Top 10 similar words or synonyms for paapaa

bose    0.997124

alagbewo    0.996035

tabili    0.995917

irojinle    0.995852

eyun    0.995750

kale    0.995286

anabi    0.995202

kookan    0.995026

karibeani    0.994723

bakteria    0.994658

Top 30 analogous words or synonyms for paapaa

Article Example
Felix Abidemi Fabunmi Omowe Felix Abidemi Fabunmi ti sise iwadii lori ede ati imo eda-ede Yoruba, o tun n sise lori awon eka-ede Yoruba paapaa awon eka-ede Yoruba to wa leyin-odi Naijiria. Die lara awon ise re to ti te jade niwonyi:
T.M. Ilésanmí Bi a ba n wo akojopo ati akosile imo-iwe ojogbon yii, a o rii pe o ni ifokantan ati iteramose. O ti sese di araba ni idi ifi-imo-soro, paapaa, ni eka eko asa Yoruba. Awon iwadii Ojogbon Ilesanmi lori awon ayeye irubọ ati itan ibile se gboogi, won si je itokasi ninu imo isewadii lori Yoruba. Akonimora ati onirele, Ojogbon Ilesanmi ti se agbekale opolopo akosile to je alariyanjiyan, alarojinle ati alakiyesi lori ipede ati ewi Yoruba.
Àyàn Iṣẹ́ ìlù lílú ni a n pe ni ìṣẹ́ àyàn, àwọn ti o n sẹ iṣẹ yii ni a n pe ni “Aláyàn tàbí ‘Àyàn’. Iṣe àtìrandíran ni èyi, nitori iṣẹ afilọmọlọwọ ni. Gbogbo ọmọ ti Onílù bá bí sí ìdi Àyàn Agalú ni o ni láti kọ ìlù lílù, paapaa akọbi onílù. Dandan ni ki àkọ́bí onílù kọ iṣẹ ìlù, ko si maa ṣe e nitori àwọn onìlu ko fẹ ki iṣẹ́ náà parun.
Arthur Wellesley, 1st Duke of Wellington Arthur Wellesley, 1st Duke of Wellington, Field Marshal KG, KP, GCB, GCH, PC, FRS (c. 29 April/1 May 1769 – 14 September 1852), je omo Ilegeesi Irelandi jagunjagun ati agbaalu, ati ikan larin awon asiwaju eniyan ologun ati oloselu orundun kandinlogun. O je titokasi bi "The Duke of Wellington" lasan, paapaa leyin iku re, nigbati awon Dukes of Wellington miran na ti joye. O tun di Alakoso Agba orile-ede Britani tele.
Ìmàle Ohun ti oun n je kadara ni nini igbagbo pe Olohun (Allah) ni O pebubu gbogbo ohun ti n be, Ohun ni O si da gbogbo eda ni ona ti mimo Re ti siwaju re ti ariwoye Re si fe bee. Gbogbo awon alaamori ni o ti je mimo ni o si ti wa ni akoole ni odo Re. Olohun (Allah) fe gbogbo ohun ti n sele ni o je ki o maa sele bee, Oun paapaa ni o si daa.