Top 10 similar words or synonyms for lincoln

ìpolówó    0.980078

kuti    0.979564

gbádò    0.973036

tropidurus    0.971075

ilê    0.970647

itọ    0.969719

túndé    0.968647

ńtúrì    0.968387

fáwẹ    0.967590

oríṣìí    0.967526

Top 30 analogous words or synonyms for lincoln

Article Example
Abraham Lincoln Abraham Lincoln (/ˈeɪbrəhæm ˈlɪŋkən/; Ọjọ́ kejìlá Oṣù kejì Ọdún 1809 – Ọjọ́ karùndínlógún Oṣù kẹrin Ọdún1865) jẹ́ ààrẹ United States kẹrìndínlógún, tí ó ṣèjọba láti Oṣù kẹta Ọdún 1861 dí Oṣù kẹrin Ọdún 1865 tí wọ́n ṣekú paá. Lincoln jẹ́ olórí orílẹ̀ èdè United States nígbà ogún abẹ́lé ìlú náà
3153 Lincoln 3153 Lincoln jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì.
Abraham Lincoln Wọ́n bíi ní Hodgenville, Kentucky, Lincoln dàgbà sí ìwọ oòrùn frontier ní  Kentucky àti Indiana. Ókpọ ara rẹ̀ ní ìwé, ó di agbẹ́jọ́ro ní Illinois, Olórí Ẹgbẹ́ Òṣèlú Whig àti ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti lllinois ní ibi tí ó ti lo ọdún méjìlá. Wọ́n yàn sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti United States ní Ọdún1846, Lincoln mú ìlọsíwájú ba okòwo látàrí ilé-ìfowópamọ́, owó orí ìṣòwò lókèèrè àti ojú irin.
Abraham Lincoln —Ogun ìtàjẹ̀sílẹ̀ tí ó pọ̀ tí ó jẹ́ tí ìtẹríba, òfin àti rògbòdìyàn òṣèlú. Ní ogun jíjà yìí ó dá ìṣọ̀kan sí , ó fi òpin sí òwò ẹrú, fún ìjọba lágbára, ó sì jẹ́ kí ìlọsíwájú bá okòwò ìlú.
Ìṣekúpa Abraham Lincoln Lincoln jẹ́ ààrẹ Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ tí àwọn agbanipa máa pa. Ìgbìyanjú àkọ́kọ́ ti ṣẹlẹ̀ lórí Andrew Jackson ní bíi ọgbọ̀n ọdún sẹ́yìn kí wọ́n tó pa Lincoln ní ọdún 1835, tí Lincoln fúnra rẹ̀ sí jẹ́ sábàbí ìpànìyàn tó jásí pàbó nígba tí apànìyàn kan tí a kò mọ̀ fẹ́ paá ní Oṣù kẹjọ Ọdún 1864. Ìṣekúpa Lincoln jẹ́ oun tí wọ́n gbèrò tí ó sì jẹ́ wípé ògbónta òṣèré orí ìtagé, John Wilkes Booth, ti gbogbo ènìyàn mọ̀ bí ẹní mọwó ni ó ṣe iṣẹ́ láabi yìí, tí ó jẹ́ ìpàdí ààpò pọ̀ pẹ̀lú àwọn kan fún ìdí ìṣọ̀kan.
Ìṣekúpa Abraham Lincoln Àwọn ẹlẹgbẹ́ Booth tí wọ́n di rìkíṣí yìí ní Lewis Powell àti David Herold, tí wọ́n yàn lati pa akọ̀wé ìlú William H. Seward àti George Atzerodt tí wọ́n fún ní iṣẹ́ lati pa Igbákejì ààrẹ Andrew Johnson. Bákan náà, kí wọ́n pa àwọn olórí mẹ́ta nínú ìjọba, Booth àti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ ní ìrètí lati