Top 10 similar words or synonyms for surulere

akure    0.998804

awka    0.998486

aniocha    0.998190

lagelu    0.997067

ifelodun    0.997066

amuwo    0.996752

clark    0.996740

alfred    0.996681

numan    0.996668

jega    0.996619

Top 30 analogous words or synonyms for surulere

Article Example
Surulere Surulere jẹ́ ibùgbé àti ibi iṣòwò agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ tó wà ní òke-odò ní Ìlú Èkó ní ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, agbègbè yíi tó ìwọn 23 km². ìkànìyàn tí wọ́n ṣe ní ọdún 2006 fihàn wípé ó kéré jù ènìyàn 503,975 ń gbé agbègbè yìi pẹ̀lú ìṣúpọ̀ olùgbé bíi 21,864 fún ìdá kan km².
Surulere Ibẹ̀ ni pápá ìdárayá ti orílë-èdè (ó gba èèyan 60,000) tí wọ́n kọ́ sí Ìlú Èkó ní ọdún 1972 fún eré ìdárayá gbogbo ilẹ̀ Áfíríkà wà. Pápá ìdárayá yìi ti ń di àkọ̀tí lati ọdún 2002. Síbẹ̀síbẹ̀, fún ìgbaradì fún ìdíje Under 17 FIFA World Cup tó wáyé ní ọdún 2009, ohun èlò pápá ìdárayá yìi rí àmójútó díẹ̀, ìdíje yií bẹ̀rẹ̀ láìsí ìdíwọ́ ní Oṣù kéwa ọdún 2009.
Surulere, Lagos State Surulere, Lagos State je ìlú ní Nàìjíríà.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Surulere, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Agbegbe Ijoba Ibile Surulere je agbegbe ijoba ibile ni Ipinle Oyo. Surulere ni oluilu re.
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Surulere, Ìpínlẹ̀ Èkó Agbegbe Ijoba Ibile Surulere wa ni Naijiria