Top 10 similar words or synonyms for nwaye

afefeayika    0.998286

bakiteria    0.998245

pese    0.998055

imu    0.997660

npa    0.997481

olowo    0.997466

akoran    0.997244

iriri    0.997231

obo    0.996999

oku    0.996974

Top 30 analogous words or synonyms for nwaye

Article Example
Kúrùpù Kúrùpù ti o niiṣe pẹlu bakiteria ṣee pin si laryngeal diphtheria, bacterial tracheitis, laryngotracheobronchitis, ati laringotrakiobronkopneumonitisi. Laringeal diphtheria maa nwaye nitori "Corynebacterium diphtheriae" nigbati bakiteria trakitisi, laringotrackiobronkaitisi, ati laringotrakobronkopneumonitisi maa nwaye nitori fairọsi, pẹlu bakiteria ti o lọwọ sii. Awọn bakiteria ti o wọpọ julọ ni"Staphylococcus aureus", "Streptococcus pneumoniae", "Hemophilus influenzae", ati "Moraxella catarrhalis".
Anafilasisi O le ṣoro nigba miiran lati da anafilasisi mọ yato si [[ikọ-ifee]], [[didaku]], ati [[awọn ikọlu ijaya]]. Ṣugbọn ikọ-ifee kii saba ni ara ti njanijẹ tabi aami aiṣan ti ifun ninu, didaku ma nwaye pẹlu ara ti o funfun dipo ara ti njanijẹ, ati ikolu ijaya le ni ara ti o pọn ṣugbọn kii ni wiwu ti o pọn to nyun ni eyiti o nwaye nitori ikorira ara si nkankan. Awọn nkan miiran ti o le waye tun ni ninu: [[Ikọlu nipa majele ounjẹ nipasẹ ẹja|skrombroidosisi]] ati [[aiṣan ti o nwaye nipa jijẹ ẹja ti a ko sè]].
Kúrùpù Fairọsi le fa kúrùpù. Awọn eniyan kan lo ọrọ naa lati ni ninularingotrakiaitisiti o lewu, kúrùpù ti o ṣẹlẹ logiji fun igba diẹ, laringeal diphtheria, trakiatisi ti bakiteriali fa, laringotrakiobronkaitisi, ati laringotrakiaobronkoneumonitisi. Ipo meji akọkọ ni ninu fairọsi kan ti o si ni aami aisan ti ko nira; awọn mẹrin ti o kẹyin maa nwaye lati ọwọ bakiteria wọn si maa nlewu gan-an.
Anafilasisi Bi ara ṣe nṣe si nkan kan dale lori bi a ti ṣe nlo ni apakan ati ni apakan awọn abuda ti nkan yii ni ninu. Anafilasisi si pẹnisilini tabi[[sẹfalosiporini]] nikan maa nwaye lẹyin ti wọn ba sopọmọ awọn protini ninu ara ti awọn nkan kan maa ntete sopọmọ pẹlu irọrun ju awọn miiran lọ. Anafilasisi si pẹnisilini maa nwaye ni ẹẹkan ninu 2,000 si 10,000 iṣẹlẹ fun itọju, ti iku si maa waye ni eyiti o kere ju ookan ninu 50,000 iṣẹlẹ fun itọju. Anafilasisi si aspirini ati awọn NSAID maa nwaye ni bii ẹẹkan ninu eeyan 50,000. Bi ẹnikan kan ba ni bi ara rẹ ṣe nṣe si pẹnisilini ti ko dara ewu bi ara wọn yoo ṣe ṣe si sẹfalosporini yoo gaju ṣugbọn yoo si kere sii ookan ninu 1000. Awọn nkan ayẹ ara wo atijọ maa nmu bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi ni 1% awọn iṣẹlẹ nigbati awọn titun maa nmu bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi ni 0.04% awọn iṣẹlẹ wa.
Anafilasisi Lori ipele nipa ayipada ti aiṣan ṣe okunfa ati ẹkọ nipa wọn, anafilasisi maa nwaye nipa jijọwọ awọn olulaja kan lati awọn oriṣi sẹẹli ẹjẹ funfun ti a taji yala nipa ajẹsara tabi awọn eto ti ko nii fiṣe pẹlu ajẹsara. A maa nṣe ayẹwo rẹ nipa awọn aami ti o nfarahan lọwọ lọwọ. Ọna itọju akọkọ ni nipa fi fun ni l’abẹrẹ efinifirini, pẹlu awọn ọna miiran ti o nṣiṣẹ papọ pẹlu rẹ.