Top 10 similar words or synonyms for kasino

anafilasisi    0.993899

sii    0.993551

kúrùpù    0.993442

dun    0.992424

abojuto    0.992092

niiṣe    0.990779

tori    0.989634

ntan    0.989618

atẹgun    0.989094

ẹjẹ    0.988842

Top 30 analogous words or synonyms for kasino

Article Example
Kàsínò Kasino je ibi ti iru awon tete kan ti un sele. O wopo ki a ri awon kasino ni ile itura, ile onje, ile itaja, ninu oko oju-omi igbadun ati ni awon ibi ibewo miran. Awon kasino miran un gbalejo awon faaji live bi awada oniyeye, orin ori-itage, ati awon ere idaraya.
Kàsínò Ikan ninu kasino akoko ti a mo ni Casinò di Venezia, ni Venice Italy larin 1638. O hun sise doni.
Kàsínò "Kasino" gege bi oro wa lati ede Italia, gbongbo oro na ni "Casa" (ile) to tumo teletele si ile kekere. Oro yi yipada lati tumosi ile igbadun nibi ti ijo, orin ati tete ti n waye.
Kàsínò Ni orundun 19, itumo "kasino" tun je awon ile igboro nibi ti orisirisi igbadun bi tete, ere idaraya ti n sele. Apere iru ile bayi ni Newport Casino ni Newport, Rhode Island.
Kàsínò Ki se gbogbo kasino lo wa fun ayo tita. Copenhagen Casino je ile tiata, ibiyi ni opolopo awon eniyan pejo si fun ipade nigba Ijidide 1848 ni Denmark to so ibe di orile-ede oba olofin ibagbepo. Titi odun 1937 o si je tiata to gbajumo. Hanko Casino to budo si Hanko, Finland ki se fun tete. Ile alejo lo je fun awon alade lati Rosia ti won be ibe wo fun igbadun spa ni opin awon odun 1800, loni won n lo gege bi ile onje. Ibi to n je "Kasino", ni Avalon Harbor ni Erekusu Katalina, ko je fun ayo tita nitoripe ofin de tete nigbati won ko ni Kalifonia.