Top 10 similar words or synonyms for ileasofin

olokiki    0.995629

oludasile    0.994279

ewon    0.994243

ita    0.993799

bebe    0.993306

leba    0.993293

koni    0.993232

egypti    0.993156

akojọ    0.993002

togajulo    0.992993

Top 30 analogous words or synonyms for ileasofin

Article Example
Lobamba Lobamba ni oluilu asa ibile ati ibujoko ileasofin orile-ede Swaziland.
Ratnasiri Wickremanayake Ratnasiri Wickremanayake ((, ) ojoibi May 5, 1933) je oloselu ara Sri Lanka ati Alakoso Agba ile Sri Lanka tele lati 2005 de 2010. Lowolowo o je omo Ileasofin ile Sri Lanka.
Jamáíkà nitelorun ara won, won si lodi si itowobo Ileasofin si oro to n lo ni erekusu ohun, botilejepe opo awon to ni eru n beru pe ijidide awon eru le se.
Valdis Dombrovskis Valdis Dombrovskis (ojoibi 5 August 1971) oloselu ara Latfia lowolowo to je Alakoso Agba ile Latfia. Teletele o sise bi Alakoso Inawo ati bi Omo Ileasofin Europe fun New Era Party.
Índíà Aare ile India ni olori orile-ede to je didiboyan latowo igbimo onidiboyan fun igba odun marun kan. Alakoso Agba ni olori ijoba, ohun lo si segbese opo agbara alase. Gege bi yiyan latowo Aare,Alakoso Agba je titileyin latowo egbe oloselu tabi ifowosowopo oloselu to ni ogunlogo awon ijoko ni ile kekere Ileasofin. Apa ijoba apase ni Aare, Igbakeji Aare, ati Igbimo awon Alakoso (Kabinet ni igbimo apase re) ti olori re je Alakoso Agba. Alakoso yiowu to ni ipo gbodo je ikan ninu awon omo ile ileasofin. Ninu sistemu onileasofin ti India, apase wa labe asofin, nibi ti Alakoso Agba ati Igbimo re wa labe ile kekere.
Roza Otunbayeva Roza Isakovna Otunbayeva (, ; ojoibi August 23, 1950) ni Aare orile-ede Kyrgyzstan. Won bura re ni July 3, 2010, leyin to ti dipo bi olori igbadie leyin ijidide April 2010 to fa lilekuro Aare Kurmanbek Bakiyev lori aga. Otunbayeva je alakoso oro okere tele ati olori ipade ileasofin fun Egbe Toseluaraalu Awujo ile Kyrgyzstan.
Índíà Asofin ile India ni Ileasofin oniyewumeji, to ni ile oke ti o n je Rajya Sabha (Igbimo awon Ipinle) ati ile kekere to n je Lok Sabha (Ile awon Eniyan). Rajya Sabha, agbarajo aiyese, ni 245 omo egbe ti won wa nibe fun odun marun. Opo won je didiboyan taara latowo awon asofin ipinle ati agbegbe gege bi iye awon eniyan won.
Dubai Dubai ( ; ) je ikan ninu awon emireti meje to wa ni United Arab Emirates (UAE). O budo si guusu Ikun-omi Persia lori Arabian Peninsula ohun sini o ni olugbe totobijulo pelu aala ileagbegbe totobijulo larin gbogbo awon emireti leyin Abu Dhabi. Dubai ati Abu Dhabi ni emireti meji pere ti won ni agbara idina lori awon oro pataki ni ileasofin.
Shavkat Mirziyoyev Shavkat Miromonovich Mirziyoyev (lede Rosia Шавкат Мираманович Мирзиёев "Shavkat Miramanovich Mirziyoyev" loun lo) (ojoibi 1957) ni Alakoso Agba orile-ede Uzbekistan. O je didaloruko sipo yi latowo Aare Islam Karimov ni ojo 12 Osu Kejila 2003, beeni ileasofin Usbeki si faramo. O ropo Alakoso Agba O‘tkir Sultonov to je lilekuro. Igbakeji re ni Ergash Shoismatov.
Andry Rajoelina Andry Nirina Rajoelina (ojoibi May 30, 1974) je omo Malagasi oloselu ati onisowo to ni redio ati telifisan. Rajoelina setuka ileasofin, o paro awon adajo ile ejo giga, o si bura funrare bi olori orile-ede igbepada ile Madagascar ni March 21, 2009, leyin igba ti awon ologun ti yan si ipo yi leyin jagidijagan oloselu to sele i 2009. Rajoelina lo je Baale ilu Antananarivo, to je oluilu Madagascar, lati December 2007 de February 2009.