Top 10 similar words or synonyms for wàjà

akíkanjú    0.991628

òpìtàn    0.990206

àbò    0.987412

gòkè    0.987310

yòókù    0.986135

orísìí    0.984037

oríkì    0.983752

ira    0.982868

aláàfin    0.982858

ògbóni    0.982545

Top 30 analogous words or synonyms for wàjà

Article Example
Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà Tí ọ̀kan nínú wọn bá sì wàjà, ón ni ogún ti wọ́n máa ń jẹ lọ́dọ̀ ara wọn bí aya, ẹrú àti ẹrù.
Ìsèdálẹ̀ Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà Tí ọ̀kan nínú wọn bá sì wàjà, óun ni ogún ti wọ́n máa ń jẹ lọ́dọ̀ ara wọn bí aya, ẹrú àti ẹrù
Ìlú Ìrèlè Ògèyìnbó lọ sí Benin lati jọba. Ó dúró sí ọ̀dọ̀ Oba Benin pé baba òun tí wàjà, òun yóò sí jọba. Ọ̀rúnbẹ̀mékún náà lọ sí ọ̀dọ̀ Ìyá Ọba Benin pé òun náà fẹ jọba nígbà tí baba òun ti kú.
Ìlú Ìrèlè Ọba Uforami sì fún Àjànà ní adé, Àjànà padà sí Ìgbẹ́kẹ̀bọ́, ó bí Ọ̀rúnbẹ̀mẹ́kún àti Ògèyìnbó, ọkùnrin sì ni àwọn mejeeji. Kò pẹ́, kò sí jìnà, Àjànà wàjà. Àwọn ọmọ rẹ̀ mejeeji lọ si Benin lati jọba.
Ìlú Ìrèlè Ìwádìí fí yé wa wí pé ọmọ ọba Benin tó jọba sí ìlú Ugbò1 tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ Olúgbò-amẹ̀tọ́2 bí Gbáǹgbá àti Àjànà. Gbáǹgbá jẹ́ àbúrò Àjànà ṣùgbọ́n nígbà tí Olúgbò-amẹ̀tọ́ wàjà, àwọn afọbajẹ gbìmọ̀pọ̀ lati fi Gbáǹgbà jẹ ọba èyí mú kí Àjànà bínú kuro ní ìlú, ó sì lọ tẹ ìlú Ìgbẹ́kẹ̀bọ́3 pẹ̀lú Gbógùnrọ́n arakunrin rẹ̀.
Ẹfọ̀n-Alààyè Awọn òtìtọ́ kọ̀ọ̀kan farahàn nínú ìtàn yìí. Lóòótọ́ ni Ọbalùfọ̀n Aláyémọrẹ kan wá ni Ilé-Ifẹ̀. Títí dí oní ọ̀gbọ́n Ọbàlùfọ̀n wa ní Ilé-Ifẹ̀. Àdúgbò Aláayè si wa ní Ilé-Ifẹ̀ títí dí òní. Kò sí irọ́ níbẹ̀ pé Ẹ̀fọ̀n Aláayè bá Ilé-Ifẹ̀ tan. Nínú ìtàn mìíràn, a gbọ pé àwọn oríṣìí ènìyàn bí i mẹ́fà ni wọ́n tẹ̀dó lásìkò ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ sí Ẹ̀fọ̀n-Aláayè. Nínú ìtàn yìí, a gbọ́ pé Èkúwì ló kọ́kọ́ dé sílùú Ẹ̀fọ̀n-Aláayè, igbó-àbá ni Èkúwì tẹ̀dó sí. Ọdẹ kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Oríkin náà tẹ̀dó sí Igbó àayè. Lọ́jọ́ kan, lásìkò tí oríkin tẹ̀dó, ó rí iná tó ń rú ni Igbó-Àbá. Ó ṣe ọ̀dẹ lọ sí igbó yìí. Oríkin rọ àwọn tó wa ni Igbó àbá kí wọn jọ má gbé ní Igbó-Àayè. Wọ́n gbà bẹ́ẹ̀. Lásìkò tí wọn jọ ń gbé ni wọn fí Ọbàlùfọ̀n jẹ ọba. Igbákejì Ọbàlùfọ̀n tí wọ́n jọ wá láti Ilé-Ifẹ̀ ní wọn fi jẹ igbákejì ọba tí a mọ̀ sí Ọbańlá. Bàbá Igbó Àbá ọjọ́sí ni wọn fi jẹ baba ọlọ́jà tí a mọ sí Ọbalọ́jà. Ọbàlùfọ̀n àti Ọbalọ́jà jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ nígbà náà. Bí ọba ṣe ń pàṣẹ fún àayè ní Ọbalọ́jà ṣe n pàṣẹ ní Ọ̀bàlú láyé ìgbà náà. Lónìí, Ọbalọ́jà jẹ Olóyè pàtàkì ní ìlú Ẹ̀fọ̀n. Ọbalọ́jù ní olórí àwọn Ọ̀bàlú. Àjọṣe wá láàrìn Ọba àti Ọbalọ́jà. Bí ọba kan bá wàjà ní ìlú Ẹ̀fọ̀n-Aláayè, iwájú ilé ọba-ọlọ́ja ni wọn yóò kó ọjà lọ.