Top 10 similar words or synonyms for bakiteria

nwaye    0.998245

pese    0.997656

afefeayika    0.997093

imu    0.996796

tire    0.996589

npa    0.996473

oku    0.996238

akoran    0.996128

omode    0.995808

nyan    0.995782

Top 30 analogous words or synonyms for bakiteria

Article Example
Kúrùpù Kúrùpù ti o niiṣe pẹlu bakiteria ṣee pin si laryngeal diphtheria, bacterial tracheitis, laryngotracheobronchitis, ati laringotrakiobronkopneumonitisi. Laringeal diphtheria maa nwaye nitori "Corynebacterium diphtheriae" nigbati bakiteria trakitisi, laringotrackiobronkaitisi, ati laringotrakobronkopneumonitisi maa nwaye nitori fairọsi, pẹlu bakiteria ti o lọwọ sii. Awọn bakiteria ti o wọpọ julọ ni"Staphylococcus aureus", "Streptococcus pneumoniae", "Hemophilus influenzae", ati "Moraxella catarrhalis".
Kúrùpù Fairọsi le fa kúrùpù. Awọn eniyan kan lo ọrọ naa lati ni ninularingotrakiaitisiti o lewu, kúrùpù ti o ṣẹlẹ logiji fun igba diẹ, laringeal diphtheria, trakiatisi ti bakiteriali fa, laringotrakiobronkaitisi, ati laringotrakiaobronkoneumonitisi. Ipo meji akọkọ ni ninu fairọsi kan ti o si ni aami aisan ti ko nira; awọn mẹrin ti o kẹyin maa nwaye lati ọwọ bakiteria wọn si maa nlewu gan-an.
Kúrùpù Awọn Ayẹwo ẹjẹ ati viral culture (awọn ayẹwo fairọsi) le fa irira ti ko nilo fun oju-ọ̀nà atẹgun. Nigbati awọn viral mimu kokoro dagba nipa amu nkan dagba ni yara iwadi, ti a gba nipase ilepa nasopharyngeal (ọ̀nà kan ti a nlo rọba ti o ni alafo ninu lati fa ikun imu jade ninu imu), ṣee lo lati jẹrisi ni pato ohun ti o ṣe okunfa. A maa ndekun lilo awọn mimu kokoro dagba nipa amu nkan dagba ni yara iwadi yii l’ọpọ igba fun awọn eto iṣẹ iwadi. Bi nkan ko ba gberu pẹlu abojuto ti o kun oju oṣunwọn, a le ṣe awọn ayẹwo siwaju sii lati ṣayẹwo fun bakiteria.
Kúrùpù Ọrọ naa "kúrùpù" wa lati ọrọ-ìṣe "croup," Ede Gẹẹsi Igbalode ti ati ibẹrẹ ti o tumọ si "lati sọkun pẹlu ohùn kíkẹ̀"; akọkọ lo orukọ naa fun aisan naa ni orile-ede Sikotilandi ti o si wa gbajumọ ni ẹgbẹrun ọdun kejidinlọgun (18th century). A ti mọ kúrùpù diphtheritic lati igba Homer Giriki Atijọ. Ni ọdun 1826, Bretonneau da mọ yatọ kúrùpù ti fairọsi fa ati kúrùpù ti o waye lati ọwọ diphtheria. Awọn Faranse npe kúrùpù ti fairọsi fa ni "faux-croup," nipa lilo "kúrùpù" fun arun ti bakiteria diphtheria fa. Kúrùpù ti diphtheria fa ni o fẹẹ jẹ wipe a ko mọ nitori imunadoko abẹrẹ ajẹsara.
Kúrùpù A ti ṣe iwadi fun awọn abojuto miiran fun kúrùpù, ṣugbọn ko ti si ẹri ti o to lati ṣe atilẹyin fun lilo wọn. Mimi ikuuku gbigbona simu tabi atẹgun jẹ ọ̀nà atọwọdọwọ lati ṣe abojuto ṣe abojuto ara-ẹni, ṣugbọn awọn ẹkọ iwadi iṣegun oyinbo kuna lati fi mumunadoko mulẹ ati lọwọlọwọ a kii saba lo o. Lilo awọn oogun ikọ́, eyi ti o maa ni dextromethorphan ninu ati/tabi guiafenesin, ni a ko gba ni niyanju lati lo. Nigbati fifa heliox simu (idapọ helium ati oxygen) lati din iṣẹ mimi ku ni a ti lo ni atẹyin wa, ṣugbọn ẹri ti o kere jọjọ lo wa lati ṣe atilẹyin fun lilo rẹ. Nitori kúrùpù lọpọ igba jẹ arun ti fairọsi nfa,awọn oogun apakokoro ni a kii lo a fi bi a ba fura si bakiteria. Apakokoro vancomycin ati cefotaxime ni a gba ni niyanju fun awọn arun bakiteria. Ni awọn iṣẹlẹ ti o lewu ti o rọ mọ ọfinki A tabi B, agbogun ti fairọsi neuraminidase inhibitors ṣee lo.
