Top 10 similar words or synonyms for ayẹwo

ẹjẹ    0.993250

sii    0.992377

nṣe    0.992025

anafilasisi    0.990875

okunfa    0.990785

ounjẹ    0.990743

kúrùpù    0.990384

atẹgun    0.989359

ṣugbọn    0.988027

abojuto    0.987578

Top 30 analogous words or synonyms for ayẹwo

Article Example
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Lara àwọn ayẹwo ara fun àisàn hepatitis C ni: ayẹwo ota-ara fun HCV , ayẹwo ELISA, ayẹwo Western blot, ati ayẹwo RNA HCV . Polymerase chain reaction (PCR) le kẹfin HCV RNA ni bi i ọṣẹ kan si meji leyin àisàn, nigba ti àwọn ota-ara yii le gba akoko ti o gun si i ki wọn to le ko ara jọ lati fi ara han.
Anafilasisi Ni igba ikọlu kan, ayẹwo ẹjẹ fun [[tryptase]] tabi [[hisitamini]] (ti jọwọ lati ọwọ awọn sẹẹli masiti) le wulo lati ṣe ayẹwo anafilasisi nitori titani kokoro tabi abojuto. Yatọ si eyi, awọn ayẹwo yii ni ko wulo to bi okunfa ba jẹ ounjẹ tabi bi ẹni naa ba ni [[riru ẹjẹ]] ti o ṣe deedee, wọn kii sii ṣe [[Eyiti a le mọlara tabi mọ ni pato|mọ ni pato]] fun ayẹwo.
Streptococcal pharyngitis Ayẹwo kan ti a npe ni mimu nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun (throat culture)ni ọna ti o ṣe koko ju lọ. lati mọ boya eniyan kan ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju ri. Ayẹwo yii maa nmọ ni ọna ti o daniloju ida 90 si 95 ninu awọn ti o ṣe aisan ti a yẹwo. Ayẹwo kan ti a npe ni ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan (eyiti a tun npe ni ayewo mimọ antigini ni kankan (rapid antigen detection testing), tabi RADT) tun ṣe e lo. Ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan yara ju mimu nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun lo sugbọn o maa nmọ aisan daju ninu ida aadọrin ninu ọgọrun (70 percent) awọn eniyan ti ayẹwo. Awọn ayẹwo mejeeji le mọ ni ọgbọọgba nigbati eniyan ko ba ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju ri nfa (ni ida mejidinlọgọrun awọn eniyan ti a yẹwo (98 percent)).
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Àisàn hepatitis C je àisàn ti o ti wọ ara gan an eyi ti kòkòrò-àrùn hepatitis C n ba ara wọ ija ju osu mefa lọ, ti o da lori pe RNA re n be ninu agọ-ara. Nitori pe àrùn ti o ba ti wọ ara ki i ni ìmọ̀lára-àìsàn fun aimọye odun, àwọn onise-iwadii-ilera a maa kẹfin re nipasẹ ayẹwo iṣẹ ẹdọ tàbí ni akoko ti wọn ba n se ayẹwo àwọn ti o seese ki àrùn wọle si lara. Sise ayẹwo ko le sọ iyatọ laarin boya àisàn ga ni ara tàbí pe o ti wọ ẹni naa lara gan.
Kúrùpù Awọn Ayẹwo ẹjẹ ati viral culture (awọn ayẹwo fairọsi) le fa irira ti ko nilo fun oju-ọ̀nà atẹgun. Nigbati awọn viral mimu kokoro dagba nipa amu nkan dagba ni yara iwadi, ti a gba nipase ilepa nasopharyngeal (ọ̀nà kan ti a nlo rọba ti o ni alafo ninu lati fa ikun imu jade ninu imu), ṣee lo lati jẹrisi ni pato ohun ti o ṣe okunfa. A maa ndekun lilo awọn mimu kokoro dagba nipa amu nkan dagba ni yara iwadi yii l’ọpọ igba fun awọn eto iṣẹ iwadi. Bi nkan ko ba gberu pẹlu abojuto ti o kun oju oṣunwọn, a le ṣe awọn ayẹwo siwaju sii lati ṣayẹwo fun bakiteria.