Top 10 similar words or synonyms for ológbìín

çni    0.994372

bíì    0.992804

alámọ    0.992506

dídẹ    0.992457

délé    0.992405

ìkòkò    0.992273

éè    0.991773

réré    0.991408

rèé    0.991188

ìbì    0.991138

Top 30 analogous words or synonyms for ológbìín

Article Example
Eégún Aláràn-án òfí tí ó jẹ́ ìyekan Ológbìín ni ó gbé aṣọ òdòdó tí baba Ológbìín tí ó ti kú ń lò nígbà ayé rẹ̀ bora, tí ó sì tún gbé abàmì ọmọ náà pọ̀n sẹ́hìn, tí ó sì ń jó bọ̀ wá sí àárín ìlú láti inú igbó náà pẹ̀lú ìlù àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lẹ́hìn rẹ̀. Ológbìín ti fi lọ̀ tẹ́lẹ̀ pé òun yóò ṣe ẹ̀yẹ ìkẹhìn fún baba òun tí ó ti kú nítorí náà nígbà tí wọ́n rí Aláràn-án Òrí nínú aṣọ òdòdó, wọ́n ṣe bí Ológbìín tí ó ti kú ni, pàápàá tí abàmì ọmọ tí ó pọ̀n dà bí iké ẹ̀hìn rẹ̀. Àwọn ènìyàn ń sún mọ́ ọn láti wò ó dáadáa ṣùgbọ́n pàṣán tí wọ́n fi ń nà wọ́n kò jẹ́ kí wọn sì wọ ilé baba Ológbìín tí ó ti kú lọ. Bí àwọn ènìyàn ti ń wò ó ni wọ́n wí pé:
Eégún rárá; ó kàn ń fọwọ́ osùn nu ògiri gbígbẹ ni. Èyí ni ó mú kí ọkọ rẹ̀ Ológbìín tọ Ọ̀rúnmìlà lọ. Nígbà tí ó débà tí ó débẹ̀, ó ńi “emi ló dé tí ìyàwó òun fi rọ́mọ lẹ́hìn adìẹ tó bú púrú sẹ́kún?” Ọ̀rúnmìlà sì sọ fún un pé àfi tí ó bá lè ṣe ẹ̀yẹ ìkẹhìn fún baba rẹ̀ tí ó ti kú kí ìyàwó rẹ̀ ó tó lè bímọ.
Eégún Ní àkókò yìí, Ìyá Mòsè ti lọ́ sọ́dọ̀ Amúsan láti lọ ṣe ìwádìí ohun tí ó fa sábàbí. Bí Ìyá Mòsè ti ń bọ̀ láti odò Asà níjọ̀ kan ni elégbèdè kan jáde sí i láti inu igbó tí ó sì bá a lòpọ̀. Bẹ́ẹ̀ ni Ìyá Mosè ṣe bẹ́ẹ̀ lóyún. Mòsè kò sì lè jẹ́wọ̀ bí ó ṣe lóyún fún ọkọ rẹ̀. Ó sì fọ̀n ọ́n ó di ọ̀dọ̀ Ọlọ́pọndà tí ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n Ìyá Mòsè. Níbẹ̀ ni ó ti bí ìjímèrè. Ìtìjú a máa pa gbajúmọ̀. Nígbà tíìtìjú pọ̀ fún Mòsè, ó tún fọn ọ́n, ó di ọ̀dọ̀ ọkọ rẹ̀. Bí ó sì ti ń lọ lọ́nà ni ó ju ìjímèrè sínú igbó. Ṣé ọkọ rẹ̀ kò kúkú mọ nǹ̀̀kan tí ó bí. Nígbà tí ó dijọ̀ keje ni Ato tí ó jẹ́ ìyàwó Ògògó tí ó jẹ́ ọmọ Ìgbórí rí ìjímèrè igbó. Ní àkókò tí a ń wí yìí. Ológbìín ti gbọ́ gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀. Ó ti lọ sí ọ̀dọ̀ Ọ̀rúnmìlà, Ifá sì ti sọ fún un pé sùúrù lẹbọ. Ifá ní kí Ológbìín máa tọ́jú abàmì ọmọ náà, ṣùgbọ́n kí ó tún ṣe ẹ̀yẹ ìkọhìn fún baba rẹ̀ nìpa lílọ sí igbó níbi tí wọ́n ti rí abàmì ọmọ náà láti lọ ya eégún baba rẹ̀. Àwọn ohun tí Ifá pa láṣẹ ètùtù náà ni ẹgbẹ̀rin àkàrà, ẹgbẹ̀rin ẹ̀kọ, ẹgbẹ̀rin pàsán àti ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ẹmu. Igbó tí wọn ti ṣe ètùtù náà ni a mọ̀ sí igbó ìgbàlẹ̀ di òní olónìí.
Eégún Nígbà TÌ Ọ̀wọ́nrín tí ọ́ ń gbé ní Ìsányín dolóògbé, àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta - Arúkú, Arùḱu àti Aròḱu-rọja-má-tà kò ní owó lọ́wọ́ lati fi ṣe òkú bàbáa wọn. Ìrònú ọ̀ràn náà pọ̀ dé bi pé èyí Arúkú tí ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n fún gbogbo wọn fi ìlú sílẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni èyí àtẹ̀lé rẹ̀, Arùkú, mú ìmọ̀ràn wá pé kí àwọn ó ta òkú náà1. Èyí àbúrò wọn, Aròkú-rọja-má-tà, bá kiri òkú náà lọ. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó ti kiri fún ìgbà díẹ̀ tí kò ti rí ẹni ra òkú náà ni ó ti sú u, ó sì wọ́ òkú náà jùnù sínú igbó; ó bá tirẹ̀ lọ. Lẹ́hìn ìgbà díẹ̀, èyí ẹ̀gbọ́n di baálé ilé, ó sì gba ipò bàbá rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ológbìín. Gẹ́gẹ́ bí ipò rẹ̀ òun ni ó sì wá di Ológbo2. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé abuké ni, Aláàfin fún un ní ìyàwó kan, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ìyá Mòsè. Ṣùgbọ́n fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọd́un, Mòsè kò gbọ́ mokòó