Top 10 similar words or synonyms for ntan

abojuto    0.996679

tori    0.994779

eniti    0.994550

anafilasisi    0.993899

riru    0.993829

itọju    0.993760

gidigidi    0.993406

niiṣe    0.993315

kúrùpù    0.993010

ese    0.992885

Top 30 analogous words or synonyms for ntan

Article Example
Ìrànwọ́:Báwo lẹṣe le ṣe àtúnṣe ojúewé 977. Eemeta l’omode ntan ‘na ale.
Ìrànwọ́:Báwo lẹṣe le ṣe àtúnṣe ojúewé 864. Eni ara re ba wu, l’o ntan na ale.
Ìrànwọ́:Báwo lẹṣe le ṣe àtúnṣe ojúewé 1445.Lani – ntan kan ko ni ‘ru esin.
Ìrànwọ́:Báwo lẹṣe le ṣe àtúnṣe ojúewé 161. A f’ase gbe ‘jo, o ntan ‘ra re je.
Ìrànwọ́:Báwo lẹṣe le ṣe àtúnṣe ojúewé 1757.O ntan lo niyen, baba t’o nfe ‘binrin omo re.
Leishmaniasis Leishmaniasis tabi leishmaniasis je àrùn kan ti protosan o si ntan kaakiri ni ni kété ti awon kòkòrò kan ba bu ni jẹ. kòkòrò. Kòkòrò na le farahàn lọna mẹta pataki gegebi: kútẹnọs, mukokútẹnọs,tabi fisera lẹṣmaniasisi. Kotẹnọs na ma a nwa pelu ogbe awo-ara,nigbati mukokutẹnọs ma a nwa pelu ọgbẹ awo-ara, enu, ati imu, ati wipe fisera ma a nbẹrẹ pelu ọgbẹ awọ-ara, nigba to ba ya ibà, awon sẹẹli ẹjẹ pupa diẹ, ọlọ inu ati ẹdọ to tobi.
Streptococcal pharyngitis Awọn kokoro to nfa arun(tabi bakiteria)ti a npe ni ẹgbẹ streptokokus ti bita A (A beta-hemolytic streptococcus) (GAS)lo nse okunfa ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa. Awọn kokoro miiran to nfa arun tun le fa ọna-ọfun ti o ndun ni. Ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa maa ntan nipasẹ ifarakora pẹkipẹki ni taara pẹlu alaisan kan. Ợpọ̀ eniyan, bii awọn ti o wa ni ọmọ-ogun tabi awọn ile-iwe maa mu bi aisan naa ti ntan kaakiri lati pọ sii. Awọn kokoro to nfa arun ti a ko le f’oju ri ti wọn ti gbẹ tan ti a si ri ninu erupẹ ko le sọ eniyan di aláàárẹ̀. Awọn kokoro to nfa arun ti ko tii gbẹ, bii eyiti a ri lori pako-oyinbo (burọṣi), le jẹ ki eniyan ṣe àárẹ̀fun bi ọjọ mẹẹdoogun (15 days). Ko wọpọ ki awọn kokoro to nfa arun ti a ko f’oju ri yii lati gbe ninu ounjẹ ki wọn si mu awọn ti wọn jẹ ounjẹ naa ṣe àárẹ̀. Ida mejila ninu ọgọrun awọn ọmọde ti ko ni awọn aami aisan kan fun ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa ngbe GAS awọn kokoro ti o nfa arun kaakiri ninu ọfun wọn.
Anafilasisi Oró lati ara awọn kokoro ti nt’ani tabi j’ẹni bii [[Hymenoptera]] (oyin ati agbọn) tabi [[Triatominae]] (kissing bugs) le fa anafilasisi ninu awọn eniyan ti wọn ni ailera sii. Awọn [[Aiṣan_to ntan kaa kiri gbogbo ara|Ṣiṣẹ iṣẹ lodi to tan kaa kiri gbogbo ara], eyiti o jẹ ohunkohun ti o ju bi ara ṣe ṣe ni ayika ibi ti kokoro ti t’ani lọ, eyiti o le jẹ ewu okunfa fun anafilasisi ọjọ iwaju; ẹwẹ, idaji eyiti o ja si iku ko ni bi ara ṣe nṣe lodi ti o tan kaa kiri ara tẹle.
Àtọ̀sí ajá Àrùn yìí maa ntan nipa nini ifarakan omi ti o ni awọn kokoro ti o nfa àrùn ninu. Awọn kokoro ti o nfa àrùn ni a maa jọwọ lati ìgbín omi ti o ti ni ikọlu. Àrùn yìí wọpọ laarin awọn ọmọde ni awọn orilẹ-ede ti o ṣẹṣẹ ndagbasoke nitori ti o ṣee ṣe lati ṣere ninu omi ti o ti ni àrùn. Awọn ẹgbẹ miiran ti o wa ninu ewu ti o ga ni awọn agbẹ, awọn apẹja, ati awọn ti o nlo omi ti o ti ni àrùn fun iṣẹ oòjọ́ wọn. Ohun wa ninu ẹgbẹ awọn ikọlu aràn. Ayẹwo nwaye nipa riri awọn ẹyin kokoro àrùn naa ninu itọ eniyan tabi ninu igbẹ. A tun le jẹrisii nipa rírí antibodies lodi si àrùn naa ninu ẹ̀jẹ̀.
Streptococcal pharyngitis Ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa maa ntan nipasẹ ifarakora pẹkipẹki pẹlu alaisan kan. Lati rii daju wipe eniyan kan ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa eyiti o ndun ni, ayẹwo kan ti a npe ni mimu awọn nkan ẹlẹmi dagba lori nkan amu nkan ẹlẹmi dagba l’ode ara lati inu ọna-ọfun (throat culture)fun iwadi ṣe pataki. Lai ṣe ayẹwo yii papa ẹwẹ, a le mọ nipa ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan nfa nipasẹ awọn aami aisan. Ni eyiti o jọ bẹẹ tabi ti a mọ daju, awọn apakokoro(antibiotics)(awọn oogun ti o npa bakiteria) le dẹkun aisan naa lati ma l’ewu gan-an ati lati mu ara pada bọ s’ipo ni kiakia.