Top 10 similar words or synonyms for fifun

nya    0.992921

oloko    0.992792

imu    0.992430

mosalasi    0.991963

nbo    0.991939

bale    0.991620

yara    0.991419

abajade    0.991176

rorun    0.990847

tire    0.990815

Top 30 analogous words or synonyms for fifun

Article Example
Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): D double:n; (He gets paid double for doing the same job I do.) ìoópo meji o n gba ìlópo owó mi fifun sise iye isé tí mo n se.
ISO 3166-2:NG Lowolowo, agbegbe 1 ati ipinle 36 ni won je fifun ni amioro. Amioro kookan bere pelu NG-, titele pelu leta meji.
Kalulu M’Hali je bibi ni Afrika o si di alayanfe Henry Morton Stanley leyin ti won fifun ni Tabora ni Tanzania. Stanley fun ni ominira o si yi oruko re si Kalulu. Oruko re tele ni "Ndugu M’Hali" to tumosi "Arakunrin ore mi". Stanley pe ni Kalulu nitori pe o ro pe o tumoso ọmọ ẹtù sugbon awon miran ti so pe o je "ehoro."
Anafilasisi [[Efinifrini]] (adrenaline) jẹ ọna itoju akọkọ fun anafilasisi laisi [[ewu ti o gba ẹmi kankan]] lati lòó. A gba ni niyanju ki a fun ni ni efinifirini olomi [[lati inu iṣan]] si inu itan ni kete ti a ba kiyesi ayẹwo. Bi ko ba si abajade ti o dara to, a tun le tun abẹrẹ naa fun ni ni gbogbo iṣẹju 5 si 15 si ara wọn. A nilo fifun ni ẹlẹẹkeji ninu 16 si 35% awọn iṣẹlẹ ninu eyiti fifun kọja eemeji kii saba nilo. Ọna lilo ti a ngba fun ni nipasẹ iṣan jẹ eyiti a yan ṣaaju [[ọra abẹ́ awọ]] nitori ti eyiti ti o keyin le ma tete ṣee fa sinu ara. Awọn nkan ti ko dara diẹ nipa lilo efinifirini ni ninu [[gbigbọn]], [[aibalẹ ọkan]], efọri, ati [[iro ọkan ti ko ṣe deede]].
Anafilasisi Bi o ba nilo, a tun le fun ni ni [[Ọna abojuto nipa fifi nkan sinu iṣan| fifi nkan sinu iṣan]] nipa lilo efinifirini olomi ti a ti là. Ṣugbọn a ti ri asopọ mọ [[Cardiac dysrhythmia|dysrhythmia]] ati [[myocardial infarction]]ninu efinifirini ti a fun ni nipasẹ iṣan. [[Abẹrẹ to nfun ni ni efinifirini fun ra rẹ]]ti a nlo fun fifun ara ẹni ni abẹrẹ ni eemeji, ọkan fun awọn agbalagba tabi ọmọde ti iwọn wọn kọja 25 kg ati ọkan fun awọn ọmọde ti iwọn wọn to 10 si 25 kg.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Kiko àìsàn hepatitis C lati ara iya si ara omo ko to ida mewaa ninu ogorun un lara àwọn ti wọn loyun. Kò si odiwọn kankan ti o yi ewu yii pada. Kiko àìsàn le sele ni akoko oyun tàbí ni akoko ibimo. Irobi ti o gun maa n saaba fa ewu kiko àìsàn naa. Ko si eri kankan pe fifun-omo-ni-ọyàn maa n tan àìsàn HCV kale; sibe, ki iya naa ti o ni àìsàn yii ma se fun ọmọ ni ọyàn mu ti ori ọyàn re ba la tàbí ti o ba n se ẹ̀jẹ, tàbí ti kokoro-àìsàn ba pọ lara re.
Kúrùpù Kúrùpù (tabi laringotrakiobronkaitis) jẹ arun nipa mimi ti o lewu gan-an ti o maa nwaye nipa aisan ọ̀nà-atẹgun oke. Arun yii maa nfa wiwu ninu ọ̀nàfun. Wiwu yii maa nfa idiwọ fun mimi deede; awọn aami aisan Kúrùpù ni ikọ́ "gbígbó", idiwọ ọnafun (mimi ti o ngbọn ti ìró rẹ lọ soke), ati ohùn kíkẹ̀. Awọn aami aisan kúrùpù le ma nira, mọ niwọnba, tabi lewu, ti o si le nira ni òru. Fifun ni oògùn sitẹriodu lẹẹkan lati ẹnu le ṣe abojuto arun naa. Nigba miiran epinifini ni a maa nlo fun awọn iṣẹlẹ ti o lewu gan-an. Kii saba nilo ki a da ni duro ni ile-iwosan.