Streptococcal pharyngitis Ayẹwo nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun ti o ri bẹẹ (ni ọrọ miiran, eyiti o mo wipe eniyan ṣe aisan) tabi ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan, pẹlu awọn aami aisan ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju ri nfa, nfidi wiwa aisan naa mulẹ. A ko gbọdọ maa ṣe ayẹwo nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun tabi ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan loorekoore fun awọn eniyan ti ko ni aami aisan. Ida awọn eniyan kan l’awujo ni kokoro aifoju lasan ri streptokokal bakiteria naa ninu ọfun wọn lai si abajade ewu kankan.
Streptococcal pharyngitis Ọna-ọfun to ndun ni eyiti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa(Strep throat)jẹ aisan ti awọn kokoro to nfa arun ti a npe ni “ẹgbẹ bakiteria streptokokal ti A” nfa. Ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa maa nyọ ọna-ọfun, awọn belubelu (awọn gilandi ribiti meji ti o wa ni ọna-ọfun, ni ẹyin ẹnu), ati bi o ba ṣee ṣe apoti ohùn (larynx)lẹnu. Awọn aami aisan ti o wọpọ ní ninu ibà, ọna-ọfun ti o ndun ni(ti a tun npe ni ọọfun to ndun ni, ati awọn nodu ẹjẹ funfun ti o wu (lymph nodes) ni ọrùn. Ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa maa nfa ida mẹtadinlogoji ninu ọgọrun (37%) ọna-ọfun ti o ndun ni laarin awọn ọmọde.
Streptococcal pharyngitis Ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa maa ntan nipasẹ ifarakora pẹkipẹki pẹlu alaisan kan. Lati rii daju wipe eniyan kan ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa eyiti o ndun ni, ayẹwo kan ti a npe ni mimu awọn nkan ẹlẹmi dagba lori nkan amu nkan ẹlẹmi dagba l’ode ara lati inu ọna-ọfun (throat culture)fun iwadi ṣe pataki. Lai ṣe ayẹwo yii papa ẹwẹ, a le mọ nipa ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan nfa nipasẹ awọn aami aisan. Ni eyiti o jọ bẹẹ tabi ti a mọ daju, awọn apakokoro(antibiotics)(awọn oogun ti o npa bakiteria) le dẹkun aisan naa lati ma l’ewu gan-an ati lati mu ara pada bọ s’ipo ni kiakia.
Streptococcal pharyngitis ọna-ọfun to ndun ni(tabi faringitisi), iṣori ti o gbòòrò ninu eyiti ti ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri wa, ni a ṣe awari rẹ ninu awọn eniyan milliọnu mọkanla (11 million) l’ọdọọdun ni orilẹ-ede Amẹrika. Fairọsi ni o ma nfa ọpọlọpọ iṣẹlẹ ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa. Ṣugbọn, ẹgbẹ bakiteria ti kokoro ti a ko f’oju ri ti bita A (group A beta-hemolytic streptococcus)maa nfa ninu ọgọrun ida 15 si 30 ọfun ti o ndun ni laarin awọn ọmọde ati 5 si 20 laarin awọn agbalagba. Awọn iṣẹlẹ maa nsaba waye nigba ti jijabọ yinyin baa nkasẹ nlẹ ti Ợrinrin (Spring)si ṣẹṣẹ nbẹrẹ.
Streptococcal pharyngitis Awọn kokoro to nfa arun(tabi bakiteria)ti a npe ni ẹgbẹ streptokokus ti bita A (A beta-hemolytic streptococcus) (GAS)lo nse okunfa ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa. Awọn kokoro miiran to nfa arun tun le fa ọna-ọfun ti o ndun ni. Ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa maa ntan nipasẹ ifarakora pẹkipẹki ni taara pẹlu alaisan kan. Ợpọ̀ eniyan, bii awọn ti o wa ni ọmọ-ogun tabi awọn ile-iwe maa mu bi aisan naa ti ntan kaakiri lati pọ sii. Awọn kokoro to nfa arun ti a ko le f’oju ri ti wọn ti gbẹ tan ti a si ri ninu erupẹ ko le sọ eniyan di aláàárẹ̀. Awọn kokoro to nfa arun ti ko tii gbẹ, bii eyiti a ri lori pako-oyinbo (burọṣi), le jẹ ki eniyan ṣe àárẹ̀fun bi ọjọ mẹẹdoogun (15 days). Ko wọpọ ki awọn kokoro to nfa arun ti a ko f’oju ri yii lati gbe ninu ounjẹ ki wọn si mu awọn ti wọn jẹ ounjẹ naa ṣe àárẹ̀. Ida mejila ninu ọgọrun awọn ọmọde ti ko ni awọn aami aisan kan fun ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa ngbe GAS awọn kokoro ti o nfa arun kaakiri ninu ọfun wọn.