Top 10 similar words or synonyms for lóòrèkóòrè

ìsòrí    0.992291

ìjo    0.990905

orùn    0.989907

ìsàlè    0.989717

ìgbómìnà    0.988862

joyè    0.988774

abbl    0.987379

àbò    0.987236

òkèèrè    0.986697

ira    0.986526

Top 30 analogous words or synonyms for lóòrèkóòrè

Article Example
Àjẹsára ibà pọ́njú-pọ́ntọ̀ Àjọ Ìlera Àgbáyé (WHO) gba ni nímọ̀ràn láti má a gba àjẹsára lóòrèkóòrè ní gbogbo orílẹ̀-èdè tí àrùn náà ti wọ́pọ̀. Èyí gbọ́dọ̀ wáyé láàárín àkókò tí ènìyàn jẹ́ ọmọ oṣù mẹ́ẹ̀sán sí mẹ́ẹ̀wá. Àwọn ènìyàn tó ń rin ìrìn-àjò lọ sí àwọn agbègbè ibití àrùn náà ti ń wáyé ní a tún gbọdọ̀ fún ní àjẹsára náà. A kìí sábà nílò àfikún ìwọ̀n àjẹsára náà lẹ́yìn èyítí a bá ti kọ́kọ́ fún ni.
Àjẹsára Rubella Wọ́n kọkọ gba lílò àjẹsára rubella láàyè ní ọdún 1969. Ó wà lórí Àkójọ Àwọn Egbògi Kòṣeémáàní ti Àjọ Ìlera Àgbáyé, àwọn òògùn tó ṣe pàtàkì jùlọ tí a nílò fún ètò ìlera ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ yòówù. Ní bíi 2009, orílẹ̀ èdè tó fi gbígba àjẹsára yíi lóòrèkóòrè sí ètò wọn jú 130. Iye owó  àjẹsára MMR lójú pálí jẹ́ 0.24 USD fún ìda ́ kan ní bí ọdún 2014. Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà iye owó rẹ̀ bíi 50 sí 100 USD.
Àjẹsára ikọ́ọfe Àjọ Ìlere Àgbáyé àti Ilé-iṣẹ́ Ìṣàkóso àti Ìdènà Àrùn gba ni nímọ̀ràn pé kí a fún gbogbo ọmọdé ní àjẹsára ìkọ́ọfe, àti pé kí a fikún àwọn àjẹsára tí à ngbà lóòrèkóòrè. Èyí sì kan àwọn tó ní àrùn kògbóògùn HIV/AIDS pàápàá. Ìwọ̀n egbògi mẹ́ẹ̀ta tí a bẹ̀rẹ̀ lọ́gán tí ọmọ bá ti pé ọmọ ọ̀sẹ̀ mẹ́ẹ̀fà ni a má a ń sábà dámọ̀ràn fún àwọn ọmọdé kékèké. A  lè fún àwọn ọmọ tó ti dàgbà díẹ̀ síi àti àwọn àgbàlagbà ní àfikún ìwọ̀n egbògi. Àjẹsára náà wà gẹ́gẹ́ bí àdàlù pẹ̀lú àwọn àjẹsára mìíràn nìkan.
Àjẹsára Ọ̀fìnkì oríṣi B tí kòkòrò àrùn Haemophilus ń fà Àjẹsára Ọ̀fìnkì oríṣi B tí kòkòrò àrùn Haemophilus ń fà jẹ́ àjẹsára tí ń lò láti dènà àkóràn Ọ̀fìnkì oríṣi B tí kòkòrò àrùn Haemophilus ń fa (Hib). Ní àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti kàá kún ara àjẹsára tí à ń lò lóòrèkóòrè, iye àkóràn àrùn Hib tó ní ipá ti dín kù pẹ̀lú ìwọ̀n tó ju 90% lọ. Èyí sì ti mú kí àwọn àrùn bíi dídáranjẹ̀ awọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tó bo ọpọlọ àti ọ̀pá-ẹ̀yìn (meningitis), dídáranjẹ̀ ẹ̀dọ̀fóró (pneumonia), àti dídáranjẹ̀ bèlú-bèlú (epiglottitis) dín kù lọ́pọ̀lọpọ̀.
Àjẹsára rotavirus Àjọ Ìlera Àgbáyé (WHO) gbani nímọ̀ràn pé kí àjẹsára rotavirus jẹ́ ara àwọn àjẹsára tí à ń gbà lóòrèkóòrè, pàápàá júlọ ní àwọn agbègbè ibi tí àrùn náà ti wọ́pọ̀. A gbọ́dọ̀ ṣe èyí ní ìdàpọ̀ pẹ̀lú gbígbé àwọn ohun bíi fífún ọmọ lọ́yàn, fífọ ọwọ́ ẹni, àti lílo omi tó mọ́ àti ìmọ́tótó lárugẹ. Ẹnu ni a ń gbà fúnni ní àjẹsára náà, ènìyàn sì nílò ìwọ̀n egbògi náà méjì sí mẹta. A gbọ́dọ̀ bẹ̀rẹ̀ sí fúnni láti ìgbà tí ènìyàn bá ti tó ọmọ ọ̀sẹ̀ mẹ́fà.