Top 10 similar words or synonyms for bakteria

ayafi    0.996169

safihan    0.995247

karibeani    0.995203

tabili    0.995136

igbega    0.994846

aiye    0.994816

eyun    0.994720

paapaa    0.994658

kale    0.994122

aginju    0.993917

Top 30 analogous words or synonyms for bakteria

Article Example
Baktéríà Baktéríà (; "ìkan": Bakterio) je idipo ninla awon ohun elemintintinni prokarioti ti won ni ahamo eyokan. Gigun won je mitatintinni, idasi bakteria je orisirisi, lati roboto de opa de ilo. Bakteria wa nibi gbogbo ni ile-aye, won wu ninu erupe, omi kikan gbigbona, idoti,omi, ati jinjin ninu ile aye, bakanna ninu elo elemin, ati ninu ara awon ogbin ati eranko. 40 legbegberun ahamo bakteria ninu erupe gramu kan be sini egbegberun kan ahamo bakteria lo wa ninu omi; lapapo egbegberunkesan marun (5×10) bakteria lowa ni aye ti won sedajo opo isupoalaaye ni agbaye.
GFAJ-1 GFAJ-1 je bakteria kan ninu ebi Halomonadaceae to je pe, ti ko ba ni fosforos, le lo apilese oloro arsenik ninu DNA re.
Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ da lori idimu ati imuse oniakinkinni awon abinimo, pelu iwa abinimo ninu ahamo tabi adirajo (f.a. ilagbaralori ati isiseabinimoju), pelu ogun latodo obi si omo, ati pelu ipinkari, iyasoto ati iyipada larin awon olugbe. Nitoripe awon abinibi wa ninu gbogbo awon adirajo alaaye, isiseabinibi se lo lati se akomo gbogbo awon sistemu alaaye, latori awon eran ati bakteria, de ori awon ogbin (agaga awon eso oko) ati awon eran osin, de ori awon eniyan (bi ninu isiseabinibi oniwosan).
DNA Ninu awon ahamo DNA je gbigbajo si idimu gigun kan to unje kromosomu. Nigba ipin ahamo awon kromosomu yi je didameji ninu igbese itunda DNA, to si unpese fun ahamo kookan awon kromosomu pipe tikookan fun won. Awon agbarajo eukarioti (awon eranko, ogbin, ehu, ati protisti) ko opo awon DNA won pamo sinu kóróonú àhámọ́ ati awon DNA won miran sinu awon apainu àhámọ́, bi mitokondria tabi adáláwọ̀. Lafiwe si awon prokarioti (bakteria ati arkea) ti won unko DNA won pamo sinu idanuahamo nikan. Ninu awon kromosomu, awo proteini kromatini bi histoni undipo o si unsegbajo DNA. Awon idimu idipo yi unselana ibasepo larin DNA ati awon proteini miran, nigba tounsejanu awon apa DNA wo ni yio sawoko.