Anafilasisi Awọn eniyan ti o le tete ni anafilasisi ni agba ni imọran lati ni "eto iṣẹ fun nkan ti ara korira si", awọn obi ni agba ni imọran lati fi to awọn ile-iwe awọn ọmọ wọn leti nipa ikọrira ara ati awọn nkan ti o ye ki wọn ṣe bi pajawiri anafilatiki ba ṣẹlẹ. Eto iṣẹ maa nni ninu lilo [[fifun ara ẹni ni abẹrẹ efinifirini]], igbani niyanju lati wọ [[ẹ̀gbà-ọwọ́ itaniji to niiṣe pẹlu iṣegun oyinbo]] kan, ati imọran lati yẹra fun awọn ohun ti o nṣe okunfa. [[Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni lati ṣe bojuto Nkan ti ara korira| Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni]] wa fun awọn ohun ti o nṣe okunfa lati dena anafilasisi ọjọ iwaju. Ẹkọ onilọpọ ọdun nipa didinku tabi mimu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan ninu ọra ni ati ri wipe o munadoko lodi si awọn kokoro ti njẹ ni nigbati dinku tabi mimu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan lati ẹnu munadoko fun ọpọlọpọ ounjẹ.
Òfin Òfin je sistemu awon ilana kan, to se gbe ro nipa ikojopo awon ifidimule kan. O un tona iselu, ekonomiki ati awujo lorisirisi ona, o si je olulaja akoko lawujo fun ibasepo larin awon eniyan. Ofin adehun un setona ohun gbogbo latori rira tiketi oko de idunadura ni ile pasiparo. Ofin Ohun ini n setoka awon eto ati ojuse to jemo fifun ati nini ohun ini araeni (ti a n pe ni ẹrù) ati ohun ini gidi (bi ile ti ko se mu kuro). Ofin igbalawin je mo dukiya ti a fi pamo fun idaabo inawolori ati oninawo, nigbati ofin ibaje gbani laaye lati gba esan atunse ti eto tabi ohun ini eniyan ba bibaje lowo elomiran. Ti ibaje yi ba je sisododaran ninu iwe ofin, ofin odaran ni yio so bi ijoba yio se fi esun kan iru eni be. Ofin ibagbepapo un pese ona dida ofin, idaabo bo awon eto omoniyan ati idiboyan awon asoju oloselu. Ofin amojuto lo n sagbeyewo awon ipinu awon ile-ise ijoba, nigbati ofin akariaye un dari ìṣe larin awon orile-ede lati tona idunadura, ayika tabi imuse ologun. Ninu iwe to ko ni 350 kJ, Aristotle amoye ara Griisi so pe, "Ona to bofin mu dara ju ona enikeni lo."
Àìjẹ̀un-dáradára Ipa lati mu gbooro ounjẹ jẹ lara awọn ipo ti o ya iranwọ idagba. Ifun lọmu le din iye aijẹ ounjẹ to ati iku ninu awọn ọmọde ku, ati awọn ipa lati mu gberu iṣe bẹẹ dagba pọ. Ninu awọn ọmọde pipese ounjẹ pẹlu ọmu-mimu laarin oṣu mẹfa ati ọdun meji mu abajade gberu. Ẹri gidi wa ti o kin lẹhin pe eroja ounjẹ ti ọpọ awọn eroja ounjẹ lakoko oyun ati laarin awọn ọmọde ni awọn orilẹ-ede ti o n dagba. Lati pese ounjẹ fun awọn ti o nilo rẹ ju ni ipese ounjẹ ati ipese owo ki awọn eniyan le ra ounjẹ laarin ọja ilu lọ geere. Fifun awọn eniyan lounjẹ nikan to. Ibojuto aijẹ ounjẹ t'oyẹ ti o l'ewu laarin ile eniyan pẹlu àwọn ounjẹ ìlo iwosan aarun ṣeeṣe lọpọ igba. Laarin awọn ti o ni ewu aije ounjẹ toyẹ lowọ awọn iṣoro itọju ilera miiran laarin ile-iwosan ni a bọwọlu. Eyi nilo abojuto aito ṣuga, imọlara ara, ara-gbigbẹ, ati ifun-lounjẹ diẹdiẹ. Igbesẹ awọn ogun aṣodi si akoran ni a bọwọlu nitori akoran ti o pọ. Awọn ilana itọju ọjọ pipẹ ni: imugbooro awọn iṣe agbẹ, re dioṣi kuim, imumọtoto gbooroth, atiofifun awọn obinrin ni agbara iṣẹ