Top 10 similar words or synonyms for tropidurus

itọ    0.984995

microlophus    0.981013

íntótó    0.976935

adìẹ    0.976161

ńtúrì    0.975754

fonọ    0.975077

fáwẹ    0.974150

nílùú    0.973910

ìránlọṣe    0.973885

olófìn    0.973813

Top 30 analogous words or synonyms for tropidurus

Article Example
Tropidurus Kòsí orúkọ tí wọ́n mọ àwọn ẹ̀yà ìdílé "Tropidurus sí". In their native range they are simply called "iguanas" as are most similar animals. If anything, the Brazilian term calango is used to particularly refer to lizards of the genus "Tropidurus".
Tropidurus Tropidurus jẹ́ ìdílé àwọn ẹranko afàyàfà. Àwọn ẹ̀yà alángbá (ẹbí Tropiduridae) orí ilẹ̀ náà wà ní ìdílé"Tropidurus". "Tropidurus" jẹ́ ìdílé tị ọ jẹ́ ẹbí Tropiduridae, tí ó sì jẹ́ ẹbí alángbá iguanian.
Tropidurus A máa ń rí àwọn ẹ̀yà ìdílé "Tropidurus" ní òkè odò Gúúsù Amẹ́ríkà mainland, pàápàá ní igbó agijù igbóẹgàn ibi òjò Amazon àti àwọn ibi ọ̀gbẹlẹ̀
Tropidurus Àwọn ẹ̀ya wònyí ni ojúlówó tí wọ́n mọ̀ (wọ́n tò wọ́n bi ábídí).
Microlophus habelii Wọ́n fí "M. habelii" sí ìdílé "Microlophus" ṣùgbọ́n wọ́n ti kó wọn sí ẹ̀yà "Tropidurus", tí wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀ tẹ́lẹ̀.
Microlophus bivittatus Alángba àpáta San Cristóbal ("Microlophus bivittatus") jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos. Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé "Microlophus" ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé "Tropidurus" tẹ́lẹ̀.
Microlophus delanonis Microlophus delanonis, alángbà àpáta Española  tàbí alángbà àpáta Hood wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galapagos ti  Española. Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé "Microlophus" ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé "Tropidurus" tẹ́lẹ̀.
Microlophus duncanensis Microlophus duncanensis, jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos ti.  Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé "Microlophus" ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé "Tropidurus" tẹ́lẹ̀.
Microlophus peruvianus Microlophus peruvianus, ti Peru Pacific iguana, jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní Ecuador, Peru, àti Chile. Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé "Microlophus" ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé "Tropidurus" tẹ́lẹ̀
Microlophus grayii Microlophus grayii, tí wọ́n mọ̀ sí alángbá Floreana , jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos ti Floreana Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé "Microlophus" ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé "Tropidurus" tẹ́lẹ̀.