Top 10 similar words or synonyms for ironsi

abu    0.994078

abiola    0.993446

sani    0.992890

hispaniola    0.991524

bamako    0.991288

adua    0.990314

ilaoorun    0.990237

hermann    0.990026

azikiwe    0.989913

saleh    0.989200

Top 30 analogous words or synonyms for ironsi

Article Example
Johnson Aguiyi-Ironsi Johnson Thomas Umunnakwe Aguiyi-Ironsi (March 3, 1924 - 29 July, 1966) je ologun omo orile-ede Naijiria. Leyin ti ologun gba ijoba ni 15 January, 1966, Aguiyi-Ironsi di Olori Orile-ede Naijiria titi di 29 July, 1966 nigbati won dote si ijoba re ti won si pa.
Johnson Aguiyi-Ironsi A bi ni ilu Umuahia to wa ni Ipinle Abia loni ni ojo keta osu keta odun 1924 fun Mazi ati Ezugo Aguiyi. Nigba to pe omo odun mejo Aguiyi-Ironsi ko lo si odo egbon re obinrin Anyamma eni to je aya Theophilius Johnson to je osise asoju ijoba fun ile Sierra Leone ni Umuahia. Nigbato to omo odun mejidinlogun Ironsi bo si ise ologun Naijiria botilejepe egbon re lodi si.
Nàìjíríà Aidogba yi ati ibaje eto idiboyan ati oloselu fa ni 1966 de awon ifipagbajoba ologun lera lera. Akoko sele ni January ti awon odo oloselu alapaosi labe Major Emmanuel Ifeajuna ati Chukwuma Kaduna Nzeogwu. O ku die ko yori si rere - awon olufipagbajoba pa Alakoso Agba, Sir Abubakar Tafawa Balewa, Asolori Agbegbe Apaariwa Naijiria, Sir Ahmadu Bello, ati Asolori Agbegbe Apaiwoorun ile Naijiria, Sir Ladoke Akintola. Botileje bayi, sibesibe awon olufipagbajoba na ko le gbe ijoba kale nitori isoro bi won yio ti se, nitori eyi Nwafor Orizu, adelede Aare je mimu dandan lati gbe ijoba fun Ile-ise Ologun Adigun Naijiria labe Apase Ogagun JTY Aguyi-Ironsi.
Murtala Muhammad Murtala kò faramó ìjoba ológun Johnson Aguiyi Ironsi tí ó fipá gbà joba ni osù kìíní odún 1966 nínú èyí tí wón pa òpòlopò olórí Nàíjíríà tó jé omo apá gúúsù lónà tó burú jáì! Fún ìdí èyí ó kópà nínú ìfipá - gbà ijòba tó wáyé ni July 21, 1966. Wón fipá gba papakò òfurufú ìkejà; èyí tí wón ti yí orúko rè sí Murtala Mohammed International Airport làti fi yé. Ó kókó fé fi ìfipá gbà ijoba yìí gégé bíi igbésè fún àwon ara gúúsù láti ya kúrò lára Nàíjíríà sùgbón ó da àbá yìí nù nígbèyìn.