Top 10 similar words or synonyms for pese

nwaye    0.998055

bakiteria    0.997656

dinku    0.997327

imu    0.997262

tire    0.997050

oru    0.996494

laisi    0.996395

ọmọde    0.996252

afefeayika    0.996251

oore    0.995977

Top 30 analogous words or synonyms for pese

Article Example
Ìwọ́ ìtanná Ìwọ́ iná n pese pápá gbéringbérin (magnetic field). A le wo papa gberigberin bii ọ̀pọ̀ ìlà to yi waya po.
Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): E equip: (They equiped themselves for the expedition.) pese-pèsè ohun èlò fún Wón pèsè fún ara won fún ìrìn-àjò náà.
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró September 11, 2001 Awon arinajo miran se ipe telifonu nipa lilo telifonu ati telifonu alagbeka, won si pese ekunrere ohun to un sele, ninu re nipe awon melo kan ninu awon afipagboko wa ninu awon baalu ohun, pe ata tabi iru awon ifon kemika noxious, bi efuufu ataju tabi ifon ata je lilo, ati pe won ti fi obe gun awon.
Ikot Abasi Ikot Abasi, je awujo ni nu igberiko Calabar, fun idi ti o dara. Biotilejepe Ikot Abasi, tẹlẹ je ipa ti ilu olokiki Opobo Kingdom, wà tẹlẹ lori iwe itokasi aye ṣaaju akoko 1929, ti awọn obirin lodi si olori amunisin ti Nàìjíríà ni odun 1929 je lati pese siwaju titari sinu ọlá fun ilu yi.
Júpítérì Júpíta je ise awari pelu opolopo akitiyan nipa lilo oko-ofurufu roboti, agaga nigba ti awon asewadi akoko bii: Pioneer ati Voyager leyin awon wonyii ni Galileo orbiter. Oko iwadi to pese lo si Júpítérì ni oko-ofurufu to n lo si Pluto, New Horizons ni opin osu Irele 2007. Oko iwadi yi lo iwolura lati odo Júpíta lati fun ni agbara ere pupo. Awon iwakiri ojo iwaju ninu sistemu Jofia ni wiwa omi ti ti yinyin bo mole ninu osupa Europa.
Òrùn Òòrùn ni ìràwọ̀ ti o wa ni arin Sistemu Orun. Ile-aye ati awon ohun miran (awon planeti yoku, onirawo, olokuta, okutaina ati eruku) won n yipo òòrùn, ti o se fun ra re nikan ni itobi 99.8% gbogbo eto oorun. Okun lati inu oorun gege bi ooruntitan n pese fun awon ohun elemi lona ti a mo si ikommolejo (photosynthesis), be ni orun lo n so bi igba ati oju-ojo se n ri.
UNESCO-IHE Làti ìsèdálè re wa ni odún 1957, IHE- gégé bi ati moosi- ti pese èkó àgbà fún àwon amòye (onímò èro àti siensi) tí ólé ni egbèrún mérìnlá, òpòlopò won làti àwon orílè èdè to sèsè n'dìde alè ,lápapò bi orílè èdè ogójo. O ti fi oyè fún àwon òmòwé ti ólé ni aarun di l'ogorin, bakan naa o ti se àwon isé ìwádî ìjìnlè àti ti igbe ni n'igunpa sókè kakakiri àgbáyé.
Àdìjọ ìtanná Àdìjọ ìtanná tabi àdìjọ iná (electric charge) adamo ipilese ifipamo awon igbonwo abeatomu ti o n so bi abasepo inagberigberin won se je. Ohun ti o ba ni agbara ina n pese papa inagberingberin eyi si n nipa lori re. Ibasepo larin agbara ina to n gbera lo ati papa inagberingberin ni o n fa Ipa inagberingberin (electromagnetic force), ti o je ikan larin merin ipilese ipa.
C++ C++ je ikan lara awon ede ti o gbajumo pelu apilication domain ti o ni sisitem software ninu (gege bi Microsoft Windows), application software, device drivers, embedded software, high-performance server ati client applications, pelu software idaraya gege bi video games. ai moye akojopo ni o man pese C++ ofe ati propreitary compiler software, pelu GNU Project, Microsoft, Intel ati Embarcadero Technologies. C++ ti je arikoshe ti o ni agbara fun awon ede programming yoku tio gbajumo , e yin ti o gbajumo ju C# ati Java.
Nelson Mandela Leyin ti egbe oselu Egbe Omoorile-ede egbe oseluAfrikaner ninu eto idibo odun 1948, nitoripe awon wonyi fowo mo eto apartheid's apartheid's apartheid's eleya-meya, Mandela bere si ni kopa gidigidi ninu oro oselu. O siwaju ninu Kampein Agidi ti ANC se ni 1952 ati ninu Kongresi awon eniyan ni 1955 ti pinu ti abajade re je ipile eto ilodi si ise eleya-meyaanti apartheid. Larin asiko yi, Mandela ati agbejoro re Oliver Tambo da ile-ise agbejoro Mandel's ati Tambo sile lati pese imoran ofin ofe fun opo awon alawodudu ti won ko ni agbejoro.