Top 10 similar words or synonyms for efinifirini

iba    0.995932

kin    0.995711

abẹrẹ    0.995042

eku    0.994588

ọmọde    0.994123

nbo    0.993966

oru    0.993965

rorun    0.993726

dinku    0.993427

taara    0.993360

Top 30 analogous words or synonyms for efinifirini

Article Example
Anafilasisi Awọn eniyan ti o nlo [[β-blockers]] le ṣiṣẹ lodi si iṣẹ efinifirini. Ni ipo yii bi efinifirini ko ba ṣiṣe nipasẹ iṣan a le fun ni ni [[glukagoni]] eyiti o ni bi o ṣe maa nṣiṣe ti ko da lori [[β-receptor]].
Anafilasisi Bi o ba nilo, a tun le fun ni ni [[Ọna abojuto nipa fifi nkan sinu iṣan| fifi nkan sinu iṣan]] nipa lilo efinifirini olomi ti a ti là. Ṣugbọn a ti ri asopọ mọ [[Cardiac dysrhythmia|dysrhythmia]] ati [[myocardial infarction]]ninu efinifirini ti a fun ni nipasẹ iṣan. [[Abẹrẹ to nfun ni ni efinifirini fun ra rẹ]]ti a nlo fun fifun ara ẹni ni abẹrẹ ni eemeji, ọkan fun awọn agbalagba tabi ọmọde ti iwọn wọn kọja 25 kg ati ọkan fun awọn ọmọde ti iwọn wọn to 10 si 25 kg.
Anafilasisi Awọn iṣẹ kan nlọ lọwọ lati ṣẹda efinifirini [[sublingual]] lati ṣe itọju anafilasisi. [[Abẹrẹ si abẹ ọra ara]] ti o lodi si IgE (anti-IgE) antibody [[omalizumab]] ni a nṣe ayẹwo gẹgẹ bii ọna lati dẹkun pipada, ṣugbọn a ko ti gba ni niyanju lilo rẹ.
Anafilasisi [[Efinifrini]] (adrenaline) jẹ ọna itoju akọkọ fun anafilasisi laisi [[ewu ti o gba ẹmi kankan]] lati lòó. A gba ni niyanju ki a fun ni ni efinifirini olomi [[lati inu iṣan]] si inu itan ni kete ti a ba kiyesi ayẹwo. Bi ko ba si abajade ti o dara to, a tun le tun abẹrẹ naa fun ni ni gbogbo iṣẹju 5 si 15 si ara wọn. A nilo fifun ni ẹlẹẹkeji ninu 16 si 35% awọn iṣẹlẹ ninu eyiti fifun kọja eemeji kii saba nilo. Ọna lilo ti a ngba fun ni nipasẹ iṣan jẹ eyiti a yan ṣaaju [[ọra abẹ́ awọ]] nitori ti eyiti ti o keyin le ma tete ṣee fa sinu ara. Awọn nkan ti ko dara diẹ nipa lilo efinifirini ni ninu [[gbigbọn]], [[aibalẹ ọkan]], efọri, ati [[iro ọkan ti ko ṣe deede]].
Kúrùpù Kúrùpù ti o mọ niwọnba tabi ti o lewu ṣee ran lọwọ pẹlu nebulized efinifirini(nkan olomi ti a nfa simu lati jẹ ki ọ̀nà-atẹgun le fẹ) Nigbati efinifirine lọpọ igba maa ndin ewu kúrùpù ku laarin iṣẹju mẹwa si ọgbọn (10–30 minutes), awọn anfaani maa npẹ fun bii wakati meji. Bi ipo ba tẹsiwaju lati gberu fun wakati 2–4 lẹyin abojuto ti ti nkan ti ko rọgbọ kankan ko si ṣẹlẹ, omo naa le fi ile-iwosan silẹ.