Top 10 similar words or synonyms for kambodia

owonina    0.997218

aba    0.996522

isola    0.996492

dije    0.996387

iparapo    0.996081

ajegunle    0.995928

davis    0.995452

triangle    0.995366

ajapo    0.995331

ipase    0.995290

Top 30 analogous words or synonyms for kambodia

Article Example
Kàmbódíà Itobi Kambodia fe to ati iye awon eniyan to ju egbegberun 14 lo ti won je Khmer. Araalu Kambodia la n pe ni "ara Kambodia" tabi "Khmer", botilejepe yi to gbeyin yi ntokasi si awon eya eniyan Khmer. Opo awon ara Kambodia ni won je elesin Theravada Buddhist, sugbon bakanna ni awon elesin musulumi Cham tun wa nibe, bakanna awon ni awaon eya Saina, Vietnam ati awon eya elesin oosa tun wa..
Àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè Kambodia - Kamẹroon - Kanada - Kazakhstan - Kenya - Kiribati - Kuwait - Kyrgyzstan
Norodom Sihamoni Norodom Sihamoni (, ojoibi 14 May 1953) ni Oba orile-ede Kambodia.
Kàmbódíà Kambodia je ifobaje onilana-ibagbepo pelu Norodom Sihamoni gege bi Oba. Phnom Penh ni oluilu re ati ilu titobijulo nibe, ohun si tun ni gbanga fun okowo, aje, ile-ise ati asa ni Kambodia. Siem Reap, to je ilu to sunmo Angkor Wat ni enu bode si agbegbe Angkor nibi to je ibi ibewo. Battambang, ilu titobijulo ni apaiwoorun Kambodia, ggbajumo fun ogbin iresi re, Sihanoukville, ilu leba odo ni ebute alakoko ati ibi igbadun eti odo.
Kàmbódíà Ileoba Kambodia, to je mimo bi Kampuchea tele, tabi ', to wa lati Sanskrit ' ()), je orile-ede ni Guusuilaorun Asia to ni bode mo Thailand ni iwoorun ati ariwaiwoorun, Laos ni ariwa, Vietnam ni ilaorun ati guusuilaorun, ati Ikun-omi Thailandi ni guusu. Jeografi ile Kambodia wa labe Odo Mekong (Khmer: "" () tabi "odo ninla") ati Tonlé Sap (; "adagun odo tutu").
Kàmbódíà Ise-Agbe ni eyi to se kokojulo ninu okowo Kambodia, pelu bi 59% awon eniyan ngbera le ise agbe fun igbe won (nibi ti iresi ti je ogbin pataki). Aso, isebewo, ati ile kiko na tun se pataki, ibewo awon ara okere si Angkor Wat fe to egbegberun 4. Ni 2005, alumomi ile bi epo ati efuufu adanida je wiwari ni labe agbegbe omi Kambodia, nigbati wiwajade won fun tita ba bere ni 2011, ipawo epo yi yio kopa gidigidi lori okowo ile Kambodia.