Top 10 similar words or synonyms for béèyàn

gbádùn    0.991024

méwàá    0.990921

síwáju    0.990690

ìjàmbá    0.990545

leè    0.989708

ìsoro    0.989321

ronú    0.989315

oníkálukú    0.989230

méta    0.989201

    0.989056

Top 30 analogous words or synonyms for béèyàn

Article Example
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá Lẹ́yìn iṣẹ́jú méjì ààbọ̀ éńjìnnì tó wà ní ìpéle àkọ́kọ́ ti jó tán ó jábọ́ kúrò lára ọkọ̀ yìí, éńjìnnì tì péle kejì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ó sì gbé wọn rin ẹgbẹ̀rún méji, ó lé ni ọgọrun mẹta kìlómítà 2,300 kilometres láàrin ìṣẹ́jú mẹ́fà lọ́ sí nú òfururú lọ́ùnlọ́ùn, ẹńjìnnì ìpéle kejì jó tán òhun náà jábọ́, tipéle kẹta bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Ẹ́njìnnì tìpéle kẹta ló wá jáwọn gbà kúrò lọ́wọ́ òǹfà tí ń bẹ nínú ayé pátápátá, wọ́n sì bọ́ sínú àlàfo tí ń bẹ láàrin ilé-ayé àtoṣùpá. Nínú àlàfo yìí, ̣ òǹfà ayé ò ní pa púpọ̀ mọ́ lórí wọn Wọ́n wá sẹ̀sẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ni rìnrìnàjò wọn lọ́ sínú òṣùpá ní ìrowọ́ ìrọsẹ̀. Nínú àlàfo tí a ńpè ní space yìí, béèyàn bá ju ̣ ǹkan ókè kìí padà wá lẹ̀ yíó dúró pa sókè ni, kó dà gan béèyàn gan fò sókè èèyàn ò ní tètè padà wálẹ̀ tórí kò sí ̣ òǹfà kan tí ó fààyàn padà nínú àlàfo yìí ṣùgbọ́n béèyàn bá dẹ́nú òṣùpá, ̣ òǹfà ń bẹ nínú òṣúpá ṣùgbọ́n àmẹ́ kò tó tayé béèyàn bá ju ǹkan sókè nínú òṣùpá naa kìí tètè padà walẹ, ẹ má gbàgbé àti nínú àfìfo tí ń bẹ láàrin ilé-ayé àtọ̀ṣùpá àti nínú òṣùpa gan-an kò sí atẹ́gùn níbẹ̀ o báwo wá làwọn tí wọ́n ń lọ inú òṣùpá ṣé má ń mí, wọ́n má ń gbé atẹ́gùn pamọ́ sínú àpò kan ni, kí wọn o le rátẹ́gùn fi mí. Tòò wọ́n dénú òṣùpá lógúnjọ́ oṣù kẹfà lọ́dún 1969 lọ́jọ̀ Sunday ọjọ ìsinmi ló bọ́ sí ẹ̀yin tẹ́ẹbá ní kàlẹ́ńdà 1969 lọ́wọ́ ẹ wòó ọjọ́ márùn-ún ni wọ́n fi rin ìrìn ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọrun mẹ́ta , ó lé ní ọgọrun lọ́nà ogún kìlómítà 320,000km lọ sí nú òṣùpá, Neil Armstrong lórukọ fẹẹ̀ ẹní tó kọkọ fi ẹsẹ tẹnú òṣùpá bó sẹ́ ń sòkalẹ̀ láti inú ọkọ̀ tí wọ́n gbé lọ óní bí ó ti lẹ̀ jẹ́pé ìgbéṣẹ̀ ti òhun gbé wọnú òṣùpá ó kéré óní ìgbésẹ̀ ńlá ni fún ìran ọmọ ènìyàn. Edwin Aldrin tí wọ́n dìjọ lọ náà sọ̀kalẹ̀ sínú òṣùpá wọ́n bá ààrẹ oríléèdè Amerika Nígbànáà ààrẹ Richard Nixon sọ̀rọ̀ pé tò àwọn tí dé nú òṣùpá o. Àwọn méjéèjì bẹ̀rẹ̀ ìwádí ti wọ́n bá lọ sínú òṣùpá wọ́n fìdíẹ̀ múlẹ̀ pé erùpè, òkúta àtàwọn òkè ń bẹ nínú òṣùpá ṣùgbọ́n kò sí ẹ̀dá alàyè tàbí ohun abẹ̀mí kan níbẹ̀.
Ìnáwó Síwájú sí i, àwọn oníṣòwò gbọ́dọ̀ máa sètò to jíire lórí ìnáwó wọn. Nípa ṣíṣe èyí, wọn óò ni àǹfààní láti mọ̀ bọ́yá Ọláńrewájú ni iṣẹ́ wọn tàbí Ọláńrẹ̀yìn. Níbi tí àtúnṣe bá sì ti pọn dandan, “a kì í fòdù ọ̀yà sùn ká tó í nà án ládàá,” wọn kò nì í bèsù bẹ̀gbà, wọn óò sì se àtúnṣe ní wéréwéré. Àwọn ọmọ ilé-ìwé gan-an gbọdọ̀ mọ̀ pé ká sètò ìnáwó ẹni kì í sohun tó burúkú bí ti í wù kó mọ. Gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé ẹ̀kó gíga, béèyàn bá gbowó fún àwọn orísirísi ìnáwó láti ilé lórí ẹ̀kọ́ ẹni, ó seése kí irú ẹni bẹ́ẹ̀ máa ná ìná-àpà tó bá dé ààrin àwọn ẹlẹgbẹ́ẹ rẹ̀. Irú wọn ló máa ń pe ọ̀sẹ̀ tí wọ́n bá ti ilé lọ́dọ̀ àwọn òbí wọn dé ní ‘Ọṣẹ ìgbéraga’ Èyí kò yẹ ọmọlúàbí pàápàá. Ó sì ń pè fún àtúnṣe.