Top 10 similar words or synonyms for dẹkun

oyun    0.994760

efon    0.994756

gbigbọn    0.994752

ewure    0.994282

kole    0.994018

foo    0.993985

fifẹ    0.993940

epe    0.993933

tẹle    0.993911

oya    0.993882

Top 30 analogous words or synonyms for dẹkun

Article Example
Kúrùpù Abẹrẹ ajẹsara (oogun abẹrẹ ajẹsara) fun influenza ati diphtheria le dẹkun kúrùpù.
Anafilasisi Awọn iṣẹ kan nlọ lọwọ lati ṣẹda efinifirini [[sublingual]] lati ṣe itọju anafilasisi. [[Abẹrẹ si abẹ ọra ara]] ti o lodi si IgE (anti-IgE) antibody [[omalizumab]] ni a nṣe ayẹwo gẹgẹ bii ọna lati dẹkun pipada, ṣugbọn a ko ti gba ni niyanju lilo rẹ.
Anafilasisi Ninu awọn ti a mọ okunfa wọn ti itoju si wa ni kiakia, asọtẹlẹ rẹ dara. Bi o ti le jẹ wipe a ko mọ okunfa rẹ, bi awọn itọju lati dẹkun ba wa, asọtẹlẹ ma ndara. Bi iku ba waye, o maa nsaba jẹ yala nipa eto mimi (paapaa [[àìlèmí]]) tabi ti ọkan ([[ijaya (lilọ kiri ẹjẹ)|ijaya]]), pẹlu 0.7–awọn isẹlẹ 20% ma nfa iku. Awọn isẹlẹ fifarahan iku laarin iṣẹju ti wa. Awọn abajade ninu awọn to ni anafilasisi ti idaraya nṣe okunfa maa ndara, pẹlu abajade ti o nira ti o kere tabi ti ko nira bi awọn eniyan ti ndagba.
Streptococcal pharyngitis Yiyọ awọn belubelu kuro le jẹ ọna ti o loye lati dẹkun ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa ninu awọn eniyan to maa nsaba ni aisan naa. Ṣiṣe aisan pẹlu ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri fun igba mẹta tabi ju bẹẹ lọ ninu ọdun kan ni a ri bii idi lati yọ awọn belubelu kuro, ni titi di ọdun 2003. Kikiyesara nigbati eniyan nduro naa tun tọna.
Anafilasisi [[Antihistamines]] ([[H1 antihistamine|H1]] ati [[H2 antagonist|H2]]), bi o tile jẹ wipe wọn loo ti wọn nro wipe o dara nitori ero ṣugbọn ẹri iwadi ko kin eyi lẹyin to. [[Atunyẹwo Cochrane]] kan ni ọdun 2007 ko ri eyikeyi ẹkọ ti o dara lati gbani niyanju rẹ a ko si gbagbọ pe wọn ni nkan ti wọn nṣe lori edema tabi gbigbon ọna atẹgun. [[Kọtikositẹrọidu]] le ma le mu iyatọ wa lọwọ yii nipa ipo anafilasisi, ṣugbọn o ṣee lo ni ireti wipe yoo din ewu anafilasis bafasiki ku. Mimunado wọn lati dena tabi dẹkun nkan ko yọranti to ni awọn ipo yii. [[Ti a sọ di alatẹgun]] [[salbutamol]] le munadoko fun [[sisunki ẹdọ foo]] ti efinifirini ko yanju. A ti lo [[Methylene blue]] lara awọn ti ko ṣe daradara si awọn ọna miiran nitori ero wipe o ntu iṣan lara.
Streptococcal pharyngitis Ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa maa ntan nipasẹ ifarakora pẹkipẹki pẹlu alaisan kan. Lati rii daju wipe eniyan kan ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa eyiti o ndun ni, ayẹwo kan ti a npe ni mimu awọn nkan ẹlẹmi dagba lori nkan amu nkan ẹlẹmi dagba l’ode ara lati inu ọna-ọfun (throat culture)fun iwadi ṣe pataki. Lai ṣe ayẹwo yii papa ẹwẹ, a le mọ nipa ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan nfa nipasẹ awọn aami aisan. Ni eyiti o jọ bẹẹ tabi ti a mọ daju, awọn apakokoro(antibiotics)(awọn oogun ti o npa bakiteria) le dẹkun aisan naa lati ma l’ewu gan-an ati lati mu ara pada bọ s’ipo ni kiakia.
Ṣiṣunu Dídádúró ti akoran ṣiṣunu nipa imudara imọtoto, mimọ omi mimu, ati ọwọ fifọ. Ifun lọmu okere oṣu mẹfa ní a gbàníyànjú ogun ilodisi ajakalẹ arun. ọna abayọ ida omi pada sara (ORS), eyi ti o jọ omi mimọ pẹlu iwọn iye iyọ ati ṣuga, ohun ni aayo itọju. Tabulẹti Zinc ní a tun gbàníyànjú.Itọju yii ni o ti gba ẹmi miliọnu 50 awọn ọmọde la ni ọdun 25 sẹyin. Nigba ti awọn eniyan bani ṣiṣunu a gbàníyànjú ki wọn maa jẹ ounjẹ onilera ati ki awọn ọmọ wẹwẹ maa mu ọyan. Bi kobasi ORS ti a polowo, ọna abayọ ti a ṣe nile ni a lelo. Fun awọn ti o ni omi gbigba ara ti o lewu, ifa omi sara ni a lelo. Ni ọpọ igba; sibẹsibẹ, ni a le bojuto nipa ilo omi lati ẹnu. awọn aṣodi si kokoro, ti a kii saba lo, ni a le gbaniyanju ni awọn kan bi awọn ti o ni ṣiṣe aajo ati iba lile, awọn ti o ni lile iṣunu ti o n tẹle awọn arinrin-ajo, ati awọn ti o ni awọn kokoro ati afomọ pato ninu igbẹ wọn. Loperamide le ṣeranwọ lati dẹkun iye inu kikun ṣugbọn ako gbaniyanju fun awọn ti o ni arun lile.