Top 10 similar words or synonyms for aginju

tounje    0.994545

ayafi    0.994336

paapaa    0.994086

ewon    0.994043

bakteria    0.993917

yinyin    0.993611

tabili    0.993073

ogunlogo    0.992873

niwaju    0.992768

klein    0.992506

Top 30 analogous words or synonyms for aginju

Article Example
Bòtswánà Botswana je petele, be sini 70% je bibomole pelu Aginju Kalahari. O ni bode mo orile-ede Guusu Afrika ni gusu ati gusuilaorun, Namibia ni iwoorun ati ariwa, ati Zimbabwe ni ariwailaorun. Bode re mo Zambia ni ariwa nitosi Kazungula, Zambia ko fi be nitumo sugbon ko gun ju bi ogorun mita lo.
Ògbójú Ọdẹ nínú Igbó Irúnmọlẹ̀ “Nigbati o to bi wakati kan mo jade ninu iho yi si gbangba, mo mu okuta nì mo fi i sinu apo ọdẹ mi nitori lati igbati iya ti bẹrẹsi jẹ mi yi, ibọn mi ati apo ọdẹ mi kò kuro lọwọ mi. Jijade ti mo si jade na ọkunrin kan ti orukọ rẹ njẹ Lamọrin ni mo ba pade: ọkunrin na ti ṣina si aginju igbẹ yi lati ọdun mẹta.
Bẹ̀lárùs Belarus, ( ; , ), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Belarus, je orile-ede ayikanule ni Apailaorun Europa, to ni bode bi owo-ago pelu Rosia ni ariwailaorun, Ukrein ni guusu, Poland ni iwoorun, ati Lithuania ati Latvia si ariwaiwoorun. Oluilu re ni Minsk; awon ilu re pataki miran tun ni Brest, Grodno (Hrodna), Gomel (Homiel), Mogilev (Mahilyow) ati Vitebsk (Viciebsk). Idalogorun ogoji re lo je igbo aginju, be sini apa okowo re to tobijulo ni ise agbe ati ise elero.
Indonésíà Kakiri awon opo erekusu re, Indonesia ni awon eya eniyan, ede ati esin otooto. Awon ara Java ni eya eniyan totobijulo, to si unbori loloselu. Indonesia ti sedagbasoke idamo kanna to ni ede orile-ede, orisi eya-eniyan, iseopo esin larin ogunlogo olugbe musulumi, ati itan iseamuin ati bi won se koju re.Motto orile-ede Indonesia, ""Bhinneka Tunggal Ika"" ("Okan ninu Opo"), tokasi awon opo orisirisi to da orile-ede yi. Botilejepe o ni olugbe pupo ati awon agbegbe sisupo ololugbe, Indonesia ni awon agbegbe aginju to ni opoelemin giga keji lagbaye. Botilejepe o ni awon ohun alumoni ile pupo aini unba ja gidigidi loni.
Brasil Nipa gbigbogun ti awon ara Fransi, awon ara Portugal diedie fe ile won de guusuilaorun, won si gbesele ilu Rio de Janeiro ni 1567, ati de ariwaiwoorun, nibi ti won ti gbesele ilu São Luís ni 1615. Won ran awon ologun losi igbo-aginju Amasoni won si bori awon ajagun Britani ati Holandi to wa nibe, ki won o to bere sini da abule ati ile ologun sibe lati 1669. Ni 1680 won de guusu nibi ti won da Sacramento sile si ni eba Rio de la Plata, ni agbegbe Etiomi Apailaorun region.