Top 10 similar words or synonyms for marksisti

titobi    0.997680

apartheid    0.997616

ojise    0.997403

adebayo    0.996751

olokiki    0.996690

alawujo    0.996511

isotopu    0.996063

eseese    0.995429

koni    0.995061

jeometri    0.994997

Top 30 analogous words or synonyms for marksisti

Article Example
Àròjinlẹ̀ aláyẹ̀wò Ninu lilo oloro-awujo, irojinle alagbewo untoka si iru irojinle Marksisti pelu agbara lati koju awon ipa alaise Marksisti (fun apere iwe Friedrich Nietzsche ati Sigmund Freud). Agbara yi ni awon asemarksisti gbamugbamu unpe bi abuku ni 'iseatunyewo'. Irojinle alagbewo odeoni dide lati inu eka to ta wa lati inu oro-awujo alaiseonididaloju ti Max Weber ati Georg Simmel, irojinle Marksisti tonituntun ti Georg Lukács ati Antonio Gramsci, titi de ti awon to sepo mo Ibi-Eko Iwadi Awujo Frankfurt.
Leon Trotsky Leon Trotsky (Russian: , ("Lev Davidovich Trotsky", also transliterated "Lyev", "Trotski", "Trotskij", "Trockij" and "Trotzky") – 21 August 1940), oruko abiso Lev Davidovich Bronstein (), je ajidide Bolshefiki ati elero Marksisti.
Rosa Luxemburg Rosa Luxemburg (Rosalia Luxemburg, ; 5 March 1871 15 January 1919) je oludero Marksisti, onimoye, onimo okowo ati alakitiyan omo Ju Polandi to di ara Jemani. Ni telentele o di omo egbe Social Democracy of the Kingdom of Poland and Lithuania, SPD Jemani, Independent Social Democratic Party ati Egbe Komunisti ile Jemani.
Che Guevara Ernesto "Che" Guevara (; June 14, 1928 – October 9, 1967), to gbajumo bi El Che tabi lasan bi Che, je omo ile Argentina to je olujidide Marksisti, oniwosan, oludako, omowe, olori guerrilla, diplomati, oludero ologun, ati eni pataki Ijidide Kuba. Lati igba to to ailaisi, aworan re ti di ami=idamo olodiasa kakiri ati ami eye lagbaye larin asa agbajumo.
C. L. R. James Cyril Lionel Robert James (4 January 1901 – 19 May 1989) to tun gba oruko ikowe J.R. Johnson je omo Afrika-Trinidad akoitan, oniroyin, elero sosialisti ati alaroko. O ko ipa pataki ni Britani ati Amerika ninu awon egbe sosialisti ati ironu Marksisti, bakanna ati lori ero to le mu opin iseamusin wa. O si tun kowe nipa kriketi.
Àròjinlẹ̀ aláyẹ̀wò Pelu awon aserojinle ibi ti aun pe ni '"Ile-Eko Frankfurt" ni oro yi unsaba toka si: Herbert Marcuse, Theodor Adorno, Max Horkheimer, Walter Benjamin, ati Jürgen Habermas. Latowo eni to gbeyin yi ni irojinle oniagbewo ti tun jinna si ibere to ni ninu iseboseye Jemani to si bo sunmo iseoloungidi ara Amerika. Fife wa idi onirojinle fun "opo titobi" asa to wa lati "ipile" eleroja nikan ni igbagbo Marksisti toseku ninu irojinle alagbewo igbalode.
Antonio Gramsci Antonio Gramsci () (January 22, 1891 – April 27, 1937) je was an amoye ara Itali, olukowe, oloselu ati oniro oloselu. O je ikan ninu awon oludasile ati olori Egbe Komunisti ile Itali,o je jiju si ogba ewa latowo ijoba Fasisti Benito Mussolini. Awon iwe kiko re da le lori ituyewo asa ati isolori oloselu. O se pataki gege bi aronu ogidi ninu asa Marksisti. O gbajumo fun ajotunmo hegemoni asa gege bi ona ti orileijoba ninu awujo kapitalisti, be na sini won gba bi akopa koko ninu imoye.