Top 10 similar words or synonyms for ayewo

afijuwe    0.995349

tire    0.994901

akopa    0.994263

fairọsi    0.994211

ese    0.994150

alejo    0.994087

nile    0.993755

yara    0.993560

eniti    0.993546

imu    0.993283

Top 30 analogous words or synonyms for ayewo

Article Example
Àròjinlẹ̀ aláyẹ̀wò Ìròjinlẹ̀ oníàgbéwò tabi irojinle alagbewo je idanwo ati ayewo awujo ati asa, nipa lilo imo inu awon sayensi awujo ati awon sayensi omoniyan. Oro yi ni itumo meji pelu awo orisun otooto ati itan: ikan bere lati inu oro-awujo ekeji lati inu iseagbewo onimookomooka. Eyi lo fa to je pe This has led to the very literal use of 'irojinle alagbewo' to ka si gbogbo irojinle to ba duro lori ayewo.
Motorhead Motörhead je egbe olorin Geesi rock, O je diddasile ni England ni 1975 be sini o je ikan ninu awon olorin to yori si rere julo ati ti o gba ayewo daada julo ninu itan orin togbajumo.
Paramore Paramore je egbe olorin Geesi rock, O je diddasile ni USA ni 2004 be sini o je ikan ninu awon olorin to yori si rere julo ati ti o gba ayewo daada julo ninu itan orin togbajumo.
George Carlin George Denis Patrick Carlin (May 12, 1937 – June 22, 2008) je ara Amerika alawada ori itage, ayewo awujo, osere ati olukowe, to gba Ebun grammy marun fun awon awo awada re.
The Beatles The Beatles je egbe olorin Geesi rock, O je diddasile ni Liverpool ni 1960 be sini o je ikan ninu awon olorin to yori si rere julo ati ti o gba ayewo daada julo ninu itan orin togbajumo. Lati 1962 egbe olorin yi ni John Lennon (rhythm guitar, olukorin), Paul McCartney (bass guitar, vocals), George Harrison (lead guitar, vocals) ati Ringo Starr (ilu, vocals).
Ìròjinlẹ̀ aláwùjọ Awon ìròjinlẹ̀ aláwùjọ tabi irojinle awujo je awon ilana isese onirojinle ti wo unje lilo lati se agbeka ati se itumo awon isele awujo larin inu ile-eko ironu pati kan. Bi irinse to se koko fun awon asesayensi alawujo, awon irojinle je mo ijiyan lati atijo lori awon oro-onaise to fesemule ati tosegbarale julo (f.a. iseonididaloju ati iseilodionididaloju), ati bakanna bi ipa ti opo tabi araunse unko. Awon irojinle awujo pato kan ungbiraka lati je ti onisayensi, aseaijuwe ati alaifisegbekan ni gbamigbamu. Awon irojinle ajodu, lodi si eyi, ni ipo to duro lori ise pato kan, be sini oun se ayewo awon iru oloro-erookan to wa ninu ironu alasabile to gbale.
Streptococcal pharyngitis Ayẹwo kan ti a npe ni mimu nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun (throat culture)ni ọna ti o ṣe koko ju lọ. lati mọ boya eniyan kan ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju ri. Ayẹwo yii maa nmọ ni ọna ti o daniloju ida 90 si 95 ninu awọn ti o ṣe aisan ti a yẹwo. Ayẹwo kan ti a npe ni ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan (eyiti a tun npe ni ayewo mimọ antigini ni kankan (rapid antigen detection testing), tabi RADT) tun ṣe e lo. Ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan yara ju mimu nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun lo sugbọn o maa nmọ aisan daju ninu ida aadọrin ninu ọgọrun (70 percent) awọn eniyan ti ayẹwo. Awọn ayẹwo mejeeji le mọ ni ọgbọọgba nigbati eniyan ko ba ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju ri nfa (ni ida mejidinlọgọrun awọn eniyan ti a yẹwo (98 percent)).