Top 10 similar words or synonyms for gbuuru

ṣá    0.993353

sára    0.993324

sórí    0.993299

fìn    0.993095

êrô    0.992842

òrun    0.992525

sian    0.992378

tótó    0.992263

ìdádúró    0.992144

ogùn    0.992042

Top 30 analogous words or synonyms for gbuuru

Article Example
Àjẹsára rotavirus Àjẹsára rotavirus jẹ́ àjẹsára tí a fi ń dáàbò bo ara ẹni lọ́wọ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí à ń pè ní rotavirus. Àwọn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn wọ̀nyí ló má a ń sábà ṣe òkùnfà ìgbẹ́ gbuuru tó lágbára púpọ̀ láàárín àwọn ọmọdé. Àjẹsára náà a má a dènà ìwọ̀n 15 sí 34% ìṣẹ̀lẹ̀ ìgbẹ́ gbuuru tó lágbára púpọ̀ náà ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ṣì ń tẹ̀síwájú, àti ìwọ̀n 37 sí 96% ìṣẹ̀lẹ̀ ìgbẹ́ gbuuru tó lágbára púpọ̀ náà ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ti ní ìtẹ̀síwájú. Àjẹsára náà dàbí èyí tó má a ń dín ewu ikú tó ti ipasẹ̀ ìgbẹ́ gbuuru wáyé kù láàárín àwọn ọmọdé. Fífún àwọn ọmọ-ọwọ́ ní àjẹsára náà dàbí ohun tó má a ń dín ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn náà kù láàárìn àwọn àgbàlagbà àti láàárín àwọn tí kò tíì gba àjẹsára náà tẹ́lẹ̀ rí.
Ṣalanga oniho Ṣalanga oniho tabi ile igbọnsẹ oniho jẹ irufẹ ile igbọnsẹ ti o n gba igbọnsẹ eniyan sinu iho ilẹ. Wọn le malo omi tabi ki wọn fomi fọ lẹhin ti ẹni mẹta gbọnsẹ sinu ile igbọnsẹ oniho. Bi wọn ba kọ daradara ti wọn ṣetọju rẹ daradara wọn le din ajakalẹ arun ku nipa didinku iye igbọnsẹ eniyan ni awujo lati igbọnsẹ sita gbangba. Eyi din atankalẹ ti awọn kokoro atan arun laarin igbẹ ati ounjẹ nipasẹ awọn kokoro. Awọn awọn kokoro atan arun ni okunfa gan ti akoran igbe gbuuru ati aisan aran inu. Akoran igbe gbuuru ṣokunfa iku 0.7 miliọnu awọn ọmọde labẹ ọdun marun ni 2011 ati 250 miliọnu padanu lilọ ile ẹkọ. Ṣalanga oniho jẹ ọna ti owo rẹ ko han lati ya igbẹ sọtọ kuro lọdọ awọn eniyan.
Àrùn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn Ebola Àrùn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn Ebola (EVD) tàbí Ibà ẹlẹ́jẹ̀ sísun Ebola (EHF) jẹ́ àrùn ẹ̀dá ènìyàn èyítí Kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn Ebola n ṣe òkùnfa rẹ̀. Àwọn àmì àìsàn náà a má a bẹ̀rẹ̀ lẹyìn ọjọ́ méjì sí ọ̀sẹ̀ mẹta tí ènìyàn bá ṣe aláàbápàdé kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn náà, pẹ̀lú ibà, ọ̀fun dídùn, ìrora nínú iṣan ara, àti orí fífọ́. Gẹ́gẹ́ bí ó ti má a nwáyé, inú ríru, èébì, àti ìgbẹ́ gbuuru a má a tẹ̀lẹ́ èyí, pẹ̀lú àìṣedéédé iṣẹ́ ẹ̀dọ̀ àti àwọn kídìnrín. Lásìkò yìí, àwọn ènìyàn kan a má a bẹ̀rẹ̀ sí ní ìṣòro ẹ̀jẹ̀ sísun.
Ascariasis Ascariasis jẹ́ àrùn tí kòkòrò ajọ̀fẹ́ tí a npé ní aràn alára rógódó "Ascaris lumbricoides" nṣe òkùnfà rẹ̀. Àkóràn àrùn náà kò ní ààmì àìsàn kankan lára marundinlaadọrun nínú ọgọrun (85%) àwọn ènìyàn tó ti ní àrùn náà, pàápàá bí iye àwọn aràn náà bá kèrè. Àwọn ààmì àìsàn a má a pọ̀ síi pẹ̀lú iye aràn tó wà lára, lára irú àwọn ààmì bẹ́ẹ̀ sì ni àìlèmíkanlẹ̀ àti ibà ní ìbẹ̀rẹ̀ àìsàn náà. Àwọn ààmì àìsàn bíi inú wíwú, inú rírun àti ìgbẹ́ gbuuru lè tẹ̀lé èyí. Àwọn ọmọdé ni ó má a nsábà ní àkóràn àrùn náà, láàárín àwọn ọmọdé bẹ́ẹ̀, àkóràn àrùn náà tún lè ṣe òkùnfa àìlẹ́ranlára, àìtó èròjà oúnjẹ lára àti àwọn ìṣòro nípa ẹ̀kọ́-kíkọ́.
Hepataitisi A Hepataitisi A (tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí àjàkálẹ̀ hepataitisi) jẹ́ àjàkálẹ̀ àrùn kan tó jẹ́ ara àwọn àìsàn-kẹ̀kẹ̀ tó máa n bá ẹ̀dọ̀ jà èyí tí kòkòrò-àrùn hepataitisi A {HAV} máa n tàn kálẹ̀. Ọ̀pọ̀ ìgbà ni àìsàn yìí máa n farahàn fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ tàbí kí ó má tilẹ̀ farahàn rárá pàápàá júlọ̀ lára àwọn ọ̀dọ̀. Láàrin ìgbà tí ẹnìkan kó àìsàn náà sí àkókò tí yóò farahàn máa n tó bí i ọ̀ṣ̀ẹ̀ méjì sí mẹ́fà . Fífarahàn àìsàn náà máa n sáábà gbà tó ọ̀ṣẹ̀ mẹ́jọ, tí ó sì máa n wá pẹ̀lú ọkàn-rínrìn, èèbì, ìgbẹ̀-gbuuru, awọ-ara bí-àyìnrín,ibà àti inú rírun. Ìmọ̀lára-àìsàn yìí máa n wá lemọ́lemọ́ lára bí i ìdá mẹ́wàá sí mẹ́ẹ̀dógún ninu ọgọ́rùn ún ènìyàn láàrin oṣù mẹ́fà lẹ́hìn tí àìsàn náà bá ti kọ́kọ́ kọluni. Àìsàn-kẹ̀kẹ̀ tí-n-mú-ẹ̀dọ̀ ṣíwọ́-iṣẹ́ kí í sáábà bá ìmọ̀lára yìí rìn nítorí tí ó wọ́pọ̀ júlọ láàrin àwọn àgbàlagbà.