Top 10 similar words or synonyms for niiṣe

anafilasisi    0.998221

abojuto    0.997098

ṣugbọn    0.995753

idi    0.995430

itọju    0.994723

elektronu    0.994250

abo    0.993744

ipele    0.993616

wahala    0.993457

ntan    0.993315

Top 30 analogous words or synonyms for niiṣe

Article Example
Kúrùpù Kúrùpù ti o niiṣe pẹlu bakiteria ṣee pin si laryngeal diphtheria, bacterial tracheitis, laryngotracheobronchitis, ati laringotrakiobronkopneumonitisi. Laringeal diphtheria maa nwaye nitori "Corynebacterium diphtheriae" nigbati bakiteria trakitisi, laringotrackiobronkaitisi, ati laringotrakobronkopneumonitisi maa nwaye nitori fairọsi, pẹlu bakiteria ti o lọwọ sii. Awọn bakiteria ti o wọpọ julọ ni"Staphylococcus aureus", "Streptococcus pneumoniae", "Hemophilus influenzae", ati "Moraxella catarrhalis".
Anafilasisi Eto ti ko niiṣe pẹlu ajẹsara ni ninu awọn nkan ti o nfa ni taara [[bi sẹẹli ṣe njọwọ granuli]] fun awọn sẹẹli masiti ati basofili. Eyi ni ninu awọn nkan bii [[nkan ti a fi nwo bi nkan ṣe ri ninu ara]], [[opioids]], iwọn gbigbona tabi tutu (gbigbona tabi tutu), ati gbigbọn.
Anafilasisi Anafilasisi jẹ [[bi ara ṣe nṣe si nkan ti ara korira]] ti o nira gan-an ti o le ṣe okunfa oniruru idena fun [[eto bi ara ṣe nṣiṣe]]. Eyi dale lori jijọwọ [[awọn olulaja to nfa aiṣe deede]] ati [[saitokinisi]] lati ara awọn sẹẹli masiti ati awọn [[basofili]], ti dale lori [[Eto ajẹsara ara| bi ara ṣe nṣiṣe ajẹsara]] ṣugbọn nigbamii lori awọn eto ti ko niiṣe pẹlu ajẹsara ara.
Anafilasisi Awọn aami aiṣan ninu ifun le ni pajapaja ninu [[inu rirun]], igbẹ-ọrin, ati eebi bίbὶ. Idamu le wa, ipadanu akoso apo-ὶtợ tabi irora egungun ibadi ti o jọ ti pajapaja [[ile-ọmọ|niiṣe pẹlu ile-ọmọ]]. Lilanu silẹ ọpa ti o ngbe ẹjẹ ni ayika ọpọlọ le fa [[ẹfọri]]. Imọlara [[iporuru ọkan]] tabi "ewu kan ti o nbo wa" ni a ti ṣe apejuwe rẹ ri.
Anafilasisi Oriṣi anafilasisi mẹta lo wa. Ayajija ti o niiṣe pẹlu anafilasisi ni asopọ pẹlu [[fifẹ awọn ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara]]ti o tan kaa kiri gbogbo ara ti o nfa [[riru ẹjẹ ti o lọ silẹ |riru ẹjẹ ti o lọ silẹ]] eyiti o fi 30% lo silẹ ju ila ti o kere julọ tabi iwọn odiwọn itumọ lọ.Anafilasisi ti baifasiki jẹ fifi ara han pada awọn aami aiṣan laarin wakati 1–72 laisi ifarako nkan ti ara korira siwaju. Agbejade iṣẹlẹ yatọ si ara wọn, ti awọn ẹkọ kan njẹwọ irufẹ iṣẹlẹ ti o pọ to 20%. Fifi ara han pada yii maa nsaba waye laarin wakati 8. A maa nṣe abojuto rẹ ni ọna kanna pẹlu anafilasisi. Anafilasisi ti kii ṣe e tootọ tabi abajade anafilasisi ti ko mu awọn aami aiṣan lọwọ jẹ oriṣi anafilasisi ti ko ni awọn abajade nkan ti ara korira ṣugbọn ti o wa ni taara lati ọwọ [[bi sẹẹli ṣe njọwọ granuli]] awọn sẹẹli masiti.Anafilasisi ti ko niiṣe pẹlu ajẹsara jẹ ọrọ ti [[World Allergy Organization]] nlo lọwọlọwọ pẹlu imọran pe ki a ma lo awọn ọrọ atijọ mọ.
Anafilasisi [[Ṣiṣayẹwo nkan ti ara korira]] le ṣe iranlọwọ nipa mimọ ohun ti o nfaa. [[Ṣiṣayẹwo nkan ti awọ-ara korira]] (fun apẹẹrẹ [[Patch test (medicine)|patch testing]]) wa fun awọn ounjẹ kan ati oró. Ṣiṣayẹwo ẹjẹ fun IgE ni pato le wulo lati jẹrisi wara-olomi, ẹyin, ẹpa, ẹpa igi ati awọn nkan ti ara korira ninu ẹja. Ṣiṣayẹwo awọ-ara wa lati jẹrisi awọn nkan ti ara korira bii [[pẹnisilini]] ṣugbọn ko si fun awọn itọju miiran. Iru anafilasisi ti ko niiṣe pẹlu ajẹsara ṣee mọ nipa itan ati ikọlu si nkan ti ara korira nikan, ti kii si ṣe nipa ayẹwo awọ-ara ati ayẹwo ẹjẹ.
