Top 10 similar words or synonyms for ewadun

NotFoundError    0.789

Top 30 analogous words or synonyms for ewadun

Article Example
Jean-Michel Basquiat Jean-Michel Basquiat (December 22, 1960 – August 12, 1988) je onisona ara Amerika. O bere bi onisona grafiti ni New York City ni opin ewadun 1970, o si se ni ewadun 1980 aworan kikun Alafarahan-tuntun. Basquiat ku nitori ilokulo heroini ni August 12, 1988, nigba to je omo odun 27.
Martha Karua Lẹyìn o wà laarin awon ti o akoso awọn oselu Iṣọkan NARC ti o gba 2003 Gbogbogbo idibo ni Kenya o si pari Kanu ká fere merin ewadun ti olori ni Kenya ká iselu .
Etta James Etta James (oruko abiso Jamesetta Hawkins, Oṣù Kínní 25, 1938 - Oṣù Kínní 20, 2012) je akorin blues, soul, R&B, rock & roll, gospel ati jazz ara Amerika. Eni to bere ise orin kiko larin ewadun 1950, o gbajumo pelu orin bi "Dance With Me, Henry", "At Last", "Tell Mama", ati "I'd Rather Go Blind", awon eyi to ko fun ra re. O koju orisirisi isoro, larin eyi ti se lilo ogun oloro, ko to tun gbe awo rin miran jade ni opin ewadun 1980 pelu awo orin "The seven year Itch".
Harry Belafonte Harold George "Harry" Belafonte, Jr. (ojoibi March 1, 1927) je akorin, osere ati ati alakitiyan awujo ara Amerika. O je pipe bi "Oba Orin Calypso" fun imugbajumo iru orin Caribbean kakiri aye ni ewadun 1950. Belafonte gbajumo fun kiko orin "The Banana Boat Song", pelu igbe-orin "Day-O." Kakiri ise re o je agbejero fun eto araalu ati ija omoniyan.
Gàbọ̀n Lati igba ilominira latowo Fransi ni August 17, 1960, awon aare meta loti joba ni Gabon. Ni arin ewadun 1990, Gabon bere sistemu egbe oloselu pupo ati isepo oloselu tuntun to fi aye gba igbese aladiboyan kedere to si satunse opo awon ise ijoba. Gabon ti je omo-egbe alaije tigba gbogbo ni Igbimo Abo UN fun igba 2010-2011.
Teddy Pendergrass Theodore DeReese "Teddy" Pendergrass, Sr. (March 26, 1950 – January 13, 2010) je akorin R&B/soul ara Amerika. Pendergrass koko gbajumo gege bi akorin asiwaju egbe olorin Harold Melvin & the Blue Notes ninu awon odun 1970 koto bere sini da korin nipari ewadun na. Ni odun 1982 o ni ipalara gidi leyin ijamba oko ni Philadelphia eyi fa iyaro re lati ibadi de sale.
Patti LaBelle Patricia Louise Holte-Edwards (ojoibi May 24, 1944), to gbajumo pelu oruko ori-itage, Patti LaBelle, je akorin to gba Ebun Grammy, olukowe ati osere to ti lo to 50 odun nidi orin. LaBelle lo odun 16 bi akorin asiwaju egbe Patti LaBelle and the Bluebelles, ti won yi oruko won si Labelle ni ibere ewadun 1970, ti won si gbe orin disco "Lady Marmalade" jade to si gbajumo titi di oni.
Donna Summer Donna Summer (oruko abiso LaDonna Adrian Gaines) (December 31, 1948 – May 17, 2012) je akorin ati akoweorin ara Amerika to gbajumo nigba asiko disco ni opin ewadun 1970s. O gba Ebun Grammy ni emarun, Summer je olorin akoko to ni awo-orin meta to de ipo kinni ni Amerika lori atojo "Billboard", be sini o tun ni orin merin ni ipo kinni larin osu 13.
Tẹ́lískópù Òfurufú Hubble Awon teliskopu ofurufu je dida laba lati odun 1923. Owo fun iko Hubble bere sini je kikojo ni ewadun 1970s, pelu ireti pe yio gbera ni 1983, sugbon o ku seyin nitori isoro isise, inawo ati ijamba "Challenger". Nigba to gbeyin gbera ni 1990, awon onimo sayensi ri pe jigi iwaju re ko duro daada, eyi fa ko mo sise boseye. Iranlose se atunse eyi ni 1993.
Chaka Khan Chaka Khan (oruko abiso Yvette Marie Stevens; ojoibi March 23, 1953) je akorin-olorin ara Amerika to gbajumo ni ewadun 1970 gegebi asiwaju fun egbe olorin to unko orin funk Rufus. Diedie Khan bere si ni da korin latin 1978. Ninu awon orin re togbajumo, to dako tabi pelu Rufus, ni "Tell Me Something Good", "Sweet Thing", "Ain't Nobody", "I'm Every Woman", "I Feel for You" ati "Through the Fire".