Top 10 similar words or synonyms for bhutan

jersey    0.998608

honduras    0.998510

mauritania    0.998436

belarus    0.998141

tunisia    0.997920

switzerland    0.997737

qatar    0.997578

kazakhstan    0.997528

swiss    0.997452

caledonia    0.997436

Top 30 analogous words or synonyms for bhutan

Article Example
Àsìá ilẹ̀ Bhùtán Àsìá ilẹ̀ Bhutan.
Jigme Khesar Namgyel Wangchuck Jigme Khesar Namgyel Wangchuck (, ojoibi 21 February 1980) ni Druk Gyalpo ile Bhutan ikarun (Oba ile Bhutan) ati olori ilé-oba Wangchuck. O gori oye ni 14 December 2006, o si gbade ni 6 November 2008.
.bt .bt ni amioro orile-ede ti Internet fun top-level domain (ccTLD) fun orile-ede Bhutan.
Bhùtán Ileoba ile Bhutan () je orile-ede tileyika ni Guusu Asia, to budo si apailaorun eti awon Oke Himalaya o si ni bode ni guusu, ilaorun ati iwoorun pelu orile-ede Olominira ile India ati ni ariwa pelu Tibet. Awon ara Bhutan n pe orile-ede won ni "Druk Yul" () to tumo si "Ile Dragon" ni ede Tibet. Awon ara Bhutan je eya eniyan Tibet. Bakanna wo tun ni esin ati asa pelu awon ara Tibet.
Àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè Bahamas - Bahrain - Bangladesh - Barbados - Belarus - Belgium - Belize - Benin - Bermuda - Bhutan - Bolivia - Bosnia and Herzegovina - Botswana - Brazil - Brunei - Bulgaria - Burkina Faso - Myanmar (formerly Burma) - Burundi
Jigme Thinley Jigme Yoser Thinley (ojoibi 1952) lo ti je Alakoso Agba orile-ede Bhutan lati April 2008. Won mo si Lyonchen Jigme Yoser Thinley. "Lyonchen" tumosi "alakoso agba".
Índíà India, fun tonibise bi orile-ede Olominira ile India ( ""; see also in other Indian languages), je orile-ede kan ni Guusu Asia. Ohun ni orile-ede keje titobijulo gege bi itobi jeografi, orile-ede keji toni iye awon eniyan julo pelu bi 1.18 egbegberunkeji eniyan, ati orile-ede oseluaralu toni iye awon eniyan julo lagbaye. O ja mo Okun India ni guusu, Okun arabu ni iwoorun, ati Ebado Benga ni ilaorun, India ni ile eti odo to je . O ni bode mo Pakistan ni iwoorun; Saina, Nepal, ati Bhutan si ariwa; ati Bangladesh ati Burma ni ilaorun. India wa nitosi Sri Lanka, ati Maldives ti won wa ni Okun India.