Oyún ṣíṣẹ́ Oyún ṣíṣẹ́ ni ìtàn eyiti o pé ìtàn. A ti ṣe e nipasẹ oriṣiriṣi ọna, ti o ni ninu awọn egbòògi, lilo ohun-elo ti o mú, ibanilọkanjẹ ti a le f’ojuri, ati awọn miiran awọn ọna ibilẹ́ lati igba lailai. Awọn awọn ofin ti o rọ̀mọ́ oyún ṣíṣẹ́, ni bi o ti ṣe wọ́pọ̀ lati ṣe e tó, ati awọn ipo àṣà ati ti ẹ̀sìn yàtọ̀ si ara wọn gan-an kaakiri agbaye. Ni abẹ awọn iṣẹlẹ kan ni pàtó, oyún ṣíṣẹ́ tọ̀nà labẹ ofin, bíi ibalopọ laarin mọlẹbi, ifipabanilopọ, awọn iṣoro kan pẹlu oyún-inu, awọn nnkan ti o niiṣe pẹlu ọrọ-ajé tabi ewu nipa ilera iya. Ni ọpọlọpọ ibi l’agbaye ariyanjiyan nwa awuyewuye l’awujọ lori bi o ṣe tọ́ sí, ṣíṣẹ̀tọ́, ati awọn ọrọ labẹ ofin lori oyún ṣíṣẹ́. Awọn ti o lodi si oyún ṣíṣẹ́ maa nsọ wipe ọmọ-inu tabi oyún-inu jẹ eniyan ti o si ni ẹ̀tọ́ si ìyè ti wọn si nfi oyún ṣíṣẹ́ wé ìpànìyàn. Awọn ti o faramọ awọn ẹ̀tọ́ oyún ṣíṣẹ́ ntẹnumọ ẹ̀tọ́ obinrin lati pinnu ohun ti o niiṣe pẹlu ra rẹ̀ ti wọn si tun ntẹnumọ awọn ẹ̀tọ́ gẹgẹ bi eniyan l’apapọ.
Anafilasisi Anafilasisi le waye ni esi si eyikeyi ohun ajeji. Ohun ti o le faa ti o wọpọ ni ninu [[oró]]lati [[jijẹni ati titani kokoro|jijẹni ati titani kokoro]], awọn ounjẹ, ati [[ogun lilo]]. Ounjẹ ni o wọpọ julọ ti o ma nfaa ninu awọn ọmọde ati ọdọ ṣugbọn ogun lilo ati jijẹni ati titani kokoro ni o wọpọ julọ laarin awọn agbalagba. Awọn okunfa ti ko wọpọ nί ninu: awọn nkan ti eniyan le f’ojuri, nkan ti o niiṣe pẹlu nkan ẹlẹmi bii [[àtọ̀]], oje, ayipada ti o niiṣe pẹlu homoni, awọn afikun ounjẹ bii iyọ oyinbo lati inu ireke ati àwợ ounjẹ (food colors), ati awọn ogun lilo kan.Awọn nkan ti a le f’ojuri bii ṣiṣe idaraya (eyiti a mọ si anafilasisi ti idaraya ṣe okunfa rẹ) tabi iwọn gbigbona tabi titutu (yala gbigbona tabi titutu) le tun ṣe okunfa nipa ipa wọn ni taara lori [[sẹẹli masiti]]. Awọn nkan ti idaraya ṣe okunfa maa nni asopọ pẹlu jijẹ awọn ounjẹ kan. Nigba [[kikunni loorun fun iṣẹ abẹ]], [[neuromuscular blocking agents]], oogun aporo, ati [[oje]] lo wọpọ julọ ti o nfaa. Ninu 32-50% awọn iṣẹlẹ, ohun ti o ṣe okunfa jẹ eyiti a ko mọ idi rẹ, eyiti a npe ni "anafilasisi ti idiopatiki".
Anafilasisi Awọn eniyan ti o le tete ni anafilasisi ni agba ni imọran lati ni "eto iṣẹ fun nkan ti ara korira si", awọn obi ni agba ni imọran lati fi to awọn ile-iwe awọn ọmọ wọn leti nipa ikọrira ara ati awọn nkan ti o ye ki wọn ṣe bi pajawiri anafilatiki ba ṣẹlẹ. Eto iṣẹ maa nni ninu lilo [[fifun ara ẹni ni abẹrẹ efinifirini]], igbani niyanju lati wọ [[ẹ̀gbà-ọwọ́ itaniji to niiṣe pẹlu iṣegun oyinbo]] kan, ati imọran lati yẹra fun awọn ohun ti o nṣe okunfa. [[Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni lati ṣe bojuto Nkan ti ara korira| Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni]] wa fun awọn ohun ti o nṣe okunfa lati dena anafilasisi ọjọ iwaju. Ẹkọ onilọpọ ọdun nipa didinku tabi mimu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan ninu ọra ni ati ri wipe o munadoko lodi si awọn kokoro ti njẹ ni nigbati dinku tabi mimu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan lati ẹnu munadoko fun ọpọlọpọ ounjẹ.