Top 10 similar words or synonyms for olómìnira

kóngò    0.970183

túrkì    0.950970

ṣáínà    0.943898

ààrẹ    0.938388

áfríkà    0.928776

ọmọẹgbẹ    0.925852

kroatíà    0.925810

nàìjíríà    0.924281

orílẹ    0.917395

ède    0.916377

Top 30 analogous words or synonyms for olómìnira

Article Example
Helveti Olómìnira Helvetic Republic (1798–1803)
Weimar Olómìnira Gege bi Weimar Olómìnira ("Weimar Republic") (, ) ni awon olukoitan n pe orile-ede olominira onileasofin ti o je didasile ni 1919 ni Jemani lati dipo iru ijoba tobaluaye to wa tele, won soloruko fun Weimar, ilu ti igbimo ilana-ibagbepo ti pade. Sibesibe, oruko tonibise re si duro si "Deutsches Reich" ("Ile Obaluaye Jemani"; "German Empire"). Leyin Ogun Agbaye Akoko, ile olominira yi loyojade lati Ijidide Jemani ni November 1918. Ni 1919, igbimo ile apapo pade ni ilu Weimar, nibiti won ti ko ilana-ibagbepo tuntun fun Raik Jemani (German Reich), won gba ni 11 August. Iru oseluaralu asolominira kose nile ni ibere awon odun 1930, eyi samona fun igori aga NSDAP ati Adolf Hitler ni 1933. Botilejepe ilana-ibagbepo odun 1919 ko je fifagile fun tonibise, awon ofin ti ijoba Nazi se ni February ati March 1933, to je mimo bi "Gleichschaltung" ("coordination") tumosi pe ijoba le sofin to tako ilana-ibagbepo. Ilana-ibagbepo ko niyi mo; bi be, odun 1933 ni won gba bi opin Weimar Olominira ati ibere "Raik Keta" ti Hitler.
Weimar Olómìnira Ni odun 14 ti Weimar Olominira fi wao koju opolopo awon isoro, ninu won ni Owonpupo, awon oloselu alaseju ati awon ologun oto won, ati ikorira latowo awon asegun Ogun Agbaye Akoko. Sibesibe, o bori awon ilana buburu Iwe-ipinnu Versailles, o se atunse owonina, seisodokan iselu owo-ode ati sistemu onaojurin.
Tsẹ́kì Olómìnira Tsẹ́kì Olómìnira (Tsẹ́kíà; ; , , short form "Česko" ) je orile-ede ni Arin Europe. O ni bode mo Poland ni ariwailaorun, Jemani ni iwoorun ati ariwaiwoorun, Austria ni guusu ati Slovakia ni ilaorun. Orile-ede Tseki Olominira ti je omo egbe NATO lati 1999 ati Isokan Europe lati 2004. Bakanna o tun je omo egbe Agbajo fun Abo ati Ifowosowopo ni Europe (OSCE).
Rómù Olómìnira Romu Olominira (Latini: Res publica Romanorum) ni a n pe igba itan Romu ti awon ara Romu le oba ikeyin won kuro lori ite lati sepilese oselu. Igba oselu tabi igba olominira bere pelu iwolulo oba tokeyin ara Etruski, eyun Tarkuinu Onigberaga (Tarquinius Superbus) ni 509 kJ o si dopin pelu ibori Oktabiani lori Marku Antoni ni Ija Aktiomu ni 31 kJ.
Olómìnira Nagorno-Karabakh Orile-ede Olominira Nagorno-Karabakh (NKR) ( ', or Artsakh Republic ( ') je "de facto" orile-ede olominira to budo si agbegbe Nagorno-Karabakh (tabi agbegbe Artsakh) ni Guusu Kaukasu.
Orílẹ̀-èdè olómìnira Ijoba Olominira je iru ijoba eyi ti olori orile-ede ki se adobaje, tabi ọba, ti awon eniyan ibe tabi ijoba ti won yan, si je alaselorile lati se akoso orile-ede bi won se fe lai toro ase lowo elomiran. Ni ede Geesi, "republic" wa la ti "res publica" ede Latini to tumosi "ohun ode" tabi "ohun igboro".
Àsìá ilẹ̀ Tsẹ́kì Olómìnira Àsìá ilẹ̀ Tsẹ́kì Olómìnira je asia orile-ede Tsẹ́kì Olómìnira.
Olómìnira ilẹ̀ Kóngò (Léopoldville) Orile-ede Olominira ile Kongo () je aladawa olominira to je didasile leyin igba ti imusin Kongo Belgiomu gba ominira ni 1960. Oruko yi lo je titi di 1 August 1964, nigba ti won yi si Olominira Toselu ile Kongo, lati yatosoto si orile-ede keji toni bode mo to n je Olominira ile Kongo, imusin Kongo Fransi tele.
Orílẹ̀-èdè olómìnira alájọṣepọ̀ Ninu orile-ede apapo olominira, isejoba je pinpin larin ijoba apapo ati awon ijoba ipinle/ibile to wa ni be.