Top 10 similar words or synonyms for itọju

abojuto    0.996791

niyi    0.995173

niiṣe    0.994723

eniti    0.994485

ese    0.994310

labẹ    0.994183

anafilasisi    0.994162

wọpọ    0.994138

fairọsi    0.994046

adijo    0.993992

Top 30 analogous words or synonyms for itọju

Article Example
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C . Dida ara wa ni ida 70-80% ninu awọn eniyan ti o ni irufẹ ẹjẹ 2 ati 3 HCV pẹlu itọju ọsẹ mẹrinlelogun . Dida ara wa ni ida 65% ninu awọn eniyan ti o ni irufẹ ẹjẹ 4 pẹlu itọju laarin Ọsę mejidinlaadọta. Ẹri itọju arun irufẹ ẹjẹ 6 ko wọpọ, ẹri itọju ti o wa si jẹ bi ọsẹ mejidinlaadọta ni irufẹ iye oògun kanna pẹlu àrùn irufẹ ẹjẹ 1.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Ni 2011, bii ọgọọrun awon oògùn itọju ni won nse iwadi re lowo fun àrùn jẹdọjẹdọ C. Lara awọn oogun naa ni ogun itọju lati wo àrùn jẹdọjẹdọ, immunomodulators, ati cyclophilin oludilọwọ. Awọn ọna tituun itọju yii waye nipa imọsi lori kokoro àrùn jẹdojẹdọ C.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Didaraya nipa itọju yatọ gęgębi irúfẹ ẹyà ẹjẹ ti ję. Dida ara fun igba pipę ję 40-50% ninu awọn eniyan ti o ni irufẹ ẹjẹ 1 HCV pẹlu itọju ọsẹ mejidinlaadọta
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Awọn ti o ni akoran segesege ẹdọ HCV to daju gbọdọ lọ fun itọju. Itọju tó wà bayi jẹ apapọ pegylated interferon ati ogun asodisi kokoro ribavirin fun ọsẹ 24 tabi 48, ti o da lori irufẹ HCV. Abajade to yanranti nṣẹlẹ fun àádọta si ọgọta ninu ìdá ọgọrun awọn eniyan ti a ṣetọju. Àpapọ yala boceprevir tabi telaprevir pẹlu ribavirin ati peginterferon alfa nse iranlowo fun aṣodisi kὸkὸrὸ fun irúfẹ ẹjẹ 1 ti abajade arun jẹdọjẹdọ C. Awon abayọri fun itọju wọpọ; idaji awọn ti a tọju ni, ami ìdánimọ àrùn ayỌkęlę; ati irírí kẹta ní ìṣÒro imọlára. Itọju ni oṣu mẹfa akọkọ dara ju itọju lẹhin ti àrùn jẹdọjẹdọ C ba ti lewu. Bi eniyan kan bani akoran titun ti ko si tii kuro lẹhin oṣu mẹjọ si mejila, a gba iru ęni bęę niyanju lati lo pegylated interferon fun Ọsę mẹrinlelogun. Fun awọn ti o ni talasémíà (a blood disorder), ribavirin dara, ṣugbọn yoo fa gbigba ẹjẹ.
Àtọ̀sí ajá Awọn ọna lati dena àrùn naa ni ninu mimu gberu nini aaye si omi ti o mọ́ ati di din iye awọn ìgbín ku. Ni awọn agbegbe ti àrùn naa ti wọpọ a le ṣe itọju gbogbo ẹgbẹ papọ lẹẹkan naa ati l’ọdọọdun fun àrùn naa pẹlu ogun praziquantel. A nṣe eyi lati din iye awọn eniyan ti o ni ikọlu ku ati pe nipa bẹẹ ki a din titan kiri àrùn naa ku. Praziquantel tun jẹ itọju ti Ajọ Ilera Lagbaye (World Health Organization) gba n’imọran fun awọn ti a mọ wipe wọn ti ni ikọlu.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C The World Hepatitis Alliance coordinates World Hepatitis Day, waye lọdọọdun ni July 28. Inawo ori arun jẹdọjẹdọ C nipa lori olukuluku ati si awujọ. Ni United States iwọn owo igbe aye arun naa ni a ṣiro si 33,407 USD ni 2003, pẹlu apapọ iye igbin ẹdọ si ara jẹ 200,000 USD ni 2011. Ni Canada iye owo ẹkọ itọju aṣodikokoro gaa bii 30,000 CAD ni 2003, nigba ti iye owo ti United States wa laarin 9,200 ati 17,600 ni 1998 USD. Ni ọpọ ibi lagbaye ni awọn eniyan kole san owo itọju aṣodikokoro yi nitori wọn koni idábòbò adíyelófò tabi idíyelófò ti wọn ni kole sanwo aṣodikokoro naa.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Awọn alatilẹhin sọ pe itọju nipa lilo oògun ibilę yoo wulo fun àrùn jẹdọjẹdọ C pẹlu wàràa thistle, ginseng, ati kọlọida silfa. Sibẹsibe, ko si oògùn ìbílẹ ti o wo àrùn jẹdọjẹdọ C, ko si si àrídájú ẹrí pe oògùn ibilẹ ni agbára lóri kòkòrò na rárá.
Anafilasisi Awọn iṣẹ kan nlọ lọwọ lati ṣẹda efinifirini [[sublingual]] lati ṣe itọju anafilasisi. [[Abẹrẹ si abẹ ọra ara]] ti o lodi si IgE (anti-IgE) antibody [[omalizumab]] ni a nṣe ayẹwo gẹgẹ bii ọna lati dẹkun pipada, ṣugbọn a ko ti gba ni niyanju lilo rẹ.
Ìrìnkèrindò nínú Igbó Elégbèje “Ṣugbọn kini kan ko ni ṣai ya yin lẹnu nipa emi papa ẹ kò bi mi nkan na dan? On ni wipe lati igbati a ti kuro ni ibiti Ẹlẹgbara ti le wa, ọkan mi ko kuro lara obinrin ti o ṣe itọju mi nigbati Ẹlẹgbara fi le mi kọja oke odò. Gẹ́gẹ́ bi mo ti sọ ṣaju, nko fẹran obinrin ṣaju akoko na, nwọn tilẹ nma rùn si mi ni, nko si mọ ohun ti o fa ti fifẹ ti mo dede wa fẹran obinrin na ju ti itọju mi ti o ṣe nigbana lọ, ṣugbọn ki a má sa fa a gun lọ titi, gongo ori ẹmi mi ni ọmọ na duro le, ọrọ rẹ̀ ki isi ikuro lẹnu mi tobẹ ti o jẹ pe awọn ẹnikeji mi ma nfi mi ṣe yẹ̀yẹ́ ṣa ni...
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Àwọn ohun itọju ara bi i abẹfẹlẹ, burọọsi-eyin, ati àwọn irin-iṣẹ́ ṣíṣe ọwọ tàbí fun ṣíṣe ẹ́sẹ́ lóge lè kan ẹ̀jẹ. Pínpín wọn lò lè ṣe okunfa ewu àisàn HCV. Àwọn eniyan ni lati ṣọra pelu ọgbẹ́ ati egbo tàbí àwọn ohun miran ti o le mu ara ṣe ẹ̀jẹ. Eniyan ki i ko àìsàn HCV nipa ara-kan-ara lasan, bi i didi mọ ni, fifi-ẹnu-ko-ẹnu, tàbí nipa ajọlo ohun-elo ijẹun tàbí ohun-elo sise-ounje.