipele imudagba, ati wipe awọn kan si ti fi esi iwunilori han. Àgbájọpọ awọn ìlànà ìdádúró, gẹgẹbi awọn ètὸ fun ipàsípààrọ abęrę ati itọju fun oὸgùn ìlòkulò, jęki ewu àrùn jẹdọjẹdọ C laarin awọn to ngbabęrę oògùn inu iṣan dinku si ìdá marun-din-lọgọrin ninu ọgọrun. Iṣewadii awọn olufęjẹsilẹ ṣe pataki ni orilẹ- ede, gẹgẹbi o ṣe wa ni ibamu pęlu titęle àkíyèsára gbogbogbòò ni ti ilera. Ni awọn orilẹ ede ti awon abęrę ti a ti fọ kὸ pọ tó, awọn olutọju gbọdọ funni l’ogun lilo dipo gígún ni abẹrẹ.
Oyún ṣíṣẹ́ O to miliọnu mẹrinlelọgọta (44) oyún ṣíṣẹ́ ti o nwaye l’ọdun kan l’agbaye, ti diẹ si eyi jẹ eyiti a nṣe lai si ààbò. Diẹ ni iye oyún ṣíṣẹ́ fi yatọ laarin ọdun 2003 ati 2008, lẹyin ti o ti fi ọpọlọpọ ọdun dinku nitori bi rírí ààyè si ẹ̀kọ́ nipa fifi ètò s’ọmọ bibi ati dida ọmọ bibi duro ṣe gberu. , ida ogoji obinrin l’agbaye ti ni ààyè si oyún ṣíṣẹ́ ti a mọọmọ ṣe okunfa rẹ labẹ ofin "lai si idiwọ fun ohun ti o fàá". Ṣugbọn o ni gbèdéke ibi ti oyún le pẹ́ dé ti a fi le ṣẹ́ ẹ.