dojú ìjà kọ ìjọba Àwọn Ìpínlẹ̀ Àṣọ̀kan Àmẹ́ríkà. Wọ́n yin Lincoln nígbọn nígbà tí ó ń wo eré ìtàgé "Our American Cousin" pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀  Mary Todd Lincoln ní ilé ìṣeré orí ìtàgé Ford ní Washington, D.C.. Ó kú ní agogo méje lé ìṣẹ́jú méjìdínlógún àárọ̀. Ìgbìyànjú àwọn oní rìkíṣí tó kù jásí pàbó; Powell kàn ṣe Seward léṣe,  Atzerodt tí ó fẹ́ pa Johnson sì ferége.  Ètò ìsìnkú àti ìsìnkú Abraham Lincoln jẹ́ àkókò ọ̀fọ̀ fún gbogbo ìlú.
Ìṣekúpa Abraham Lincoln Ní bíì ìparí ọdún 1860, Booth tí darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òkùnkùn Knights of the Golden Circle ní ìlú Baltimore.
Ìṣekúpa Abraham Lincoln Ní Oṣù kẹta Ọdún 1864, Ulysses S. Grant, tí ó jẹ́ balógún fún ìṣọ̀kan àwọn olọgun ṣetán lati fòpin sí pàṣípààrọ̀ àwọn tí wọ́n mú lójú ogun. Bí ó ti lẹ̀wù kí ó burú tó, àwọn ẹlẹ́wọ̀n ológun méjèèjì niwọ́n, Grant rìi wípé pàṣípààrọ̀ yìí ń jẹ́ ki ogun yìí máa gbòrò síi, tí ó ń jẹ́ kí àwọn ọmọ ogun tí ó ń padà, jẹ́ kí àwọn ọmọ ogun tí ó wà ní gúúsù máa tó. John Wilkes Booth, tí ó jẹ́ ara apa Gúúsù, tí ó sì já fáfá nínú ìsọ̀rọ̀ nípa ìṣọ̀kan ṣe ètò lati fipá jí ààrẹ gbé kí ó sì mu fún àwọn Ologun ìṣọ̀kan, títí di ìgbà tí àwọn àríwá á fi gbà láti padà sí fífi ẹlẹ́wọ̀ ṣe pàṣípààrọ̀. Booth gba ọmọṣẹ́ Samuel Arnold, George Atzerodt, David Herold, Michael O'Laughlen, Lewis Powell (tí wọ́n tún mọ̀ sí  "Lewis Paine"), àti John Surratt lati ran-án lọ́wọ́. Ìya Surratt, Mary Surratt, fi ibi tí ó ti ń ta ọtí sílẹ̀ ní  Surrattsville, Maryland, ó sì lọ sí ilé kan ní  Washington, D.C., níbi tí Booth ti ń báa lálejò.
Ìṣekúpa Abraham Lincoln Bí ó tilẹ̀jẹ́ wípé  Booth àti Lincoln kò mọ ara wọn rí, Lincoln mọ̀ nípa Booth, ó sì ma ń fẹ́ràn lati máa wo eré rẹ̀ ní orí ìtàgé Ford. Lincoln ti wo Booth ní oríṣiríṣi eré ìtàgé tí ó ti ṣe ní orí ìtàgé Ford, pẹ̀lú ìkan tí wọ́n ń pè ní Marble Heart ní orí ìtàgé Ford ní Ọjọ́ kẹsán Oṣù kọkànlá, Ọdún 1863. Washington Chronicle pèé ni "eré tí ó rẹwà tí ó sì tí ó fún ni ní ẹ̀dùn ọkàn" tí Booth aì gba àwọn àyẹ̀wò agbohùn tí ó dára fún ipa tí ó kó nínú eré yìí́. Gẹ́gẹ́ bi ìwé  "Lincoln's Sanctuary: Abraham Lincoln and the Soldiers' Home", Lincoln
Ìṣekúpa Abraham Lincoln Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló gbà wípé Lincoln mọ̀ wípé àwọn agbanipa má a pa oun.