Top 10 similar words or synonyms for ojise

marksisti    0.997403

isotopu    0.997339

olokiki    0.996562

alaaye    0.996205

apartheid    0.995725

titobi    0.995680

oludasile    0.995529

aije    0.995249

alawofunfun    0.995190

aaye    0.995102

Top 30 analogous words or synonyms for ojise

Article Example
Ìmàle Olohun (Allah) ti ran awon ojise kan si awon eda Re.
Ìmàle Eni akoko ninu awon ojise naa ni anabi Nuhu nigbati anabi Muhmmad (ki ike ati ola Olohun o ma a baa ati gbogbo awon ojise ti o siwaju re)si je olupinnu won. Gbogbo awon ojise Olohun pata -ti o fi mo anabi Isa- je eda abara ti ko si nkankan ninu jije Olohun ni ara won . Awon paapaa je eru Olohun (Allah) gegebi awon eda yoku naa ti je eru Olohun sugbon ti Adeda won se aponle fun won pelu riran won ni ise mimo si awon eda abara yoku. Ni akotan, Olohun (Allah) ti pari gbogbo ise ti o fe ran si aye pelu ise-imona ti o fi ran anabi Muhammad (ki ike ati ola Olohun o maa baa).O si ti ran an si gbogbo eniyan laiko da enikan si. Nitori naa, ko si anabi kankan mo leyin anabi Muhammad (ki ike ati ola Olohun o maa baa).
Ìmàle Ijeri (igba-tokantokan) pe Olohun (Allah) nikan ni Oba (ti a a josin fun) ati pe ojise Olohun ni anabi Muhammad (ki ike ati ola Olohun o maa baa) i se. Ijeri yii ni kokoro ISLAM ati ipilese re ti gbogbo eka yoku duro le lori.
Ìjẹ́ẹ̀rí Shahada tabi ìjẹ́ẹ̀rí (Arabic: ' ) (lati oro-ise ', "o jeri"), tumo si "lati mo ati gbagbo laisi ifura, bi jijeri"; o je ikan ninu awon opo marun islam. Shahada ni ike igbagbo ninu okan Allahu ta'âlâ ati igba Muhammad gege bi ojise Olorun. Ike yi ni pe:
Ìmàle Olohun (Allah), Oba ti o tobi ti o si gbon-un -gbon julo so awon iwe kale fun awon ojise Re eyi ti ona mimo, rere ati daradara wa ninu re. Awon ti gbedeke re waye ninu awon tira yii ni wonyii:
Margaret Court Margaret Court AO MBE (abiso Margaret Jean Smith, ojoibi 16 July 1942 ni Albury, New South Wales), bakanna bi Margaret Smith Court, je agba tenis ara Australia to ti feyinti ati ojise Kristiani. O gbajumo fun ise ereidaraya re, nigba kan o je agba tenis onipo akoko lagbaye.
Ìmàle Itumo ijeri (ifaramo) pe anabi Muhammad (ki ike ati ola Olohun o maa baa) je ojise Olohun ni gbigba a ni ododo ninu gbogbo ohun ti o fun ni ni labare re, titele e ninu gbogbo oun ti o pa lase ati jijinna si gbogbo ohun ti o ko fun ni lati se ti o si jagbe mo a i fe be e.
Ìmàle Eleyi tumo si pe ki ire Musulumi maa sin Olohun re pelu igbagbo ati esin ododo gegebi eni-wipe o n wo Olohun Adeda lojukoroju bayi ni, biotileje pe ire kori I dajudaju Oun n ri o. Bakanaa, ki o rii daju wipe oun se ohun kohun ni ibamu pelu ilana (Sunnah) ojise e Re; annabi Muhammad (ki ike ati ola Olohun ki o baa).
Gregor Mendel Gregor Johann Mendel (July 20, 1822 – January 6, 1884) je ojise olorun ati onimosayensi ara Austria, to gbajumo leyin iku re gege eni pataki ninu sayensi tuntun genetics nitori agbeka ijogun iru maruloawon iwa kan pato ninu ogbin ewa popondo. Mendel fihan pe ijogun awon iwa wonyi untele awon ofin kan pato, ti won gba oruko re lojowaju. Bi ise Mendel yi se se pataki to ko je didamo ki o to di ibere orundun 20k. Itunwari alominira awon ofin wonyi ni won se ifilole sayensi odeoni ton unje genetiki.
Ìmàle Awon molaaika ni awon eru Olohun kan ti won je eni aponle gegebi won ti je eda Olohun (Allah). Bakannaa, won je oluse ibaada (ijosin) fun Olohun de oju ami won si tun je atele ase re ni perepere. Olohun (Allah) fi awon ise (ojuse) orisirisii fun okookan won. Ninu won ni Jibiriilu eni ti a se afiti ise mimo ti o ba n waye lati odo Olohun (Allah) si odo eni ti O ba fe ninu awon anabi Re ati awon ojise Re ti si. Ara won si tun ni Miikailu eni ti o wa fun alaamori riro ojo ati awon koriko ti n hu. Bee naa ni ara won ni Isiraafiilu eni ti o wa fun fifon fere ni asiko ti Olohun (Allah) ba fe ki gbogbo eda o sun oorun asun- fonfon- n-tefon ti yoo kase ile aye nile ati nigba ti o ba tun fe ki won dide (lati jabo nipa igbesi aye won). Ara won si tun ni molaaika iku eni ti ojuse re je gbigba awon emi ni asiko ti Olohun (Allah) ba ti ni asiko re to.