Top 10 similar words or synonyms for awori

davis    0.995532

missouri    0.994784

mughal    0.993983

shaw    0.993679

oseluarailu    0.993591

nazi    0.993555

berkeley    0.993553

einstein    0.993548

olobiri    0.993424

aba    0.993359

Top 30 analogous words or synonyms for awori

Article Example
Badagry Division Awon ibugbe ni ibile Badagry pin so ona meji. Ikini ni Awori, ikeji si ni ogu tabi egun. Ede ati asa awon meji yato gidi. Amo apere to dara lawon meji nitoripe awon eya mejeji ngbe papo lalafia laisi wahala. Irepo na, lomu pe kosese lati ma pe ilu meji, Iworo to je awori po mo Ajido to je egun, gegebi ikan, Iworo-Ajido.
Èkó Awon Eya Yoruba ti Awori ni o koko tedo si agbegbe Ilu Eko, labe isakoso ati Itona olori-i won, Olofin, awon Awori koko tedo si erekusu Iddo, lehin igba naa ni won bere si ni wonu-u awon agbegbe yoku Eko lati tedo. Ni senturi k'arun din l'ogun {15th Century}, Ilu Eko, bo si abe isakoso Ijoba Bini. Igba naa ni awon ologun Ilu naa so agbegbe ilu naa ni "Eko", eleyii, ti o tumo si [Ibi ti awon Ologun ti n simi} Ni ede Edo/Bini. Gbogbo eleyii sele labe olori awon Bini ni igba naa- Oba Orogba. Leyin ti eyi sele,ni Ijoba Bini fi Baale je oye, lati maa M'ojuto/Se Akoso, ati Gbigba Isakole {Tribute} ilu naa bii agbegbe labe-e Ijoba nla ti Bini. Oba Yoruba akoko ti Ilu Eko je, ni Oba Asipa. Ni odun-un 1472, awon Oyibo Potoki{Portuguese} de si ile Eko, awon Potoki naa ni Oyinbo akoko, ti o maa de Ile -Eko lati Erekusu Orile-ede Yuropu ni igba naa...