Top 10 similar words or synonyms for júpítérì

dagba    0.997708

ojuorun    0.997628

waye    0.996881

lona    0.996095

marun    0.995719

mejeji    0.995353

nje    0.995333

bee    0.995295

eti    0.995044

pilaneti    0.994524

Top 30 analogous words or synonyms for júpítérì

Article Example
Júpítérì Júpítérì ni sistemu faint oruka planeti die to ni igesoto meta: an inner toru awon inu particles ti won unje halo, oruka to mole lafiwe, ati oruka gossamer ode. Awon oruka yi da bi pe won je eruku, laije yinyin bi ti awon oruka Saturn. Oruka agba se e se ko je sise lati owo awon eroja to ta kuro lodo awon ajaeyin Adrastea ati Metis. Eroja to je pe yio bo pada sinu osupa na je fifa sinu Júpítérì nitori agbara irelura to ni. Ojuonaiyipo eroja te lo sodo Júpítérì be sini eroja tuntun unje fifikun pelu ifaragbara miran. Lona kanna ni awon osupa Thebe ati Amalthea da iru ohun inu meji ti oruka gossamer.
Júpítérì Lati bi 75 itanka Júpítérì lati odo planeti na, ibasepo igberinojuorun na mo iji orun unfa bow shock. Eyi to yi igberinojuorun Júpítérì ka je a magnetopause, to budo si eti inu magnetosheath—agbegbe larin re ati bow shock. Iji orun unsebasepo mo awon agbegbe yi, lati fa igberinojuorun na ni lee side Júpítérì to si unfa sita titi to fi fe de ojuonaiyipo Saturn. Awon osupa Júpítérì merin titobijulo ni gbogbo won yipolojuona to wa ninu igberinojuorun Júpítérì, eyi unda ao bo won lowo iji orun.
Júpítérì Júpíta ni pilánẹtì karun lati odo Oorun ati pilaneti toto-bijulo ninu Ilana Oorun. O je omiran efuufu kan pelu isupo kan to fi die din ju ikan ninu ida egberun ti Orun lo, sugbon isupo lona meji ati abo gbogbo awon pilaneti yoku ninu aato Orun wa lapapo. Júpíta je kikosoto bi omiran efuufu kan pelu Satoonu, Uranoosi ati Nepitun. Lakopo, awon planeti merin yi je pipe nigba miran bi pilaneti .
Júpítérì Júpíta je ise awari pelu opolopo akitiyan nipa lilo oko-ofurufu roboti, agaga nigba ti awon asewadi akoko bii: Pioneer ati Voyager leyin awon wonyii ni Galileo orbiter. Oko iwadi to pese lo si Júpítérì ni oko-ofurufu to n lo si Pluto, New Horizons ni opin osu Irele 2007. Oko iwadi yi lo iwolura lati odo Júpíta lati fun ni agbara ere pupo. Awon iwakiri ojo iwaju ninu sistemu Jofia ni wiwa omi ti ti yinyin bo mole ninu osupa Europa.
Júpítérì Júpíta je kiki ohun elo elefuufu(gass) ati olomi. Ohun ni o tobi julo laarin awon omiran efuufu mererin ati bakan naa pilaneti ti o tobi julo ninu aato Orun pelu diamita 142,984 km ni agbede-meji re. Iwonba ninu Júpítérì, 1.326 g/cm³, ni elekeji to ga julo laarin awon pilaneti omiran efuufu. Sugbon, igbi re kereju ti awon pilaneti onile mererin lo.