Top 10 similar words or synonyms for iṣoro

iṣẹlẹ    0.998019

obo    0.997415

irufẹ    0.997295

asopọ    0.997282

mita    0.997215

gbooro    0.997185

ewure    0.996684

taani    0.996503

fifẹ    0.996409

ṣalanga    0.996076

Top 30 analogous words or synonyms for iṣoro

Article Example
Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): P puzzle, n. iṣoro, isúju, rú ni lojú, ohun gígọ
Streptococcal pharyngitis Awọn iṣoro ti o l’ewu gan-an wọnyii le waye nitori ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa:
Àìjẹ̀un-dáradára Àìjẹ̀un-dáradára tabi aijẹ ounjẹ t'oyẹ jẹ ipo ti o n waye lara jijẹ ounjẹ ti awọn ounjẹ aṣara l'ore koto tabi ti o ti pọju ti o si fa awọn iṣoro ilera. Awọn ounjẹ aṣara lore le jẹ́: kalori, puroteni, kabọhidireti, awọn fitamin tabi minira. A saba maa n lo ni pataki lati tọkasi aijẹun to dara to nibi ti kosi kalori, puroteni tabi awọn eroja ounjẹ; sibẹsibẹ, o tun pẹlu ijẹun ju. Bi aijẹ eroja ounjẹ to ba waye boya ni iloyun tabi ṣaaju ọmọ ọdun meji o le jasi awọn iṣoro aileyipada pẹlu idagba ifojuri ati ọpọlọ. Aijẹ ohun aṣara lore to ti o gaju, ti a mọsi ifebipa, leni awọn aami ti o pẹlu: ràrá, ara gbigbẹ, ailokun ti o to, ati ẹsẹ wiwu ati ikùn. Awọn eniyan tun saba maa n ni awọn akoran wọn si saba maa n tutù. Awọn aami ti aisi eroja inu ounjẹ to dale irufẹ eroja ounjẹ ti kosi nibẹ.
Àtọ̀sí ajá Àtọ̀sí ajá (ti a tun mọ si bilhasia, ibà igbín, ati Ibà katayama) jẹ àrùn ti awọn aràn ti o nfa ijamba fun ara ti irú"Ṣistosoma". O le yọ ọpa ti o ngbe ìtọ̀ tabi awọn ifunlẹnu. Awọn ààmì idamọ aisan le ni ninu inu ti o dun ni, igbẹ-ọrin, igbẹ ti o ni ẹ̀jẹ̀ ninu, tabi ẹ̀jẹ̀ ninu ìtọ̀. Fun awọn ti wọn ti ni ikọlu fun igba pipẹ, ẹdọ le bajẹ, kidirin le d’aṣẹ silẹ, ailebimọ, tabi jẹjẹrẹ apo-ìtọ̀ le waye. Ninu awọn ọmọde o le fa ifasẹyin fun idagbasoke ati iṣoro ẹkọ kikọ.
Ṣiṣunu Bi 1.7 si? 5 iṣẹlẹ biliọnu ti ṣiṣunu n ṣẹlẹ lọdọdun. O wọpọ awọn orilẹ ede ti o n gberu, nibiti awọn ọmọde ti n ni ṣiṣunu ni o kere ẹmẹẹta lọdun. Lagbaye, ni 2012, ohun ni ekeji okunfa ti o wọpọ iku awọn ọmọde ti o kere si marun (0.76 milionu tabi 11%). Iemlemọ iwọpọ ṣiṣunu naa wọpọ aijẹun to ati ti o ṣokunfa iwọpọ laarin awọn ti o keresi ọmọ ọdun marun. Awọn iṣoro ọlọjọ pipọ ti o le waye pẹlu ailera idagba ara ati ọpọlọ.