Top 10 similar words or synonyms for gbéra

crack    0.986277

vir    0.984992

havas    0.984574

kúro    0.984101

broom    0.984014

esti    0.983762

àjèjì    0.983731

adverbo    0.983722

    0.983617

bona    0.983303

Top 30 analogous words or synonyms for gbéra

Article Example
Sẹ́ríkí ń góómà Ṣe ló fẹ́ gbéra rẹ̀ sí kòtò
Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): A Agile: adj; (The boy is very agile.) Yára; gbéra kánkán Omokùrin náà yára dáadáa
Ìsèdálẹ̀ Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà Ìtàn míràn bí a ṣe tẹ Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà dò àti bí a ṣe mọ̀ ọ́n tàbí sọ orúkọ rẹ̀ ní Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ni ìtàn àwọn akíkanjú tàbí akọni ọdẹ méje tí wọ́n gbéra láti Ifẹ láti ṣe ọdẹ lọ. Wọ́n ṣe ọdẹ títí ìgbá tí wọ́n dé ibi kan, olórí wọ́n fi ara pa. Wọ́n bẹ̀rẹ̀sí í tọ́júu rẹ̀ ìgbà tí wọ́n ṣe àkíyèsí wí pé ọgbẹ́ náà san díẹ̀, wọ́n tún gbéra, wọ́n mú ọ̀nà-àjò wọn pọ̀n. Ìgà tí wọ́n dé ibi tí a ń pè ní Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà lónìí yìí ni ẹ̀jẹ̀ bá tún bẹ̀rẹ̀sí í sàn jáde láti ojú ọgbẹ́ ọkùnrin náà. Wọ́n bá dúró níbẹ̀ làti máa tọ́jú egbò náà, wọ́n sì dúró pẹ́ díẹ̀. Nígbẹ̀hìn, wón fi olórí wọ́n yìí síbẹ̀, wọ́n pa àgó kan síbẹ̀ kí ó máa gbé e. Ìgbà tí àwọn náà bá ṣọdẹ lọ títí, wọn a tún padà sọ́dọ̀ olórí wọn yìí láti wá tójùu rẹ̀ àti láti wá simi lálẹ́. Wọ́n ṣe àkíyèsí pé ibẹ̀ náà dára láti máa gbé ni wọ́n bá kúkú sọbẹ̀ dilẹ̣́. Ìgbà tí ara olórí wọn yá tán, tí wọ́n bá ṣọdẹ lọ títí, ibẹ̀ ni wọ́n ń fàbọ̀ sí títí tí ó fi ń gbòrò sí i. Orúkọ tí Olórí wọn – Agígírí sọ ibẹ̀ ni ÌJẸ̀BÚ nítorí pe ÌJẸ ni Ìjẹ̀ṣà máa ń pe Ẹ̀JẸ́. Nígbà tí ìyípadà sì ń dé tí ojú ń là á sí i ni wọ́n sọ orúkọ ìlú da ÌJẸ̀BÚ dípò Ìjẹ́bú tí wọ́n ti ń pè é tẹ́lẹ̀. Agígírì yí ni Ọba Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà kiíní, àwọn ìran ọlọ́dẹ méje ìjọ́sí ló di ìdílé méje tí ń jọ́ba Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà títí di òní.
Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà Ìtàn míràn bí a ṣe tẹ Ijẹ̀bù-Jẹ̀ṣà dò àti bí a ṣe mọ̀ ọ́n tàbí sọ orúkọ rẹ̀ ní Ìjẹ̀bí-Jẹ̀ṣà ni ìtàn àwọn akíkanjú tàbí akọni ọdẹ méje tí wọ́n gbéra láti Ifẹ láti ṣe ọdẹ lọ. Wọ́n ṣe ọdẹ títí ìgbà tí wón dé ibi kan, olórí wọ́n fi ara pa. Wọ́n pẹ̀rẹ̀sì í tọ́júu rẹ̀ ìgbà tí wọ́n ṣe àkíyèsí wí pé ọgbẹ́ náà san díẹ̀, wọ́n tún gbéra, wọ́n mù ọ̀nà-àjò wọn pọ̀n Igbà tí wọ́n dé ibi tí a ń pè ní Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà lónìí yìí ni ẹ̀jẹ̀ bá tún bẹ̀rẹ̀sí í sàn jáde láti ojú ọgbẹ́ ọkùnrin náà. Wọ́n bá dúró níbẹ̀ láti máa tọ́jú ogbà náà, wọ́n sì dúró pẹ́ dìẹ̀. Nígbẹ̀hìn, wọ́n fi olórí wọ́n yìí síbẹ̀, wọ́n pa àgó kan síbẹ̀ kí ó máa gbé e. Ìgbà tí àwọn náà bá ṣọdẹ lọ títí, wọn a tún padà sọ́dọ̀ olórí wọn yìí láti wá tójùu rẹ̀ àti láti wá simi lálẹ́. Wọ́n ṣe àkíyèsí pé ìbẹ̀ náà dára láti máa gbé ni wọ́n bá kúkú sọbẹ̀ dilé. Ìgbà tí ara olórí wọn yá tán, tí wọ́n bá ṣọdẹ lọ títí, ibẹ̀ ni wọ́n ń fàbọ̀ sí títí tí ó fi ń gbòrò sí i. Orúkọ tí Olórí wọn –Agígírì sọ ibẹ̀ ni IJẸLÚ nítorí pe ÌJẸ̀ ni Ìjẹ̀sà máa ń pe Ẹ̀JẸ̀. Nigbà tí ìyípadà sì ń dé tí ojú ń là á sí i ni wọ́n sọ orúkọ ìlú da ÌJẸ̀BÚ dípò Ìjẹ̀bú tí wọ́n ti ń pè tẹ́lẹ̀. Agígírì yí ni Ọba Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà kiíní, àwọn ìran ọlọ́dẹ méje ìjọ́sí ló di ìdílé méje tí ń jọ́ba Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà títí di òní.
Ìsèdálẹ̀ Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà Nípa pé tẹ̀gbọ́n tàbúrò ni Ọwá Iléṣà àti Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà jẹ́ láti àárọ̀ ọjọ́ wà yìí, sọ wọ́n di kòrí – kòsùn ara wọn. Wọ́n sọ ọ́ di nǹkan ìnira làti ya ara kódà, igbín àti ìkarahun ni wọ́n jẹ́ sí ara wọn. Ṣé bí ìgbín bá sì fà ìkarahun rẹ̀ a tẹ̀ lé e ni a máa ń gbọ́. Ìgbà tí ó di wí pé àwọn tẹ̀gbọ́n tàbúrò yí máa fi Ifẹ́ sílẹ̀, ìgbà kan náà ni wọ́n gbéra kúrò lọ́hùnún, apá ibì ken náà ni wọ́n sì gbà lọ láti lọ tẹ̀dó sí. Ọ̀rọ̀ wọn náà wà di ti a já tí kì í lọ kí korokoro rẹ̀ gbélẹ̀. Ibi tí a bá ti rí ẹ̀gbọ́n ni a ó ti rí abúrò. Àjọṣe ti ó wà láàárín wọ́n pọ̀ gan-an tí ó fi jẹ́ wí pé ní gbogbo ilẹ̀ Ijẹ̀ṣà, Ọba Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà àti Ọwá Iléṣà jọ ní àwọn nǹkan kan lápapọ̀ bẹ́ẹ̀ náà si ni àwọn ènìyàn wọn.
Tẹ́lískópù Òfurufú Hubble Àwọn ìránlọṣe OSO àti OAO fihàn bí àwọn àkíyèsí ibùdó òfurufú ṣe ṣe pàtàkì sí nínú ìtòràwọ̀, bó sì ṣe di 1968, NASA ṣàgbédìde àwọn ètò gidi fún tẹ́lískópù alátànpadà pẹ̀lú jígí tí ìdákọjá rẹ̀ jẹ́ 3 m, tó jẹ́ mímọ̀ nígbà náà bíi Large Orbiting Telescope tàbí Large Space Telescope (LST), tí yíò gbéra ní 1979. Awon eto yi tenumo bi o se se pataki fun awon iranlose itoju pelu awon eniyan lo si teliskopu na lati ri pe iru eto alewo na ni emi ojo pipe, besini igbedide lasiko kanna eto fun and the concurrent development of plans for the reusable oko alobo alatunmulo fihan pe oroiseona ti yio gba eyi laye ko ni pe waye.
Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà Nipa pé tẹ̀gbọ́n tàbúrò ni Ọwá Iléṣà àti Ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà jẹ́ láti àárọ̀ ojọ́ wà yìí, sọ wọ́n di kòrí – kòsùn ara wọn. Wọ́n sọ ọ́ di nǹkan ìnira làti ya ara kódà, igbín àti ìkarahun ni wọ́n jẹ́ sí ara wọn. Ṣé bí ìgbín bá sì fà ìkarahun rẹ̀ a sẹ̀ lé e ni a máa ń gbọ́. Ìgbà tí ó di wí pé àwọn tẹ̀gbọ́n tàbúrò yí máa fi Ifẹ́ sílẹ̀, ìgbà kan náà ni wọ́n gbéra kúrò lọ́hùnún, apá ibì kan náà ni wọ́n sì gbà lọ láti lọ tẹ̀dó sí. Ọ̀rọ̀ wọn náà wà di ti ajá tí kì í lọ kí korokoro rẹ̀ gbélẹ̀. Ibi tí a bá ti rí ẹ̀gbọ́n ni a ó ti rí abúrò. Àjọṣe ti ó wà láàárìn wọ́n pọ̀ gan-an tí ó fi jẹ́ wí pé ní gbogbo ìlẹ̀ Ijẹ̀ṣà, Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà àti Ọwá Iléṣà jọ ní àwọn nǹkán kan lápapọ̀ bẹ́ẹ̀ náà si ni àwọn ènìyàn wọn.
Apiiri Eré àpíìrì jẹ́ ohun tí ó ní orin, ìlù àti ijó nínú. Gẹ́gẹ́ bí ìwádìí, erée pelebe ni ó di àpíìrì níwọ̀n ìrínwó ọdún sẹ́hìn. Ìjerò-Èkìtì ni eré àpíìrì yìí ti bẹ̀rẹ̀. Ìtàn fi yé wa pé wọn mọ̀ ọ́n fúnra wọn ni, kì í ṣe wí pé wọ́n mú un wá láti Ilé-Ifẹ̀ tí ó jẹ́ orírun Yorùbá. Eré yìí bẹ̀rẹ̀ ní àkókó tí àwọn ará Ìjerò mú Alákeji jọba dípò ẹ̀gbọ́n rẹ̀ tí ó jẹ́ ọba. Ìtàn fi yé wa pé nígbà tí ogun àti ọ̀tẹ̀ yí ìlú Ìjerò ká, ẹ̀gbọ́n Alákeji tí ó jẹ́ ọba wá gbéra láti lọ wá ọ̀nà tí wọn yíò fi ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá tí ó yí wọn ká. Nígbà tí àwọn ará ìlú kò tètè rí i, wọ́n gbèrò láti fi àbúrò rẹ̀ Alákeji jọba. Nígbà tí ẹ̀gbọ́n Alájeji wá padà, ó rí i pé wọ́n ti mú àbúrò òun jọba. Ó ka gbogbo ètùtù tí wọ́n ní kí ará ìlú ṣe láti lè ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá tí ó yí wọn káàkiri. Ìtàn yìí náà ni ó fi yé wa pé kò torí èyí bínú kúrò ní ìlú. Ó sọ fún àwọn ará ìlú pé kí wọn máa ṣe eégún fún òun lákòókò ọdún Ògún fún ìrántí òun, kí wọn sì máa ṣeré àpíìrì tí egúngún yìí bá jáde. Lẹ́hìn èyí ni eré àpíìrì ti bẹ́rẹ̀ ní ìlú Ìjerò-Èkìtì.
