Top 10 similar words or synonyms for fairọsi

afijuwe    0.996682

niyi    0.996146

gbagbo    0.995756

pese    0.995566

tire    0.995450

bakiteria    0.995414

eniti    0.995380

yara    0.995199

ese    0.994904

nwaye    0.994823

Top 30 analogous words or synonyms for fairọsi

Article Example
Kúrùpù Ninu ida marundinlọgọrin (75%) iṣẹlẹ parainfluensa fairọsi, oriṣi 1 ati 2, ni fairọsi ti o nfa kúrùpù/laringotrakiatisi ti o lewu gan-an. Awọn fairọsi miiran ti o le fa kúrùpù ni influenza A ati B, measles, adenofairọsi ati respiratory syncytial virus (RSV). Kúrùpù ti o ṣẹlẹ logiji fun igba diẹ (kúrùpù ti o ni gbígbó) maa nwaye nitori iru ẹgbẹ fairọsi kanna bii ti o lewu gan-an laryngotracheitis, ṣugbọn kii saba ni awọn aami arun ti o wọpọ (bii iba, ọ̀nà-ọfun ti o ndun ni, ati sẹẹli ẹjẹ funfun ti o lọ silẹ) ninu. Abojuto, ati idahun si abojuto naa tun jọra.
Kúrùpù Fairọsi le fa kúrùpù. Awọn eniyan kan lo ọrọ naa lati ni ninularingotrakiaitisiti o lewu, kúrùpù ti o ṣẹlẹ logiji fun igba diẹ, laringeal diphtheria, trakiatisi ti bakiteriali fa, laringotrakiobronkaitisi, ati laringotrakiaobronkoneumonitisi. Ipo meji akọkọ ni ninu fairọsi kan ti o si ni aami aisan ti ko nira; awọn mẹrin ti o kẹyin maa nwaye lati ọwọ bakiteria wọn si maa nlewu gan-an.
Kúrùpù Arun fairọsi maa nwo inu awọn sẹẹli ẹjẹ funfun ti o si ma nfa wiwu larynx, trachea, ati ẹ̀dọ̀-f ọ́ọ́rọ́ nla (ọ̀nà-atẹgun ). Wiwu le jẹ ki mi i ki o nira.
Kúrùpù Ọrọ naa "kúrùpù" wa lati ọrọ-ìṣe "croup," Ede Gẹẹsi Igbalode ti ati ibẹrẹ ti o tumọ si "lati sọkun pẹlu ohùn kíkẹ̀"; akọkọ lo orukọ naa fun aisan naa ni orile-ede Sikotilandi ti o si wa gbajumọ ni ẹgbẹrun ọdun kejidinlọgun (18th century). A ti mọ kúrùpù diphtheritic lati igba Homer Giriki Atijọ. Ni ọdun 1826, Bretonneau da mọ yatọ kúrùpù ti fairọsi fa ati kúrùpù ti o waye lati ọwọ diphtheria. Awọn Faranse npe kúrùpù ti fairọsi fa ni "faux-croup," nipa lilo "kúrùpù" fun arun ti bakiteria diphtheria fa. Kúrùpù ti diphtheria fa ni o fẹẹ jẹ wipe a ko mọ nitori imunadoko abẹrẹ ajẹsara.
Kúrùpù Kúrùpù ti o niiṣẹ pẹlu fairọsi jẹ lọpọ igba self-limited arun (fun saa diẹ); kúrùpù kii saba fa iku lati owo ikuna mimi ati/tabicardiac arrest. Awọn aami aisan maa nsaba ngberu laarin ọjọ  meji, ṣugbọn eyi le wa fun bii ọjọn meji. Awọn ewu miiran ti ko wọpọ ni ninu bacterial tracheitis, pneumonia, ati pulmonary edema.
Kúrùpù Kúrùpù ti o niiṣe pẹlu bakiteria ṣee pin si laryngeal diphtheria, bacterial tracheitis, laryngotracheobronchitis, ati laringotrakiobronkopneumonitisi. Laringeal diphtheria maa nwaye nitori "Corynebacterium diphtheriae" nigbati bakiteria trakitisi, laringotrackiobronkaitisi, ati laringotrakobronkopneumonitisi maa nwaye nitori fairọsi, pẹlu bakiteria ti o lọwọ sii. Awọn bakiteria ti o wọpọ julọ ni"Staphylococcus aureus", "Streptococcus pneumoniae", "Hemophilus influenzae", ati "Moraxella catarrhalis".
