Top 10 similar words or synonyms for málì

amòye    0.989273

nsì    0.986406

sístẹ    0.980274

fránsì    0.980163

àkójọ    0.979520

ntì    0.979303

abùjá    0.978353

límẹ    0.977744

nìs    0.976376

bùn    0.975712

Top 30 analogous words or synonyms for málì

Article Example
Málì Mali, fun tonibise bi Olominira ile Mali (), je orile-ede tileyika ni Apaiwoorun Afrika. Mali ni bode mo Algeria ni ariwa, Nijer ni ilaorun, Burkina Faso ati Côte d'Ivoire ni guusu, Guinea ni guusu-iwoorun, ati Senegal ati Mauritania ni iwoorun. Itobi re fi die ju 1,240,000 km² lo pelu iye awon eniyan to ju egbegberun 14 lo. Oluilu re wa ni Bamako.
Málì Mali ni agbegbe mejo be sini awon bode re ni ariwa sun de arin Sahara, nigbati agbegbe apaguusu, nibi ti opolopo eniyan ngbe, ni awon odo Niger ati Sénégal. Ise agbe ati ise apeja ni won se ju nibe. Awon ohun alumoni Mali ni wura, uraniomu, ati iyo. Mali je ikan ninu awon orile-ede to je talaka julo mi agbaye.
Málì Present-day Mali oni fi igba kan wa ni apa awon ile obaluaye meta ti Iwoorun Afrika to n dari idunadura kiri Sahara: Ile Obaluaye Ghana, ile Obaluaye Mali (nibiti orile-ede Mali ti gba oruko re), ati Ile Obaluaye Songhai. Ni opin awon odun 1800, Mali bo sowo awon ara Fransi, o di apa Sudan Fransi. Mali gba ilominira ni 1959 lapapo mo Senegal, gege bi Ile Apapo Mali. Leyin odun kan, Ile Apapo Mali di orile-ede alominira ile Mali. Leyin igba pipe ijoba egbe oloselu-kan, ifipagbajoba ni 1991 mu ilana-ibagbepo titun jade ati idasile Mali gege bi orile-ede toseluaralu egbe oloselu-pupo.
Jẹ́ọ́gráfì ilẹ̀ Málì Geography of Mali
Ìṣèlú ilẹ̀ Málì Ìṣèlú ilẹ̀ Málì je ti orile-ede Málì