Top 10 similar words or synonyms for núkléù

aláìjẹ    0.989666

tábìlì    0.989474

saworoide    0.988004

ìbátan    0.986095

ìpìlẹ    0.984547

nama    0.984337

fúùfù    0.983354

pàràkòyí    0.983160

ayára    0.982828

àtí    0.982146

Top 30 analogous words or synonyms for núkléù

Article Example
Núkléù átọ̀mù Núkléù ni ibi kiki to ni protoni ati neutroni ni arin atomu. O je wiwari ni 1911, nipase itumo ti Ernest Rutherford fun idanwo Rutherford 1909 ti Hans Geiger ati Ernest Marsden se, labe idari Rutherford. Afiwera protoni–neutroni fun nukleu je aba Dmitry Ivanenko ni 1932. Kìkì gbogbo ìkórajọ atomu lo wa ni inu nukleu ayafi die elektroni ayipo.
Ísótòpù Àwọn ísótòpù tabi áísótòpù ni àwọn àyàsórísirísi ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà pàtó kan. Bótilẹ̀jẹ́pé gbogbo àwọn ísótòpù ẹ́límẹ̀ntì kan ní iye prótọ̀nù kannáà, ísótòpù kọ̀ọ̀kan yàtọ̀ sí àwọn yìókù ní iye neutrons tó ní. Orúkọ ìsótòpù jẹ́ dídá láti èdè Gríìkì isos (ἴσος "dọ́gba") àti topos (τόπος "ibi"). Nítoríẹ̀: "ibi kannáà," túmọ̀sí pé àwọn Ísótòpù orísirísi ẹ́límẹ̀ntì kan wà ní orí àyè kannáà lórí tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì. Iye àwọn prótọ̀nù nínú núkléù átọ̀mù ni óún ṣèyàtọ̀ àwọn ẹ́límẹ̀ntì sí ra wọn, sùgbọ́n ẹ́límẹ̀ntì kan le ní iye neutron èyíkéyìí. Iye àwọn núkléónì (protons ati neutrons) nínú núkléù ni nọ́mbà àkọ́jọ, and each isotope of a given element has a different mass number.
Ìsopọ̀ kẹ́míkà Ìsopọ̀ kẹ́míkà ni ìfàmọ́ra láàrin àwọn átọ̀mù tó gba ààyè ìdá àwọn kẹ́míkà tí wọ́n ní átọ̀mù méjì tàbí mẹ́ta. Ìsopọ̀ náà sẹlẹ̀ nítorí agbára ẹlẹktrostátìkì ìfàmọ́ra láàrin àwọn àgbéru olódì, bóyá láàrin àwọn ẹ̀lẹ́ktrọ̀nù àti núkléù, tàbí gẹ́gẹ́bí ìdá ìfàmọ́ra ipoméjì. Agbára àwọn ìsopọ̀ kẹ́míkà jẹ́ orísirísi; àwọn "ìsopọ̀ líle" bíi àjọfagbáradìmú tábí íónì wà àti àwọn "ìsopọ̀ dídẹ̀" bíi ìbáṣepọ̀ ipoméjì sí ipoméjì, agbara ìfọ́nká London àti ìsopọ̀ háídrójìn.