Kúrùpù Awọn Ayẹwo ẹjẹ ati viral culture (awọn ayẹwo fairọsi) le fa irira ti ko nilo fun oju-ọ̀nà atẹgun. Nigbati awọn viral mimu kokoro dagba nipa amu nkan dagba ni yara iwadi, ti a gba nipase ilepa nasopharyngeal (ọ̀nà kan ti a nlo rọba ti o ni alafo ninu lati fa ikun imu jade ninu imu), ṣee lo lati jẹrisi ni pato ohun ti o ṣe okunfa. A maa ndekun lilo awọn mimu kokoro dagba nipa amu nkan dagba ni yara iwadi yii l’ọpọ igba fun awọn eto iṣẹ iwadi. Bi nkan ko ba gberu pẹlu abojuto ti o kun oju oṣunwọn, a le ṣe awọn ayẹwo siwaju sii lati ṣayẹwo fun bakiteria.
Kúrùpù A ti ṣe iwadi fun awọn abojuto miiran fun kúrùpù, ṣugbọn ko ti si ẹri ti o to lati ṣe atilẹyin fun lilo wọn. Mimi ikuuku gbigbona simu tabi atẹgun jẹ ọ̀nà atọwọdọwọ lati ṣe abojuto ṣe abojuto ara-ẹni, ṣugbọn awọn ẹkọ iwadi iṣegun oyinbo kuna lati fi mumunadoko mulẹ ati lọwọlọwọ a kii saba lo o. Lilo awọn oogun ikọ́, eyi ti o maa ni dextromethorphan ninu ati/tabi guiafenesin, ni a ko gba ni niyanju lati lo. Nigbati fifa heliox simu (idapọ helium ati oxygen) lati din iṣẹ mimi ku ni a ti lo ni atẹyin wa, ṣugbọn ẹri ti o kere jọjọ lo wa lati ṣe atilẹyin fun lilo rẹ. Nitori kúrùpù lọpọ igba jẹ arun ti fairọsi nfa,awọn oogun apakokoro ni a kii lo a fi bi a ba fura si bakiteria. Apakokoro vancomycin ati cefotaxime ni a gba ni niyanju fun awọn arun bakiteria. Ni awọn iṣẹlẹ ti o lewu ti o rọ mọ ọfinki A tabi B, agbogun ti fairọsi neuraminidase inhibitors ṣee lo.
Streptococcal pharyngitis Awọn aami aisan ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa fi ara jọ awọn aami aisan miiran. Fun idi eyi, mimọ ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri mọ lai lo nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun tabi ayẹwo kokoro to nfa ni kankan le soro. Ikọ́ wiwu, fi fun ikun-imu, igbẹ-ọrin ati oju pipọn ti o nta ni ni afikun pẹlu ibà ati ọna-ọfun to ndun ni le fẹẹ jẹ ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri ti fairọsi (virus)fa ju ki o jẹ ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa lọ.
Streptococcal pharyngitis ọna-ọfun to ndun ni(tabi faringitisi), iṣori ti o gbòòrò ninu eyiti ti ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri wa, ni a ṣe awari rẹ ninu awọn eniyan milliọnu mọkanla (11 million) l’ọdọọdun ni orilẹ-ede Amẹrika. Fairọsi ni o ma nfa ọpọlọpọ iṣẹlẹ ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa. Ṣugbọn, ẹgbẹ bakiteria ti kokoro ti a ko f’oju ri ti bita A (group A beta-hemolytic streptococcus)maa nfa ninu ọgọrun ida 15 si 30 ọfun ti o ndun ni laarin awọn ọmọde ati 5 si 20 laarin awọn agbalagba. Awọn iṣẹlẹ maa nsaba waye nigba ti jijabọ yinyin baa nkasẹ nlẹ ti Ợrinrin (Spring)si ṣẹṣẹ nbẹrẹ.