Top 10 similar words or synonyms for irufẹ

ṣalanga    0.997534

iṣoro    0.997295

elero    0.997233

asopọ    0.997211

iṣẹlẹ    0.996853

ilo    0.996653

akara    0.996556

mita    0.996396

nfe    0.996333

isale    0.996300

Top 30 analogous words or synonyms for irufẹ

Article Example
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C . Dida ara wa ni ida 70-80% ninu awọn eniyan ti o ni irufẹ ẹjẹ 2 ati 3 HCV pẹlu itọju ọsẹ mẹrinlelogun . Dida ara wa ni ida 65% ninu awọn eniyan ti o ni irufẹ ẹjẹ 4 pẹlu itọju laarin Ọsę mejidinlaadọta. Ẹri itọju arun irufẹ ẹjẹ 6 ko wọpọ, ẹri itọju ti o wa si jẹ bi ọsẹ mejidinlaadọta ni irufẹ iye oògun kanna pẹlu àrùn irufẹ ẹjẹ 1.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Didaraya nipa itọju yatọ gęgębi irúfẹ ẹyà ẹjẹ ti ję. Dida ara fun igba pipę ję 40-50% ninu awọn eniyan ti o ni irufẹ ẹjẹ 1 HCV pẹlu itọju ọsẹ mejidinlaadọta
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Iṣayẹwo tiṣu Ẹdọ le ṣafihan ipele, tí ẹdọ ti bàjẹ dé ṣugbọn ewu wa ninu ilana yii. Irufẹ awỌn iyàtỌ ti iṣayẹwo tiṣu se àwárí rę ni limfosaites laarin tiṣu ẹdọ, awọn limfọidi foliku ninu pọta tíráyádì, ati awon iyipada si apo ÒrÓ-ǹ-ro. Oriṣirisi ayẹwo ẹjẹ lowa ti o gbiyanju lati safihan ipele idibàję ati ìdínkù ìdí fun iṣayẹwo tiṣu.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Awọn ti o ni akoran segesege ẹdọ HCV to daju gbọdọ lọ fun itọju. Itọju tó wà bayi jẹ apapọ pegylated interferon ati ogun asodisi kokoro ribavirin fun ọsẹ 24 tabi 48, ti o da lori irufẹ HCV. Abajade to yanranti nṣẹlẹ fun àádọta si ọgọta ninu ìdá ọgọrun awọn eniyan ti a ṣetọju. Àpapọ yala boceprevir tabi telaprevir pẹlu ribavirin ati peginterferon alfa nse iranlowo fun aṣodisi kὸkὸrὸ fun irúfẹ ẹjẹ 1 ti abajade arun jẹdọjẹdọ C. Awon abayọri fun itọju wọpọ; idaji awọn ti a tọju ni, ami ìdánimọ àrùn ayỌkęlę; ati irírí kẹta ní ìṣÒro imọlára. Itọju ni oṣu mẹfa akọkọ dara ju itọju lẹhin ti àrùn jẹdọjẹdọ C ba ti lewu. Bi eniyan kan bani akoran titun ti ko si tii kuro lẹhin oṣu mẹjọ si mejila, a gba iru ęni bęę niyanju lati lo pegylated interferon fun Ọsę mẹrinlelogun. Fun awọn ti o ni talasémíà (a blood disorder), ribavirin dara, ṣugbọn yoo fa gbigba ẹjẹ.
Àìjẹ̀un-dáradára Àìjẹ̀un-dáradára tabi aijẹ ounjẹ t'oyẹ jẹ ipo ti o n waye lara jijẹ ounjẹ ti awọn ounjẹ aṣara l'ore koto tabi ti o ti pọju ti o si fa awọn iṣoro ilera. Awọn ounjẹ aṣara lore le jẹ́: kalori, puroteni, kabọhidireti, awọn fitamin tabi minira. A saba maa n lo ni pataki lati tọkasi aijẹun to dara to nibi ti kosi kalori, puroteni tabi awọn eroja ounjẹ; sibẹsibẹ, o tun pẹlu ijẹun ju. Bi aijẹ eroja ounjẹ to ba waye boya ni iloyun tabi ṣaaju ọmọ ọdun meji o le jasi awọn iṣoro aileyipada pẹlu idagba ifojuri ati ọpọlọ. Aijẹ ohun aṣara lore to ti o gaju, ti a mọsi ifebipa, leni awọn aami ti o pẹlu: ràrá, ara gbigbẹ, ailokun ti o to, ati ẹsẹ wiwu ati ikùn. Awọn eniyan tun saba maa n ni awọn akoran wọn si saba maa n tutù. Awọn aami ti aisi eroja inu ounjẹ to dale irufẹ eroja ounjẹ ti kosi nibẹ.