Top 10 similar words or synonyms for nàìjíríà

ilẹ    0.965744

apáìwọ    0.956038

ààrẹ    0.952004

kóngò    0.945714

ède    0.944718

gúúsù    0.942655

túrkì    0.941180

yorùbá    0.938160

áfríkà    0.929295

tótóbijùlọ    0.927805

Top 30 analogous words or synonyms for nàìjíríà

Article Example
Nàìjíríà Awon Yoruba se ojo ti won ti wa ni agbegbe Naijiria, Benin ati Togo ayeodeoni seyin de bi odun 8500 kJ. Awon ilu-oba Ife ati Oyo ni apa iwoorun Naijiria gbale ni 700-900 ati 1400 nitelera won. Sibesibe, itan ariso Yoruba gbagbo pe Ile-Ife ni orisun eda eniyan pe be si ni o siwaju asa-olaju miran. Ife seso ere alamo ati onitanganran, Ilu-oba Oyo si fe de ibi ti Togo wa loni. Ilu-oba miran to tun gbale ni guusu apaiwoorun Naijiria ni Ilu-oba Benin lati orundun 15ru ati 19sa. Ijoba won de Ilu Eko ki awon ara Portugal o to wa so ibe di "Lagos."
Nàìjíríà Ni 1885 igbesele Iwoorun Afrika latowo awon ara Britani gba idamo kariaye, nigba to si di odun to tele ile-ise Royal Niger Company je hihaya labe ayeolori Sir George Taubman Goldie. Ni 1900 awon ile ti ile-ise yi ni di ti ijoba Britani. Ni January 1, 1901 Naijiria di ile alaabo ti Britani, ikan ninu Ile-oba Britani to je alagbara julo nigba na.
Nàìjíríà Ni 1814, agbegbe na je sisodokan gege bi Imusin ati alaabo ile Naijiria ("Colony and Protectorate of Nigeria"). Fun amojuto, Naijiria je pinpin si igberiko apaariwa ati apaguusu ati imusin Eko. Eko Iwoorun ati okowo ayeodeoni tesiwaju ni kikankikan ni guusu ju ni ariwa lo, ipa eyi n han ninu aye oloselu Naijiria de oni. Ni odun 1936 ni oko eru sese di fifofin lu.
Nàìjíríà Bakanna Naijiria tun ni opolopo alumoni aintimulo bi efuufu aladanida, edu, bauxite, tantalite, wura, tanganran, irin inule, okutadidan, niobiomu, oje, ati sinki. Botilejepe awon alumoni inule wonyi po daada, awon ile-ise akoalumoni ti yio mu won jade ko si.
Nàìjíríà Ise-agbe je eyi to n mu owo okere wole fun Naijiria teletele. Nigbakan, Naijiria lo n ta epa, koko ati epo ope to pojulo si oke okun ati olupese pataki agbon, eso osan, agbado, oka baba, ege, isu ati ireke. Bi 60% awon ara Naijiria ni won sise ninu ise-agbe, be sini ile to se dako si sugbon ti won ko je be po gidi.
Nàìjíríà Naijiria ni orile-ede ti awon eniyan posijulo ni Afrika botilejepe iye gangan ko i je mimo. Agbajo Sisokan awon Orile-ede diye pe iye awon eniyan ni 2009 je 154,729,000, ti 51.7% inu won gbe loko ati 48.3% n gbe ni ilu ati iye eniyan 167.5 ni agbegbe ilopomeji kilomita kan.
Nàìjíríà Ni apa ariwa, Kano ati Katsina ni itan akosile ti ojo won deyin to bi odun 999 kJ. Awon ilu-oba Hausa ati Ile-oba Kanem-Bornu gbooro gege bi ibudo aje larin Ariwa ati Iwoorun Afrika. Ni ibere orundun 19sa labe Usman dan Fodio awon ara Fulani di awon olori Ile-oba Fulani lojukan eyi to duro bayi titi di 1903 nigbati awon je pinpin larin awon olumusin ara Europe. Larin 1750 ati 1900, ida kan si ida meji ninu meta awon onibugbe awon ilu Fulani je eru nitori ogun.
Nàìjíríà Aidogba yi ati ibaje eto idiboyan ati oloselu fa ni 1966 de awon ifipagbajoba ologun lera lera. Akoko sele ni January ti awon odo oloselu alapaosi labe Major Emmanuel Ifeajuna ati Chukwuma Kaduna Nzeogwu. O ku die ko yori si rere - awon olufipagbajoba pa Alakoso Agba, Sir Abubakar Tafawa Balewa, Asolori Agbegbe Apaariwa Naijiria, Sir Ahmadu Bello, ati Asolori Agbegbe Apaiwoorun ile Naijiria, Sir Ladoke Akintola. Botileje bayi, sibesibe awon olufipagbajoba na ko le gbe ijoba kale nitori isoro bi won yio ti se, nitori eyi Nwafor Orizu, adelede Aare je mimu dandan lati gbe ijoba fun Ile-ise Ologun Adigun Naijiria labe Apase Ogagun JTY Aguyi-Ironsi.
Nàìjíríà Lopolopo igba Ile-ise Ologun Naijiria ti ko ipa ninu igbero alafia ni Afrika. Ile-ise Ologun Naijiria gege bi ikan ninu ECOMOG ti ko ipa gege bi olugbero alafia ni Liberia ni 1990, Sierra Leone ni 1995, Ivory Coast ati Sudan.
Nàìjíríà Bakanna, Naijiria je gbongan pataki fun orisirisielemin pataki. Agbegbe to ni awon orisirisi labalaba julo laye ni agbegbe Calabar ni Ipinle Cross River. Awon obo agbele wa ni igbe ni Guusuilaorun Naijiria ati Kameroon nikan.