Top 10 similar words or synonyms for yòò

fóró    0.988930

afárá    0.986876

níyì    0.986817

darí    0.986743

gán    0.984932

farahàn    0.984152

ìÿe    0.983863

àsomọ    0.983224

thi    0.983114

sóde    0.982773

Top 30 analogous words or synonyms for yòò

Article Example
Àjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀ Àwọn àjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀ tí a fi kòkòrò tí a ti pa ṣe náà kò léwu rárá. Pípọ́n yòò ibi ojú abẹ́rẹ́ náà àti ìrora díẹ̀ lè wáyé. Àjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀ tí à ń gba ẹnu lò a má a ṣe òkùnfa àrùn rọpárọsẹ̀ tó níí ṣe pẹ̀lú ìmúlò àjẹsára náà nínú ìwọ̀n egbògi náà tó tó mẹ́ẹ̀ta nínú mílíọ̀nù kan. A lè lo oríṣi àjẹsára méjèèjì náà láìséwu bí ènìyàn bá ní oyún àti bí ènìyàn bá ní àrùn kògbóògùn HIV/AIDS ṣùgbọ́n tí ara rẹ̀ ṣì dá ṣáká.
Àjẹsára Bacillus Calmette–Guérin Àtúnbọ̀tán kíkankíkan kò fi bẹ́ẹ̀ wọ́pọ̀. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, ojú ibi abẹ́rẹ́ náà a má a pupa yòò, a má a wú, a sì má a dun ni. Ọgbẹ́-inú kékeré kán náà lè wáyé, pẹ̀lú àpá díẹ̀ lẹ́yìn tí ojú ibi abẹ́rẹ́ náà bá jiná. Àtúnbọ̀tán wọ́pọ̀ púpọ̀ lára àwọn ènìyàn tí agbára àti kojú àìsàn wọn kò bá múnádóko, a sì má a lágbára púpọ̀. Ó léwú láti lò ó nígbàtí ènìyàn bá lóyún. A ṣe àgbéjáde àjẹsára náà láti ara kòkòrò àìlèfojúrí kan tí à ń pè ní "Mycobacterium bovis" èyítí a má a ń sábà rí lára àwọn mààlúù. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a ti sọ kòkòrò náà di aláìlágbára, ó ṣì wà láàyè.
Àjẹsára àrùn dìgbòlugi A lè lò wọ́n láìséwu fún ẹnikẹ́ni pẹ̀lú ọjọ́-orí yòówù. Iye àwọn ènìyàn tó tó 35 sí 45 nínú ọgọ́ọ̀rún a má a ní ìrírí pípupa yòò àti dídunni ojú ibi abẹ́rẹ́ náà fún ìwọ̀n ìgbà díẹ́. Iye àwọn ènìyàn tó tó 5 sí 15 nínú ọgọ́ọ̀rún lè ní ibà, ẹ̀fọ́rí, tàbí kí èébì má a gbé wọn. Lẹ́yìn tí ènìyàn bá ti wà ní sàkání ibití ènìyàn ti lè kó àrùn dìgbòlugi, kò sí ohun tó ní kí ènìyàn má gba àjẹsára náà. Púpọ̀ lára àwọn àjẹsára náà kò ní ohun ti a n pè ní thimerosal nínú. Àwọn àjẹsára tí a ṣe pẹ̀lú iṣan-ara ni à ń lò ní àwọn orílẹ̀-èdè méèló kan, pàápàá ní Éṣíà àti Latin Amẹ́ríkà, ṣùgbọ́n agbára wọn kò pọ̀ púpọ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni àtúnbọ̀tán wọn pọ̀ púpọ̀. Nítorí náà ni Àjọ Ìlera Àgbáyé kò ṣe gba ni nímọ̀ràn láti má a lò wọ́n.
Àjẹsára Àwàlù Eyín Àjẹsára náà kò ní ewu kankan rárá, ó sì ṣeé lò bí ènìyàn bá lóyún àti bí ènìyàn bá ní àrùn HIV/AIDS. Ìrírí tó jẹ mọ́ pé kí ojú ibití a ti fún ni ní àbẹ́rẹ́ náà má a pupa yòò, kó sì má a dun ni a má a wáyé lára àwọn ènìyàn tó tó bíi 25 sí 85% nínú àwọn tó gba àjẹsára náà. Ibà, àárẹ̀, àti ìrora kékèké nínú iṣan-ara a má a wáyé lára àwọn ènìyàn tó kéré sí ìwọ̀n kan nínú ọgọ́ọ̀rún lára àwọn tó gba àjẹsára náà. Ìfèsì ara ẹni lọ́nà òdì sí ohun tí ènìyàn kòrira a má a wáyé lára àwọn ènìyàn tó kéré sí ìwọ̀n kan nínú 100,000 lára àwọn tó gba àjẹsára náà.
Àjẹsára ikọ́ọfe Àwọn àjẹsára aláìní sẹ́ẹ̀lì ni a má a ń sábà lò ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ti ní ìlọsíwájú nítorí àtúnbọ̀tán rẹ̀ tí kò ní ipá púpọ̀. Ibi ojú abẹ́rẹ́ lára iye àwọn ènìyàn tó tó 10 sí 50% tí a fún ní àjẹsára ẹlẹ́ẹ̀kún sẹ́ẹ̀lì a má a pupa yòò, wọn a sì má a ní ibà. Gìrì àti igbe-kíké fún ìgbà pípẹ́ a má a wáyé lára iye àwọn ènìyàn tó kéré sí ìwọ̀n kan nínú ọgọ́ọ̀rún. Pẹ̀lú àjẹsára aláìní sẹ́ẹ̀lì, apá-wíwú tí kò ni ni lára rárá lè wáyé fún àkókò díẹ̀. Àtúnbọ̀tán pẹ̀lú àwọn oríṣi àjẹsára náà méjèèjì, pàápàá jùlọ pẹ̀lú àjẹsára ẹlẹ́ẹ̀kún sẹ́ẹ̀lì, a má a kéré síwájú síi bí ọjọ́-orí ọmọ bá ti kéré sí. A kò gbọdọ̀ lo àjẹsára ẹlẹ́ẹ̀kún sẹ́ẹ̀lì fún ọmọ tí ọjọ́-orí rẹ̀ bá ti kọjá ọdún mẹ́ẹ́fà. Kò sí ìṣòro ọlọ́jọ́-pípẹ́ tó jẹ mọ́ àìsàn nínú iṣan ara pẹ̀lú èyíkéèyí nínú àwọn àjẹsára méjèèjì.