Top 10 similar words or synonyms for itokowo

bolívar    0.996272

diedie    0.995687

kanada    0.995577

abu    0.995465

saleh    0.995190

nukleotidi    0.995129

dar    0.995106

niwon    0.994920

iyearabudo    0.994702

ayeijoun    0.994686

Top 30 analogous words or synonyms for itokowo

Article Example
Japan Alagbara itokowo ninla, Japan ni o ni itokowo keta totobijulo lagbaye gegebi GIO oloruko ati gegebi ifiwe agbara iraja. Bakanna o tun je atajalode kerin titobijulo ati arajalatode kerin titobijulo lagbaye. Botilejepe Japan lonibise ti jowo eto re lati gbe ogun, o di ile-ise ologun odeoni mu fun abo ati ise alafia. Leyin Singapore, Japan lo ni ipaniyan to kerejulo lagbaye. Gegebi UN ati WHO se diye, Japan lo ni ireti igbeaye gigunjulo larin gbogbo awon orile-ede lagbaye. Bakanna o tun ni iku omo-owo tokerejulo keta, gegebi UN se so.
Albáníà Albania je oseluarailu onileasofin pelu itokowo toun yipada. Oluilu Albania, Tirana, je ile fun awon eniyan bi 600,000 ninu awon eniyan 3,000,000 to wa lorile-ede na. Atunse oja alominira ti si orile-ede sile fun inawo idagbasoke latokere, agaga fun idagbasoke okun ati eto irinna.
Pọ́rtúgàl Ni orudnun 15k ati 16k, ntoripe o lewaju Igba Iwari, Portugal di ileobaluaye to nile kakiri Afrika, Asia, Oseania, ati Gusu Amerika, lati di ikan ninu awon alagbara itokowo, oloselu ati ologun lagbaye. Ileobaluaye Portugal ni ileobaluaye akariaye akoko ninu itan, ati eyi to pejulo ninu gbogbo awon obaluaye alamusin Europe. Sibesibe, ipo orile-ede ti je riresile gan titi to fi di orundun 19k, agaga leyin ilominira ile Brasil, to je imusin totobijulo re.
Adam Smith Adam Smith (iribomi 16 June 1723 – alaisi 17 July 1790 ) je amoye alawujo ati asiwaju ninu eko itokowo oloselu ara Skotlandi. Enikan pataki ninu Olaju Skotlandi, Smith ni o ko iwe "The Theory of Moral Sentiments" ati "An Inquiry into the Nature and Causes of the Wealth of Nations" to gbajumo lasan bi "The Wealth of Nations", je gbigba bi "ise ninla" re ati iwe akoko odeoni nipa isiseitokowo. O je ko gbajumo gidigidi be sini yio je ki o nikopa lori isiseitokowo titi doni. Smith je titokasi kakiri gege bi baba isiseitokowo ati iseowoele.