Top 10 similar words or synonyms for lárúbáwá

wúrà    0.968394

adúláwọ    0.967659

egbógi    0.965223

onímọ    0.963266

àgbáyé    0.960339

òlímpíkì    0.960028

àkójọ    0.959980

káríayé    0.958223

òrùn    0.958069

apáìwọ    0.957676

Top 30 analogous words or synonyms for lárúbáwá

Article Example
Èdè Lárúbáwá Ara èdè Sẹ̀mítíìkì ni èdè Àrábíìkì (Arabic (Èdè Lárúbááwá)). Àwọn tí ó ń sọ ọ́ tó mílíọ̀nù lọ́nà igba gẹ́gẹ́ bí èdè abíníbí ní àríwá Aáfíríkà àti ìlà-oòrùn-gúsù Eésíà (Asia). Àìmoye ènìyàn tí a kò lè fi ojú da iye wọn ni ó ń sọ èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè kejì, ìyẹn èdè àkọ́kún-tẹni ní pàtàkì ní àwọn orílẹ̀-èdè tí ẹ̀sìn Mùsùlùmú ti gbilẹ̀. Àwọn tí ó lọ ṣe àtìpó ní pàtàkì ní ilẹ̀ faransé náà máa ń sọ èdè yìí.
Èdè Lárúbáwá Ède Lárúbáwá tabi ede Araabu
Sánji Sánjì (Ède Lárúbáwá ati Èdè Fárísì: زنج, Èdè Swàhílì ati Èdè Gẹ̀ẹ́sì: Zanj, "Ile awon eniyan alawo dudu")
Èdè Árámáìkì Álúfábéètì méjìlélógún ni èdè yìí ní. Èdè yìí sì se pàtàkì nítorí pé láti ara rè ni Hébéérù, Lárúbáwá àti àwon èdè mìíràn ti dìde.
Mohammed Bin Zaal Mohammed Zaal wà nì àkójọpọ̀  làti ọwọ́ Arabian Business ninu "Ọgọ́run alágbára jùlọ Lárúbáwá lábẹ́ Ogójì", àti nípa Scoop Empire nínu "Méjì-lélógún alágbára jùlọ̣ emiratis lábẹ́ Ogójì ". Ó sí ńse déédé ní Construction Week Online's "construction week power 100".
Èdè Árámáìkì Ní nnkan bíi séńtúrì kéje ni èdè Lárúbáwá gba ipò èdè Árámáìkì. Èka-èdè apá ìwo-oòrùn èdè yìí tí a ń pè ní Síríàkì (Syricac) ni àwon ìjo Àgùdà ará fíríàkì (Syriac Catholic) ń lò.
Boko Haram ní Wilāyat Gharb Ifrīqīyyah (èdè lárúbáwá: الولاية الإسلامية غرب أفريقيا‎‎, (Islamic State West Africa Province, "ISWAP"), àti: Jamā'at Ahl as-Sunnah lid-Da'wah wa'l-Jihād (èdè lárúbáwá: جماعة أهل السنة للدعوة والجهاد‎‎, "Ẹgbẹ́ àwọn ènìyàn Sunnah fún ìwàásù àti Jihad"),  jẹ́ ẹgbẹ́ ìmàle tí ó wà ní àríwá-ìlà oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó tún ṣiṣẹ́ ní orílẹ̀ èdè Chad, Niger àti àríwá Cameroon. Olórí ẹgbẹ́ yìí ní  Abubakar Shekau. Ẹgbẹ́ yìí ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú  al-Qaeda, ṣùgbọ́n ní ọjọ́ kẹtà ọdún  2015, wọ́n ṣe ìkéde ìfọwọ́sowọ́pọ̀ wọn pẹ̀lú  Islamic State of Iraq and the Levant (ISIL). Lati ìgbà tí ìdojú ìjà kọ ìjọba yìí tí bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2009, ẹgbẹ̀rú lọ́na ogún ènìyàn ni wọ́n ti pa, tí wọ́n sí sọ ènìyàn mílíọ́nù méjì àti ọgọ́rún mẹ́ta di aláìnílé tí wọ́n sì ṣe ipò kínín nínú àwọn ẹgbẹ́ jàndùkú tí ó wà ní gbogbo àgbàyé, àwọn Global Terrorism Index ni wọ́n ṣe àkójọ yìí ní ọdún 2015.
Iléṣà Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́hìn, kí àwọn òyìnbó tó kó ẹ̀sìn àtọ̀húnrìnwá de orílè-èdè wa, àwọn Yorùbá ti ni ẹ̀́sìn ti wọn. llésà gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ilẹ́ Yorùbá maa n sin àwọn òrìsà bii ògún, ọ̀sun, ifá, èsù, ọya àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. àkọ́kọ́ nínú àwọn ẹ̀sìn àtọ̀húnrìnwá ti o wá sí orilè - èdè yìí wọ ilẹ̀ Ìjẹ̀sà ni nǹkan bíi ọdún mélòó sẹ́hìn ni a mọ̀ sí ẹ̀sìn Kìrìsìtẹ́nì, ẹ̀sìn Mùsùlùmí tí ó ti àwọn lárúbáwá wọ ilẹ̀ Ìjẹ̀sà.
Ìjẹ̀ṣà Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́hìn, kí àwọn òyìnbó tó kó ẹ̀sìn àtọ̀húnrìnwá de orílè-èdè wa, àwọn Yorùbá ti ni ẹ̀́sìn ti wọn. llésà gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ilẹ́ Yorùbá maa n sin àwọn òrìsà bii ògún, ọ̀sun, ifá, èsù, ọya àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. àkọ́kọ́ nínú àwọn ẹ̀sìn àtọ̀húnrìnwá ti o wá sí orilè - èdè yìí wọ ilẹ̀ Ìjẹ̀sà ni nǹkan bíi ọdún mélòó sẹ́hìn ni a mọ̀ sí ẹ̀sìn Kìrìsìtẹ́nì, ẹ̀sìn Mùsùlùmí tí ó ti àwọn lárúbáwá wọ ilẹ̀ Ìjẹ̀sà.
Ogun Àgbáyé Kìíní Ilẹ̀ Turkey náà dá sí ogun yìí ní osù kẹwàá ọdún 1914. Nígbà tí ilẹ̀ France náà da si ní osù kọkànlá ọdún 1914. Báyìí ni ogun yìí di ogun àgbéyé, tí ó di ìjà àjàràn. Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí awọn orílẹ̀-èdè alágbára wọ̀nyí ń ṣe àkóso lé lórí tí wọ́n ń mú sìn pàápàá jùlọ ní ilẹ̀ adúláwọ̀ [Africa] àti ilẹ̀ Lárúbáwá ni gbogbo wọn náà múra láti gbè sẹ́yìn àwọn ọ̀gá wọn láti bá àwọn orílẹ̀-èdè yòókù jà tí èyí sì di isu atayán-an yàn-an káàkiri orílẹ̀-èdè àgbáyé.