Top 10 similar words or synonyms for kúrùpù

dun    0.996393

sii    0.995887

riru    0.994907

kasino    0.993442

tori    0.993237

ntan    0.993010

abojuto    0.992768

anafilasisi    0.992244

atẹgun    0.991595

bombu    0.991238

Top 30 analogous words or synonyms for kúrùpù

Article Example
Kúrùpù Awọn aami aisan miiran ni ninu ibà, coryza (awọn aami aisan to wọpọ fun otutu), ati egungun igbaya ti o sa wọle. Dida itọ́ lẹnu tabi ìwò alaisan nṣe afihan awọn ipo aisan miiran.
Kúrùpù Idiye Westley ni ọ̀nà eto ti o wọpọ julọ lati sọ bi kúrùpù ṣe lewu si. A maa nlo ayẹwo yii fun awọn ète iwadi dipo iṣẹ iṣegun oyinbo. O jẹ akọjọ iye awọn aami ti a yan fun awọn abuda marun: ipele imolara, ti o ni àwọ̀-bulu, idiwọ ọnafun, bi atẹgun ṣe nwọle, ati si sunki. Iye aami ti a fi fun ọkọọkan awọn abuda ni a ṣe akọjọ ninu tabili ti o wa lọwọ ọtun, ati iye abajade aami wa laarin oodo si ẹẹtadinlogun (0 to 17).
Kúrùpù Ida 85% awọn ọmọde ti o nlọ si ẹka pajawiri ni aisan ti ko le, kúrùpù ti o lewu sọwọn (<1%).
Kúrùpù Abẹrẹ ajẹsara (oogun abẹrẹ ajẹsara) fun influenza ati diphtheria le dẹkun kúrùpù.
Kúrùpù Kúrùpù ti o niiṣẹ pẹlu fairọsi jẹ lọpọ igba self-limited arun (fun saa diẹ); kúrùpù kii saba fa iku lati owo ikuna mimi ati/tabicardiac arrest. Awọn aami aisan maa nsaba ngberu laarin ọjọ  meji, ṣugbọn eyi le wa fun bii ọjọn meji. Awọn ewu miiran ti ko wọpọ ni ninu bacterial tracheitis, pneumonia, ati pulmonary edema.
Kúrùpù Ninu ida marundinlọgọrin (75%) iṣẹlẹ parainfluensa fairọsi, oriṣi 1 ati 2, ni fairọsi ti o nfa kúrùpù/laringotrakiatisi ti o lewu gan-an. Awọn fairọsi miiran ti o le fa kúrùpù ni influenza A ati B, measles, adenofairọsi ati respiratory syncytial virus (RSV). Kúrùpù ti o ṣẹlẹ logiji fun igba diẹ (kúrùpù ti o ni gbígbó) maa nwaye nitori iru ẹgbẹ fairọsi kanna bii ti o lewu gan-an laryngotracheitis, ṣugbọn kii saba ni awọn aami arun ti o wọpọ (bii iba, ọ̀nà-ọfun ti o ndun ni, ati sẹẹli ẹjẹ funfun ti o lọ silẹ) ninu. Abojuto, ati idahun si abojuto naa tun jọra.
Kúrùpù Kúrùpù ti o niiṣe pẹlu bakiteria ṣee pin si laryngeal diphtheria, bacterial tracheitis, laryngotracheobronchitis, ati laringotrakiobronkopneumonitisi. Laringeal diphtheria maa nwaye nitori "Corynebacterium diphtheriae" nigbati bakiteria trakitisi, laringotrackiobronkaitisi, ati laringotrakobronkopneumonitisi maa nwaye nitori fairọsi, pẹlu bakiteria ti o lọwọ sii. Awọn bakiteria ti o wọpọ julọ ni"Staphylococcus aureus", "Streptococcus pneumoniae", "Hemophilus influenzae", ati "Moraxella catarrhalis".
Kúrùpù Kúrùpù jẹ eyiti a maa nmọ nipa iṣẹ iwadi iṣegun oyinbo. Igbese akoko ni lati yo kuro awọn iṣẹlẹ idiwo ni ọ̀nà-atẹgun oke, papa julọ epiglottitis, oju-ọ̀nà atẹgun nkan ajẹji, subglottic stenosis, angioedema, retropharyngeal abscess, andbacterial tracheitis.
Kúrùpù Awọn ọmọde ti o ni kúrùpù ni a gbọdọ jẹ ki ara wọn balẹ bi o ba ṣee ṣe si. A le fun ni awọn sitẹroidi loorekoore, pẹlu ẹfinifirini ni a nlo fun awọn iṣẹlẹ ti o lewu. Awọn ọmọde ti atẹgun ti o to (iye atẹgun ti a nmi sinu ti o wa ninu ẹjẹ) ti ko to 92% gbọdọ gba atẹgun ti a nmi simu, awọn eniyan ti o ni kúrùpù ti o lewu ni a le da duro si ile-iwosan lati bojuto wọn. Bi atẹgun ti a nmi simu ba nilo, a gba ni niyanju lati lo "blow-by" (mimu orisun atẹgun ti a nmi simu kan sunmọ oju ọmọ naa), nitori kii fa rukerudo bi lilo iboju. Pẹlu abojuto, iye eniyan ti o kere si 0.2% ni o nilo endotracheal intubation(rọba kan ti a maa nfi sinu ọ̀nà-atẹgun .
Kúrùpù Arun fairọsi maa nwo inu awọn sẹẹli ẹjẹ funfun ti o si ma nfa wiwu larynx, trachea, ati ẹ̀dọ̀-f ọ́ọ́rọ́ nla (ọ̀nà-atẹgun ). Wiwu le jẹ ki mi i ki o nira.