Top 10 similar words or synonyms for abẹrẹ

NotFoundError    0.789

Top 30 analogous words or synonyms for abẹrẹ

Article Example
Kúrùpù Abẹrẹ ajẹsara (oogun abẹrẹ ajẹsara) fun influenza ati diphtheria le dẹkun kúrùpù.
Anafilasisi [[File:Epipen.jpg|thumb|Ẹya abẹrẹ atijọ ti EpiPen kan]]
Anafilasisi Bi o ba nilo, a tun le fun ni ni [[Ọna abojuto nipa fifi nkan sinu iṣan| fifi nkan sinu iṣan]] nipa lilo efinifirini olomi ti a ti là. Ṣugbọn a ti ri asopọ mọ [[Cardiac dysrhythmia|dysrhythmia]] ati [[myocardial infarction]]ninu efinifirini ti a fun ni nipasẹ iṣan. [[Abẹrẹ to nfun ni ni efinifirini fun ra rẹ]]ti a nlo fun fifun ara ẹni ni abẹrẹ ni eemeji, ọkan fun awọn agbalagba tabi ọmọde ti iwọn wọn kọja 25 kg ati ọkan fun awọn ọmọde ti iwọn wọn to 10 si 25 kg.
Anafilasisi Awọn iṣẹ kan nlọ lọwọ lati ṣẹda efinifirini [[sublingual]] lati ṣe itọju anafilasisi. [[Abẹrẹ si abẹ ọra ara]] ti o lodi si IgE (anti-IgE) antibody [[omalizumab]] ni a nṣe ayẹwo gẹgẹ bii ọna lati dẹkun pipada, ṣugbọn a ko ti gba ni niyanju lilo rẹ.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Iye-nísirò akoran kokoro ga ni awọn orilẹ ede kan ni Afrika ati Asia. Awon orilẹ ede ti o ni iye akoran kokoro ti o ga ni Egypt (22%), Pakistan (4.8%) ati China (3.2%). Giga rẹ ni Egypt so mọ ìdádúró ìpolongo ìtọjú gbogbogbòò fun schistosomiasis, lilo abẹrẹ onídígí ti a ko fọ mọ daradara.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Ọ̀nà àkọ́kọ́ tí àìsàn n gbà tàn kálẹ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè ti wọn ti gòké-àgbà ni gbígba abẹ́rẹ́ sínu iṣan-ara (IDU). Ní àwọn orílẹ̀-èdè ti n gòké-àgbà ọ̀nà tí ó wọ́pọ̀ níbẹ̀ ni nípa gbígba ẹ̀jẹ̀ sí ara àti àwọn ọ̀nà ìtọ́jú aláìsàn tóléwu Ìdá ogún ninu ọgọ́rùn ún ọ̀nà yóòkù tí àìsàn gbà tàn kálẹ ni ó sì farasin síbẹ̀; sùgbọ́n ọ̀pò ninu àwọn ọ̀nà lè máa ṣe ẹ̀yìn gbígba abẹrẹ sinu iṣan ara, IDU.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Ti ti di 2011, ko si abęrę fun àrùn jẹdọjẹdọ C. Awon abęrę ṣi wa ni ipele imudagba, ati wipe awọn kan si ti fi esi iwunilori han. Àgbájọpọ awọn ìlànà ìdádúró, gẹgẹbi awọn ètὸ fun ipàsípààrọ abęrę ati itọju fun oὸgùn ìlòkulò, jęki ewu àrùn jẹdọjẹdọ C laarin awọn to ngbabęrę oògùn inu iṣan dinku si ìdá marun-din-lọgọrin ninu ọgọrun. Iṣewadii awọn olufęjẹsilẹ ṣe pataki ni orilẹ- ede, gẹgẹbi o ṣe wa ni ibamu pęlu titęle àkíyèsára gbogbogbòò ni ti ilera. Ni awọn orilẹ ede ti awon abęrę ti a ti fọ kὸ pọ tó, awọn olutọju gbọdọ funni l’ogun lilo dipo gígún ni abẹrẹ.
Kúrùpù Ọrọ naa "kúrùpù" wa lati ọrọ-ìṣe "croup," Ede Gẹẹsi Igbalode ti ati ibẹrẹ ti o tumọ si "lati sọkun pẹlu ohùn kíkẹ̀"; akọkọ lo orukọ naa fun aisan naa ni orile-ede Sikotilandi ti o si wa gbajumọ ni ẹgbẹrun ọdun kejidinlọgun (18th century). A ti mọ kúrùpù diphtheritic lati igba Homer Giriki Atijọ. Ni ọdun 1826, Bretonneau da mọ yatọ kúrùpù ti fairọsi fa ati kúrùpù ti o waye lati ọwọ diphtheria. Awọn Faranse npe kúrùpù ti fairọsi fa ni "faux-croup," nipa lilo "kúrùpù" fun arun ti bakiteria diphtheria fa. Kúrùpù ti diphtheria fa ni o fẹẹ jẹ wipe a ko mọ nitori imunadoko abẹrẹ ajẹsara.
Kúrùpù Awọn kotikositẹrọidi, bii desamẹtasone ati budesonide, ṣee lo lati ṣe abojuto kúrùpù awọn ọmọde. A maa nri itura to ni apẹẹrẹ ni bii wakati mẹfa lẹyin abojuto. Bi o ti le jẹ wipe awọn ogun yii nṣiṣẹ nigbati a ba fun ni lati ẹnu (nipasẹ ẹnu), parenteral (nipasẹ abẹrẹ), tabi fi fa si imu, ọ̀nà ti a yan laayo ni nipasẹ ẹnu. Fi fun ni lẹẹkan jẹ gbogbo nkan ti a nilo, eyiti ọpọ si fi ara mọ wipe ko lewu. Desamẹtasone ni idiwọn 0.15, 0.3 ati 0.6 mg/kg tun jọ wipe ohun naa muna doko.
Anafilasisi Awọn eniyan ti o ni awọn aiṣan [[nini iha si nini awọn nkan ti ara korira]] bii [[ikọ-ifee]], [[lapalapa]], tabi [[allergic rhinitis]] wa ninu ewu ti o ga lati ni anafilasisi lati inu ounjẹ, [[oje]], ati [[nkan ti a fi nwo bi nkan ṣe ri ninu ara]] lai nii lati ara oogun ti a fun ni nipasẹ abẹrẹ tabi kokoro to t’ani. Ẹkọ kan ninu awọn ọmọde ṣe iwadi pe 60% ti ni itan aiṣan nini iha si nini awọn nkan ti ara korira tẹle, ati pe fun awọn ti o ku lati ọwọ anafilasisi awọn ti o gaju 90% ni ikọ-ifee. Awọn ti wọn ni [[masitosaitosisi]] tabi ti [[ipo iṣuna owo]] wọn ga wa ninu ewu ti o pọ. Bi iye akoko ti eniyan fi ni ifarako si nkan ti a ti tọka si pe o nfaa ṣe pẹ si bẹẹ ni ewu rẹ ṣe lọ silẹ si.