Top 10 similar words or synonyms for eseese

alawujo    0.998219

apartheid    0.997094

ogba    0.996758

itileyin    0.996667

aaye    0.995954

alaaye    0.995942

oludasile    0.995836

isotopu    0.995797

jeometri    0.995645

adogba    0.995562

Top 30 analogous words or synonyms for eseese

Article Example
Ìyára Ninu isiseirin, ìyára ohun kan je itobi ìsálọ rẹ̀ (iwon eseese iyipada ipo re); bi i be o je iposi arelẹ̀ròkè.
Ùráníọ̀m Ùráníọ̀m tabi Uranium je apilese kemika onide bi fadaka funfun ninu eseese aktinidi ti tabili igba to ni nomba atomu 92. O ni ami-idamo kemika U. Atomu uraniom kan ni 92 awon protoni 92 ati awon elektroni 92.
Olùsọdipúpọ̀ Ninu mathimatiki olùsọdipúpọ̀ (Coefficient) ni akopa alassodipupo ninu oro igbekaleoroexpression kan (tabi ninu eseese kan); lopo igba o le je nomba, sugbon bo ba se je ki i se ayipada inu igbekale na. Fun apere ninu
Bẹ́rkẹ́líọ̀m Bẹ́rkẹ́líọ̀m tabi Berkelium je apilese alasopapo to ni ami-idamo Bk ati nomba atomu 97. Gege bi apilese onide alagbararadio ninu eseese aktinidi, berkelium koko je sisopapo nipa didigbolu americium pelu awon igbonwo alpha (awon ioni helium), o si je sisoloruko fun Yunifasiti Kalifornia ni Berkeley. Berkelium ni apilese teyinuraniom karun to je sisopapo.
Kùríọ̀m Kùríọ̀m tabi Curium je apilese kemika alasopapo to ni ami-idamo Cm ati nomba atomu 96. Gege bi apilese teyinuraniom onide alagbararadio ti eseese aktinidi, kuriom nje mimuwaye nipa didigbolu plutonium pelu awon igbonwo alpha (awon ioni helium). O je sisoloruko fun Marie Skłodowska-Curie ati oko re Pierre.
ISO 639-1 ISO 639-1:2002, "Àwọn àmìọ̀rọ̀ fún ìṣojú àwọn orúkọ àwọn èdè Apá 1: àmìọ̀rọ̀ Alpha-2" ni apa kinni ISO 639 awon eseese opagun kariaye fun awon amioro ede. Apa kinni dalelori iforukosile awon amioro leta meji. Awon amioro leta meji 136 ni won je fiforukosile. Awon amioro ti won je fiforukosile je ti gbogbo awon ede agbaye koko.
Fẹ́rmíọ̀m Fẹ́rmíọ̀m tabi Fermium (, ) je apilese aladipapo pelu ami-idamo Fm ati nomba atomu 100. Gege bi apilese teyinuraniom onide alagbraradio giga ti eseese aktinidi, fermium nje dida nipa ddigbolu plutonium pelu awon neutroni o si je sisoloruko fun Enrico Fermi onimofisiyiki inuatomu. Fermium ni apilese teyinuraniom kejo.
Srinivasa Ramanujan Srīnivāsa Aiyangār Rāmānujam FRS, daada bi Srinivasa Iyengar Ramanujan () (22 December 1887 – 26 April 1920) je ara India olusemathimatiki ati akekofunraeni to, lai gba eko alagbese kankan ninu mathimatiki ogidi, ko ipa pataki si ituwo onimathimatiki, iro nomba, awon eseese alailopin ati awon ida aromoniso. Talenti Ramanujan je siso, latowo eni pataki olusemathimatiki ara Ilegeesi G.H. Hardy, pe o wa niduro kanna bi ti awon olusemathimatiki bi Euler, Gauss, Newton ati Archimedes .
Ẹ́gíptì Ayéijọ́un Ẹ́gíptì Ayéijọ́un ni asailaju ayeijoun ti apailaorun Ariwa Afrika, to wo jo si isale Odo Nile nibi ti orile-ede ayeodeoni Egypt wa. Asailaju ti ara Egypti gbajo ni bi odun 3150 SK (gegebi Iseoroasiko apejose ti ara Egypti ) pelu isodokan oselu Apa Oke ati Apa Isale Egypti labe farao akoko. Itan Egypti ayeijoun sele bi eseese "awon Ileoba", ti won je pinpinniya pelu awon igba aitoro ti won unje "Igba Apinniya". Ileoba Atijo ti Igba Ibere Amobaba, Ileoba Arin ti Igba Arin Amobaba ati Ileoba Tuntun ti Igba Opin Amobaba. Egypti de ogo agbara re nigba Ileoba Tuntun, ni igba Ramesi, leyin eyi ni obere si ni bo si igba irele diedie. Egypt je sisegun latowo awon alagbara okere ni titelentele. Leyin iku Aleksanda Eninla, ikan ninu awon ogagun re to unje Ptolemy Soter, so ara re di ajoba tuntun Egypt. Iran-oba Ptolemi yi joba lori Egypt titi de odun 30 SK, nigba to bo sowo Ile Romu to si di igberiko Romu.