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà Ìtàn kìíní sọ fún wa pé ìlú Ìlayè ni wọ́n tí gbé e wá sí Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà. Ìlú Ìlayè yí ti wà lásìkò kan ní ayé àtijọ́ ṣùgbọ́n ìwádìí fi hàn wá pé kò sí i mọ́ lóde òní. Ìtàn sọ pé Ọba Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà jẹ́ jagunjagun didi tí ó lágbára púpọ̀. Ó jà títí ó lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ kan dé ìlú Ìlayè, ṣùgọ́n kí ó tó dé ìlú yìí, àwọn ọ̀tá rẹ̀ ti ránsẹ́ sí àwọn ènìyàn wọn ní ìlú tiwọn pé ki wọn wá pàdé wọn láti fi agbára kún agbára fún wọn nítorí pé ìdè ń ta wọ́n lápá. Báyìí ni àwọn ènìyàn ọ̀tá Ọba Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà gbéra láti wà gbèjà Ọba wọn. Ìlù Ìlayè yí ni wọ́n ti pàdé Ọba ọ̀tá Ọba Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà, ogún sì wá gbónà janjan. Nítorí pé agbára ti kún agbára Ọba ọ̀tá Ọba Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà yí, ó wá dàbí ọwọ́ fẹ́ tẹ Ọba Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà àti àwọn ènìyàn rẹ̀ ni òun náà bá sá tọ Ọba Ìlú Ìlayè lọ fún ìrànlọ́wọ́. Lọ́gán ni onítọ̀hún náà fún Ọba Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà ní òrìṣà kan nínú òrìṣà wọn tí ó lágbára gidi láti gbèjà Ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà. Ó si sẹ́gun ọ̀tà rẹ̀. Bayìí ni Ọba Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ṣe bèèrè fún òrìṣà yí ó sì tọrọ rẹ̀ láti gbé e wá sí ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà nítorí pé ó ti ran án lọ́wọ́ lọ́pọ̀: ṣe òrìṣà tí ó bá san ni là ń sìn. Ṣùgbọ́n Ọba yìí kò gbé e fún un, Ìlú rẹ̀ tí ń jẹ́ ÀGÀDÁ ló gbé fún un láti máa gbé lọ ní rántí òrìṣà olùgbèjà yí. Ìgbà tí ọba Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà dé ìlú rẹ̀ ni ó bá kọ́lè kan fún ìránti òrìṣà yí ó sì fi Ọkùnrin kan tì í pé kí ó màa bá òun rántí òrìṣà náà pé òun yóò sì wá máa fún un ní ewúrẹ́ kọ̀ọ̀kan lọ́dọọdún fún ìrántí oore tí ó ṣe fún wọn. Báyìí ni ó ṣe di ọdún Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà títí di òní, ìgbàkugbà tí wọ́n bá sì fẹ́ rántí rẹ̀ tàbí bọ ọ́, ìlú Àgàdá yìí ni wọ́n máa ń lù fún un, ilù ogun sì ni ìlù náà. Láti ọjọ́ náà tí ogun kan bá wọ ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà, ìlú náà ni wọ́n máa ń lù, tí wọ́n bá sì ti ń lù ú, gbogbo ọmọ -ogun ìlú ni yóò máa fi gbogbo agbára wọn jà nítorí pé orí wọn yóò máa yá, agbára sì túnbọ̀ máa kún agbára fún wọn.