Top 10 similar words or synonyms for dije

kambodia    0.996387

oniwosan    0.995971

lekunrere    0.995641

ajapo    0.995382

ajegunle    0.995210

owonina    0.995136

imusin    0.994571

tk    0.994543

ikot    0.994192

ipase    0.994116

Top 30 analogous words or synonyms for dije

Article Example
Adrian Ungur Adrian Ungur (ojoibi January 25, 1985) je agba tenis ara Románíà to un saba dije ni ATP Challenger Tour.
Àwọn eré-ìdárayá ìdíje Òlímpíkì Àwọn eré-ìdárayá ìdíje Òlímpíkì ni awon ere-idaraya ti won dije fun ninu Idije Olimpiki Igba Oru ati Igba Otutu. Olimpiki Igba Oru 2012 ni ere-idaraya 26, be sini afikun yio ba iye awon ere-idaraya fun Olimpiki Igba Oru 2016. Olimpiki Igba Otutu 2014 ni ere-idaraya meje.
Abdoulaye Wade Abdoulaye Wade (ojoibi May 29, 1926) je Aare ile Senegal iketa lati odun 2000 de 2012. Ohun tun ni Akowe-Agba egbe oloselu Senegalese Democratic Party (PDS) ohun si ni olori re lati igba idasile re ni 1974. O je olori alatako latojo pipe, o dije fun ipo Aare ni emerin, bere ni 1978, kio to dipe won diboyan wole ni 2000.
M. K. O. Abíọ́lá Moshood Kashimawo Olawale Abiola (August 24, 1937 - July 7, 1998) ti a tun mo si M.K.O Abiola jẹ́ omo orile ede Naijiria. A bi ni ilu Abeokuta ni Ipinle Ogun. O je onisowo,ontewe, oloselu ati oloye ile Yoruba Egba patapta. O dije sipo Aare orile-ede Nijiiria ni odun 1993, oun naa si ni gbogbo eniyan gbagbo ati fenuko si jake-jado orile-ede Nijiiria wipe o jawe olubori nigba ti olori ijoba ologun igba naa Ibrahim Babangida ko kede re gege bi olubori eto idibo naa ti o si fi esun aisotito ati aisododo eto idibo yan naa. M.K.O ku ni odun 1998.
Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé FIFA 2010 Gbogbo ayo sele ni papa ereidaraya mewa ni ilu mesan kakiri orile-ede na, ayo iwasopin waye ni papa ereidaraya Soccer City ni Johannesburg. Awon egbe agbaboolu mejilelogbon ni won kopa leyin ti won ti yori ninu àwon idije ikopa to bere ni Osu Kejo 2007. Ninu ere ayo akoko idije na, awon egbe agbaboolu kookan dije ninu adipo ifigagbaga larin awon egbe agbaboolu merin fun ipo, awon egbe agbaboolu meji ti won lewaju ninu won ni won tesiwaju. Awon egbe agbaboolu merindinlogun yi tesiwaju ninu idije pami-nku, nibi ere ayo pami-nku igba meta fa awon egbe agbaboolu meji ti won kopa ninu ayo amuwasopin wa.
Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): E entry: n; (The thieves had forced an entry into the building.) (There is no entry in his dary for that day.) (Painting is my entry for the art competetion.) ìwole; wíwolé. Awon olè náà fi ipá wo inú ilé náà. ohun tí a ko sínú ìwé kó sí ohun tí ohun tí wón ko sínú tí o n ko isèlè ojoojumo síi rè. Eni tí ó n díye tàbí ohun tí a n dije fún Nnkan kíkùn ni mo n se ìdíje lé lóri nínú ìdiye olónà sise náà
Serena Williams Williams ti gba eso wura Olimpiki ikan ninu idije awon obinrn enikan ati meta ninu idije awon obinrin enimeji pelu egbon re Venus Williams. Williams ti gba ebun owo fun ise ju obinrin elere-idaraya miran lo lailai. Williams ni aburo Venus Williams to ti wa ni ipo kinni lagbaye tele. Won ti ba ara won gbayo nigba 23 idije alagbase lati 1998, Serena bori ni 17 awon idije wonyi titi di Osu Kewa 2013. Titi di Osu Keje 2009, won ti pade ni opin idije Grand Slam mejo, Serena bori ni emefa. Larin Open Faranse 2002 ati Open Australia 2003, won pade ni opin awon idije enikan gbogbo Grand Slam mererin, igba akoko ni igba open ti awon oludije meji kanna dije fun opin Grand Slam ni titelentele. Awon mejeji ti gba ife-eye Grand Slam 12 idije enimeji bi ikanna.
Chinwendu Ihezuo Ihezuo darapo mo kilobu egbe ojobon ti BIIK Kazygurt fun ilu Kazakhstan ni odun 2016 fun odun kan. Ni akoko ibeere re pelu kilobu yii ti o ti wo aso ti oni ami ookandinlogun, o gba boolu erindinlogun wole ni ifarahan ogun. O dije pẹlu awọn egbe re ni odun 2016-17 UEFA ti asaju liigi obinrin, ti o ti bere ere meji. ti osi gba fun 180 iṣẹju lai gba boolu kankan wole ni akoko yii. O si tun gba kaadi ofeefee ni asekagba egbe re pelu Verona leyin ti won ti gboro eta si okan soju Verona. O gba koriya ni liigi asiwaju nigba ti awon egbe re gboro eeta si okan ni ere won pelu Wexford Youths ni idije iyege.