Top 10 similar words or synonyms for isotopu

ojise    0.997339

titobi    0.996818

olokiki    0.996537

nukleotidi    0.996209

marksisti    0.996063

curaçao    0.995901

aini    0.995860

eseese    0.995797

itelentele    0.995497

ewon    0.995350

Top 30 analogous words or synonyms for isotopu

Article Example
Háídrójìn onídẹ́útẹ́ríọ̀mù Háídrójìn onídẹ́útẹ́ríọ̀mù ("Hydrogen deuteride") je is a diatomic hóró oniatomu meji to ni isotopu hydrogen meji: isotopu to po H protium ati H deuterium. Afida onihoro re ni HD.
Àkójọ átọ̀mù Àkójọ átọ̀mù ("atomic mass") (m) ni akojo of a specific isotopu pato kan, to saba je kiko ni eyo akojo atomu. Akojo atomu ni apapo akojo awon protoni, neutroni ati elektroni ninu atomu kan soso.
Fránsíọ̀m Francium je wiwari latowo Marguerite Perey ni Fransi (nibi ti apilese yi ti ri oruko) ni 1939. Ohun ni apilese togbeyin ti o je wiwari ninu adanida, kanran jije sisopapo. Lode yara ise-idanwo, francium sowon gidigidi, iye ipase je wiwari ninu alumoni aladalu uranium ati thorium, nibi ti isotopu francium-223 ti n je didasile to si n je jijera bibaun. Iye to kere bi 20–30 g (ounce kan) lowa nigba yiowu kakiri inu igbele Aye; awon isotopu yioku je alasopapo yanyan. Iye titobijulo ti o je kikojo lai isotopu yiowu ni isupo bi awon atomu 10,000 (ti francium-210) ti won je didasaye gege bi efuufu tutugidi ni Stony Brook ni 1997.
Promethium Promethium (, ) je apilese kemika to ni ami-idamo Pm ati nomba atomu 61. O yato si awon apilese yioku nitori pe oun nika ni apilese radioalagbara leyin technetium to je titele pelu awon apilese kemika ti awon isotopu won duro sinsin.
Árgọ̀nù Árgọ̀nù je elimenti kemika kan to ni ami-idamo Ar ati nomba atomu 18. O wa ninu egbe 18 (awon efuufu abiire) lori tabili idasiko awon elimenti. Argonu ni efuufu keta to wopo julo ninu afefeayika Aye, ni 0.93% (9,300 ppm), eyi so di eyi to repete ni ona bi 23.8 bi ti efuufu inu afefeayika tto wopo julo to tele, eyun dioksidi karbonu (390 ppm), ati to po repete ni ona to to 500 bi ti efuufu abiire keji to wopo, eyun neonu (18 ppm). Bi gbogbo argonu yi lo je argonu-40 radiogeniki to wa lati ituka potassium-40 ninu igbele Aye. Ni agbalaaye, argonu-36 ni isotopu argonu to wopo julo, nitoripe o je isotopu argonu to je dida pelu stellar ikojonukleu irawo ninu awon supanofa (awon irawo akomonamona).
Maurice Wilkins Maurice Hugh Frederick Wilkins CBE FRS (15 December 1916 – 5 October 2004) je omo New Zealand ara Ilegeesi asefisiksi ati asebioloji onihoro, ati elebun Nobel ti iwadi re ko ipa lori oye sayensi ita yanyan, iyasoto isotopu, iwokekere oloju ati X-ray diffraction, ati si idagbasoke radar. O gbajumo fun ise re ni King's College London lori igbamu DNA. Fun ise yi, ohun, Francis Crick ati James Watson gba Ebun Nobel fun Iwosan 1962, "fun iwari nipa igbamu onihoro awon onikikan nukleiki ati pataki re igberin ifitonileti ninu awon eroja alaaye."
Johannes Hans Daniel Jensen Johannes Hans Daniel Jensen (June 25, 1907 ni Hamburg – February 11, 1973 ni Heidelberg) je ara Jemani to je onimo fisiksi inuatomu. Nigba Ogun Agbaye Keji, o sise lori ise okun inuatomu fun Jemani, to unje Agbo Uraniom, ninu ibi to ti se afikun pataki si ipinya awon isotopu uraniom. Leyin ti ogun pari, o sise bi ojogbon ni Yunifasiti ilu Heidelberg. O tun je ojogbon alejo ni Yunifasiti Wisconsin–Madison, the Institute for Advanced Study, Indiana University, ati the California Institute of Technology. Jensen pin Ebun Nobel ninu Fisiksi odun 1963 pelu Maria Göppert-Mayer fun aba won fun afijuwe igbaeyin inuatomu.
Astatínì Astatínì tabi Astatine je apilese kemika alagbararadio pelu ami-idamo At ati nomba atomu 85. Ohun eyi towuwojulo keji ninu awon halojin. Botilejepe astatini nje mimuwaye nitori ijera alagbararadio ninu adanida, nitori short aabo emi kukuru re a le ri ni iye tintin. Astatini koko je mimuwaye latowo Dale R. Corson, Kenneth Ross MacKenzie, ati Emilio Segrè ni 1940. Odun meta koja ki o to dipe ipase astatini bakanna je wiwari ninu awon alumoni aladanida. Titi di aipe opolopo awon iwuwa aladanida ati kemika astatini je nipa sise afiwe mo awon apilese miran. Melo ninu awon isotopu astatini nje lilo bi olufonsita iwonwo alpha ninu awon imulo sayensi, be sini adanwo awon imulo oniwosan fun astatini 211 ti sele. Lowolowo astatini ni apilese aladanida to sowonjulo pelu idiye bi 30g ni o wa ninu igbele Aye.
Sódíọ̀mù Sódíọ̀mù jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà kan tó ní àmí-ìdámọ̀ Na (láti ) lórí tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì àti nọ́mbà átọ̀mù 11. O je metali riro, alawo fadaka funfun to untete sedarapo, beesini o je ikan ninu awon metali alkali; Isotopu re nikan to fesemule ni Na. Metali yi ko da wa fun ra ara re nikan ni idaye, sugbon be o wa ni adapo; o koko je pipinsoto latowo Humphry Davy ni 1807 pelu elektrolisisi haidroksidi sodiumu. Sodiomu ni elimenti ikefa to gbale julo ninu ipele-igbele Aye, o si wa ninu opo awon alumoni bi feldspar, sodalaiti ati iyo okuta. Opo awon iyo sodiomu ni won je yiyo somi daada, be sini sodiomu won ti je yiyo jade latowo omi to fi je pe kloridi ati sodiomu ni awon elimenti to wopo ni wuwo ninu awon omi okun Ile-Aye.