Top 10 similar words or synonyms for dahomey

frank    0.996103

simon    0.996022

teeth    0.995934

rev    0.995883

beach    0.995834

hans    0.995825

cv    0.995768

tai    0.995487

journalist    0.995382

vietnamese    0.995298

Top 30 analogous words or synonyms for dahomey

Article Example
Akarigbo of Remo Orí ìtẹ́ àwọn ọba Àkárìgbò kọ́kọ́ wà ní agbègbè Remo lẹ́gbẹ́ Offin, ilú méjì tí ó wà ní ìwọ̀ oòrùn ibi tí ìtẹ́ náà wà nísìn. Látàrí òwò ẹrú ní Dahomey àti ogun tí ó wáyé láàrín àwọn olóyè Abẹ́òkúta àti àwọn Ọba Dahomey, tí ó fàá kí àwọn Yòrúbá kúrò ní Abẹ́òkúta àti ìwọ̀ oòrùn Dahomey lọ sí Àkàrígbò tí ó sì jẹ́ kí ó wọ́n wà ní ìṣàkóso àwọn Oba Àkárígbò.
Benin Ile-Oba Dahomey je didasile lat'owo awon orisirisi eya ni Abomey. Awon akọ̀tàn ro pe boya aisi abo ti owo eru dasile ni o fa ogunlogo ero eniyan lati ko lo si Abomey, larin won ni a ti ri Aja, awon omo eya Gbe ti awon akotan nigbagbo pe awon ni won se idasile ilu na. Ibasepo larin awon eya Aja ati eya Fon to fa idasile eya titun ti a mo si "Dahomey".
Benin Igbagbo ni pe awon Gbe wa lati Wyo. Gangnihessou ni o koko je oba ni Ile-Oba Dahomey. Asa jagunjagun won je ki won fe bode tobi pelu oluilu ni Abomey.
Benin "Benin" gege bi oruko re ko ni ohunkohun se pelu Ilẹ̀ọba Benin tabi Ilu Benin ni Naijiria. Oruko re tele je Dahomey (Dan-ejo (snake),Homey-Ilu tabi Ile,Ilu awon ejo) ki a to yi si Orile-ede Olominira Omoilu ile Benin ni odun 1975 nitori pe egbe odo to wa un je Etiodo Benin. Won mu oruko yi nitoripe ko fi s'egbe kan larin gbogbo awon eya eniyan bi adota ti won wa ni ile Benin. Dahomey je oruko iluoba Fon ti ayeijoun, nitori eyi won ro pe ko to.
Àwọn ọmọ Yorùbá Awon omo Yoruba ti a pe ni eniyan Yoruba ni ibi yii po gan-an ni. Ile Yoruba ni pupo ninu won wa ni ipinle Edo, Ekiti, Eko, Kwara, Kogi Ogun, Ondo, Osun, Oyo; atiwipe omo Yoruba wa ni Bene (Dahomey), Saro (Sierra Leone) ati Togo, Brazil, Cuba, Haiti, United States of America ati Venezuela. Awon Yoruba ni won se ipo keta ni pipo ni ile Naijiria.